BUFFET / masakhaner /yor /masakhaner_32_42_dev.tsv
akariasai's picture
Upload 133 files
868d802
raw
history blame
5.83 kB
sentence: Ní ìpalẹ̀mọ́ ìsààmì ọgbọ̀n ọdún tí ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́ 4 , ayàwòrán eré orí ìtàgé Deng Chuabin ti di ẹni tí ọ̀rọ̀ ìgò ọtí - líle 64 ń dá sẹ̀ríà fún lọ́wọ́lọ́wọ́ . ọgbọ̀n <location>jọ́ <location> Chuabin <person>
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Mark Franco , a gba àṣẹ láti lò ó . Franco <person>
sentence: Ó sọ fún wa :
sentence: Akọ̀ròyìn Reuters méjì Wa Lone àti Kyaw Soe Oo rìnrìn òmìnira lẹ́yìn tí awọn sílẹ̀ ní ẹ̀wọ̀n Insein ní Yangon . Reuters <person> Lone <person> Soe <person> Oo <person> ẹ̀wọ̀n <organization> Insein <location> Yangon <organization>
sentence: Ẹ̀fọn Aedes albopictus , tí ó máa ń gbé kòkòrò ibà ká .
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an
sentence: Àwọn akọrin ewì - alohùn ráàpù , Lilo Kwanza àti Adérito Gonçalves , kọ orin kan , tí wọ́n sì ya àwòrán - an orin tí ó dá lóríi ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn yìí , “ Ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà 30 , 000 ″ ni àklé orin náà , tí ó ń ṣe ẹ̀fẹ̀ lórí iye owó tabua tí ọmọ - ìlú yóò san fún ìwé ìrìnnà . Kwanza <person> Gonçalves <person>
sentence: Iyì - ara - ẹni máa ń relẹ̀ , tí èyí yóò sì mú wọn hu ìwà - ipá láti jà fún ẹ̀tọ́ọ wọn láwùjọ .
sentence: Ó sì ń fa àmì ìfòyà .
sentence: Àwòrán láti oríi Wikipedia , James Gathany , CDC ni ó ni àwòrán . Wikipedia <person> Gathany <person> CDC <person>
sentence: Deng ti wà ní Àtìmọ́lé Agbègbè Nanxi nítorí wípé “ ó ń bá ìjà bọ̀ """" – ẹ̀sùn tí wọ́n sábà máa ń kà mọ́ àwọn ènìyàn tí ó ń takò ìjba lẹ́sẹ̀ . Nanxi <organization>
sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 22 Òkúdù 2019 11 : 13 GMT 22 <location>
sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an
sentence: Èsì tí U Ye Ni fún àwọn ọmọ ajagun rè é : Ye <person> Ni <person>
sentence: Àwọn ẹgbẹ́ iléeṣẹ́ oníròyìn àti ajà - fún - ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ń ṣe àjyọ̀ọ ti ìdásílẹ̀ lẹ́wọ̀n - ọn akọ̀ròyìn Reuters Wa Lone àti Kyaw Soe Oo tí ó lò jujọ́ 500 ní àtìmọ́lé fún ipa tí wọ́n kó nínú ìwádìí òfíntótó ìṣẹ̀lẹ̀ ìpanípakúpa àwọn olùgbée Rohingya kan ní gúúsù Myanmar . Reuters <person> Lone <person> Soe <person> Oo <person> Rohingya <organization> gúúsù <organization> Myanmar <location>
sentence: Àwòrán Òde .
