BUFFET / masakhaner /yor /masakhaner_32_13_train.tsv
akariasai's picture
Upload 133 files
868d802
raw
history blame
6.26 kB
sentence:jẹ́ kí á ṣe ìṣèlú tó kún fún ọ̀wọ̀ ; ẹ dẹ́kun à ń ba dúdú jẹ́ ní etí àwọn ènìyàn [ … ] Ẹ jẹ́ ká ṣ’àjọyọ̀ àtúnrí àwọn ìgbàgbọ́ọ wa .
sentence: Bákan náà àwọn alátìlẹ́yìn AL sọ wípé ilé àtijọ́ náà kò sí lóríi àwọn ibi àjogúnbá tí ó wà nínú àkọsílẹ̀ .
sentence: Nínú ọ̀rọ̀ọ rẹ̀ nípa òmìnira ní ọjọ́ 27 , ọdún - un , Alákòóso Ìlú Dókítà . ọjọ́ <location>
sentence: Àwọn ìgòo Baijiu ń ṣe ìrántí ìpànìyànnípakúpa Tiananmen náà . Tiananmen <organization>
sentence: Health Barta gbé fídíò kan sí oríi YouTube tí ó ń ṣe àlàyé lẹ́kùnúnrẹ́rẹ́ ohun tí ó pọn dandan láti ṣe èèyán ní ibà - ẹ̀fọn : Health <person> Barta <organization> YouTube <person>
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Shakil Ahmed . Ahmed <person>
sentence: Wọ́n tú yàráa Deng Chuabin wò fún bíi wákàtí kan , wọ́n sì gbé ẹ̀rọ 20 àti agbaná sí ara ẹ̀rọ . Chuabin <person>
sentence: Àwòrán láti fídíò oríi YouTube “ Ohùn fún Àyípadà Ojú - ọjọ́ fún Ẹ̀kọ́ Àyípadà Ojú - ọjọ́ – Ìpolongo ọdún 2019 , """" tí Panos Caribbean tẹ̀ jáde . YouTube <person> ọdún <location> Caribbean <person>
sentence: Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ètòo wa , ẹ̀kọ́ tí í ṣe baba , ń gbé àwọn ènìyàn sí ipòo tálákà , kò sì fún wọn ní àǹfààní lẹ́ẹ̀kan sí i .
sentence: Ìwé ìròyìn Trinidad Express yàn láti kọ èròo rẹ̀ nípa Àyájọ́ jọ́ Òmìnira tí ó dábàá wípé Rowley , Kambon , àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọ - ènìyàn Pearl Eintou Springer ṣì sọ nígbàtí wọ́n sọ ìdí tí àwọn ọmọìlú Trinidad àti Tobago tí ó jẹ́ ènìyàn dúdú ò fi ṣe dáadáa tó : Trinidad <person> Express <organization> jọ́ <location> Eintou <person> Springer <person> Trinidad <organization> àti <location> Tobago <location>
sentence: Láìsí àmójútó , ilé yìí ṣì dúró .
sentence: Àwọn tí ó ṣì ń dúró ti di ẹgẹrẹmìtì , èyí á mú kí àwọn kan ó máa lọ ( ṣe ayédèrú ìwé láti ) gbẹ́sẹ̀ lé ilé wọ̀nyí .
sentence: Akọ̀ròyìn Reuters méWa Lone àti Kyaw Soe Oo rìnrìn òmìnira lẹ́yìn tí a dá wọn sílẹ̀ ní ẹ̀wọ̀n Insein ní Yangon . Reuters <person> Lone <person> Soe <person> Oo <person> ẹ̀wọ̀n <organization> Insein <location> Yangon <organization>
sentence: Nítorí pé Chen kò gbà wípé òun dá ẹ̀ṣẹ̀ , ó sì wà lábẹ́ẹ ṣìgún òfin .