sentence: Àjùsẹ́wọ̀n fún yẹ̀yẹ́
sentence: Kò sí ìtọ́ka kankan sí Ẹgbẹ́ Olóṣèlú Ìjba Àwa - ara - wa 89 nínú ìwé àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá kankan , àwọn ọmilé ìwé tí ó ga jù lọ ní China kò gbọ́ nípa ìpaninípakúpa náà , kò tawọn létí rí . China <organization>
sentence: Bí orin reggae àti dancehall ṣe ń lọ ni àwọn ìpolongo tí ó ń sọ nípa ohun gbogbo láti ọṣẹ ìfọṣọ àbùfọ̀ sí oúnjẹ àsèsílẹ̀ , orin ni ènìyán lè gbà dé ọkàn ọmọ Jamaica — èyí ló mú Panos Caribbean , ẹni tí ó ní ilé iṣẹ́ ìròyìn tí kì í ṣe ti ìjba , láti fi orin kéde nípa ọ̀rọ̀ àyíká . Jamaica <organization> Caribbean <person>
sentence: Níbẹ̀ , ọ̀kọrin ọmọ Jamaica Aaron Silk darapọ̀ mọ́ àwọn olórin mìíràn — pẹ̀lú eléré Belizean Adrian Martinez — láti ṣe alágbàáwí ìdínkù fún ìgbóná àgbáyé sí ìwọ̀n - ọn ojúàmì 1 . 5 . Jamaica <organization> Silk <person> Adrian <person> Martinez <person>
sentence: Ní òní , lẹ́yìn ọ̀pọ̀lpọ̀ ọdún , àwamọ ẹrú tí à ń jà fitafita fún àjogúnbá ìjba amúnisìn . òní <location>
sentence: Àkọsílẹ̀ Àìsàn Pọ̀ Sí i Ní Osù Agẹmọ Osù <location>
sentence: Ka àwọn ọ̀ràn ìsàlẹ̀ yìí síwájú :
sentence: Èyí ni àyíká tí ó mú ìkóròyìnjọ nira àti di ohun tí kò ṣe é ṣe nítorí gbogbo ìròyìn ní láti gba Asẹ́ Ńlá ìpalẹ́numọ́ orílẹ̀ èdèe China kjá . China <organization>
sentence: Wọ́n tú yàráa Deng Chuabin wò fún bíi wákàtí kan , wọ́n sì gbé ẹ̀rọ 20 àti agbaná sí ara ẹ̀rọ . Chuabin <person>
sentence: Òṣìṣẹ́ Àjọ Ìlú kan ti sọ wípé yóò tó ọ̀sẹ̀ mélòó kan kí egbògi ìdáààbòbò tí yó sì dín ẹ̀fọn kù .
sentence: Zeyar Lwin ń tọ́ka sí ìwé òfin ọdún - un 2008 tí ọ̀pọ̀lpọ̀ àwọn atúnǹkanká gbàgbọ́ wípé ae é to láti fi agbára fún ìṣèjba ikọ̀ ajagun pàápàá lẹ́yìn tí alágbáda gba ìjba . Lwin <person> ọdún <location>
sentence: Jennifer Creery ni ẹni tí ó kọ ìròyìn yìí , tí Ilé Iṣẹ́ Atẹ̀wé Olómìnira Hong Kong sì tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọjọ́ 24 oṣù Èbìbí ọdún - un 2019 . Creery <person> Ilé <person> Iṣẹ́ <organization> Atẹ̀wé <organization> Olómìnira <organization> Hong <organization> Kong <organization>jọ́ <location>
sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Shakil Ahmed . Ahmed <person>
sentence: Pẹ̀lú ìdásílẹ̀ àwọn akọ̀ròyìn - in Reuters , ẹ̀ṣẹ̀ ní òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ ṣì jẹ́ ní Myanmar Reuters <person> Myanmar <organization>
sentence: Ayàwòrán náà gba ìpè àwọn ọlọ́pàá lẹ́yìn - in ọgbọ̀n ìṣẹ́jú lẹ́yìn tí ó túwíìtì àwòrán náà pẹ̀lú wípé lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ni ó mú un wálẹ̀ , bẹ́ẹ̀ ni CHRD ṣe ti sọ . ọgbọ̀n <location> CHRD <person>
sentence: Ìgò ọtí - líle 64