sentence: Ìfẹ̀hónúhàn ọ̀dọ̀ tí ó tó bíi 100 wáyé ní ọjọ́ kẹ́rin oṣù Èrèlé , pẹ̀lú àtìlẹ́yìn ẹgbẹ́ àwọn ọmọ ìlú kan tí ó rí ìgbésẹ̀ ìjọba gẹ́gẹ́ ọ̀nà láti gbẹ́sẹ̀ lé ẹ̀tọ́ àwọn ènìyàn fún ìrìnàṣíṣe . ọjọ́ <location>
sentence: Ìfẹ̀hónúhàn náà
sentence: Nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ iṣẹ́ ìkọ̀ròyìn ni ó ti fi lélẹ̀ wípé a gbọdọ̀ tànmọ́lẹ̀ sí ìjìyà àwọn ènìyàn ní ibi tí rògbòdìyàn wà .
sentence: Ojú - ìwé Facebook ti BBC Bangla rọ àwọn òǹkàwée rẹ̀ láti jábọ̀ àwọn ìgbésẹ̀ akin tí àwọn òníṣẹ́ ìlú Dhaka ń gbé láti gbógun ti ẹ̀fọn . Facebook <person> BBC <person> Bangla <organization> Dhaka <organization>
sentence: Kí ni ẹ fi ṣe ohùn àwọn mẹ̀kúnnù ?
sentence: Lọ́dọọdún , àwọn aláṣẹ China fi ọwọ́ agbára mú ìrántí ìṣẹ̀lẹ̀ náà , tí wọ́n sì fi àwọn agbọ̀rọ̀dùn sí àtìmọ́lé . China <organization>
sentence: ‘Ohùn - un Jamaica fún Àyípadà Ojú - ọjọ́’ fi orin jíṣẹ́ẹ wọn ‘Ohùn <person> - <organization> un <organization> Jamaica <organization> fún <organization> Àyípadà <organization> Ojú <organization> - <organization> jọ́’ <organization>
sentence: Òǹlò Facebook Adrian Raymond sọ : Facebook <person> Raymond <person>
sentence: Wọ́n ò mọ̀ pé ilé náà ti di ẹgẹrẹmìtì , ó sì lè wò lulẹ̀ kí ó wó lù wọ́n — tí í ṣe àpẹẹrẹ àìmọ̀kanmọ̀kàn àwọn ènìyàn sí ìpamọ́ ohun àjogúnbá àti àtìlẹ́yìn fún àtúnṣe sí ilé àtijọ́ tí ó wà ní Bangladesh . Bangladesh <organization>
sentence: Àwọn dókítà mékan náà kú látàrí ibà - ẹ̀fọn , èyí sì ti ń mú kí àwọn ènìyàn ó máa bẹ̀rù .
sentence: Ní ọdún yìí , àwọn tí àìsàn - an ibàá kọlù tó bíi 7 , 179 , àwọn - 2800 ní sáà kínní osùu Agẹmọ nìkan . ọdún <location> osùu <location>
sentence: Ohun èlò fún ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà máa ń gbọ́n owó mì , nítorí iṣẹ́ ìdáàbòbò oríi rẹ̀ , tí àjọ ba ń kówó lé lórí tẹ́lẹ̀ kí ó tó di ìgbà yìí .
sentence: Àwọn ọlọ́pàá fi agbára gba ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ alágbèéká mẹ́ta , ẹ̀rọ ayárabíàṣá kọ̀mpútà kan , ẹ̀rọ ayárabíàṣá àgbélétan kan , iPad , ike péléìrántí àti ẹ̀rọ ayàwòrán kékeré kan nígbà tí wọ́n wá sí ilée rẹ̀ .
sentence: 18 people are talking about this
sentence: Ka àwọn ọ̀ràn ìsàlẹ̀ yìí síwá:
sentence: Akọrin , ọmọ ilé ìwé àti àwọn aládùúgbò péjọ ní — Kingston , Lionel Town , Ridge Red Bank àti White River — fún ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́jọ́ mẹ́rin nínúu oṣù Ẹrẹ́nà àti Igbe . Kingston <organization> Lionel <organization> Town <location> Ridge <organization> Red <location> Bank <location> White <organization> River <location> ọlọ́jọ́ <location> oṣù <location>
sentence: Ragib Hassan ni ó ní àwòrán ní oríi Wikipedia . Hassan <person> Wikipedia <person>
sentence: Àwa , tí a wà nínú ìlú , ni a ó fi ààtí a ó sì ké pe àwọn aráa wa ní òkè òkun , kí àwọn náà ó ké gbàjarè , nítorí ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà ṣe kókó fún wọn .