sentence: Ní ìpalẹ̀mọ́ ìsààmì ọgbọ̀n ọdún tí ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́ 4 , ayàwòrán eré orí ìtàgé Deng Chuabin ti di ẹni tí ọ̀rọ̀ ìgò ọtí - líle 64 ń dá sẹ̀ríà fún lọ́wọ́lọ́wọ́ . ọgbọ̀n ọjọ́ Chuabin sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Mark Franco , a gba àṣẹ láti lò ó . Franco sentence: Ó sọ fún wa : sentence: Akọ̀ròyìn Reuters méjì Wa Lone àti Kyaw Soe Oo rìnrìn òmìnira lẹ́yìn tí a dá wọn sílẹ̀ ní ẹ̀wọ̀n Insein ní Yangon . Reuters Lone Soe Oo ẹ̀wọ̀n Insein Yangon sentence: Ẹ̀fọn Aedes albopictus , tí ó máa ń gbé kòkòrò ibà ká . sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an sentence: Àwọn akọrin ewì - alohùn ráàpù , Lilo Kwanza àti Adérito Gonçalves , kọ orin kan , tí wọ́n sì ya àwòrán - an orin tí ó dá lóríi ìwọ́de ìfẹ̀hónúhàn yìí , “ Ìwé ẹ̀rí ọmọ - ìlú - fún - ìrìnnà 30 , 000 ″ ni àkọlé orin náà , tí ó ń ṣe ẹ̀fẹ̀ lórí iye owó tabua tí ọmọ - ìlú yóò san fún ìwé ìrìnnà . Kwanza Gonçalves sentence: Iyì - ara - ẹni máa ń relẹ̀ , tí èyí yóò sì mú wọn hu ìwà - ipá láti jà fún ẹ̀tọ́ọ wọn láwùjọ . sentence: Ó sì ń fa àmì ìfòyà . sentence: Àwòrán láti oríi Wikipedia , James Gathany , CDC ni ó ni àwòrán . Wikipedia Gathany CDC sentence: Deng ti wà ní Àtìmọ́lé Agbègbè Nanxi nítorí wípé “ ó ń bá ìjà bọ̀ """" – ẹ̀sùn tí wọ́n sábà máa ń kà mọ́ àwọn ènìyàn tí ó ń takò ìjọba lẹ́sẹ̀ . Nanxi sentence: Àtẹ̀jáde ìtúmọ̀ 22 Òkúdù 2019 11 : 13 GMT 22 sentence: Ìtúmọ̀ Ìtúnwí - ọ̀rọ̀ Ọlọ́rọ̀ gan - an sentence: Èsì tí U Ye Ni fún àwọn ọmọ ajagun rè é : Ye Ni sentence: Àwọn ẹgbẹ́ iléeṣẹ́ oníròyìn àti ajà - fún - ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ń ṣe àjọyọ̀ọ ti ìdásílẹ̀ lẹ́wọ̀n - ọn akọ̀ròyìn Reuters Wa Lone àti Kyaw Soe Oo tí ó lò ju ọjọ́ 500 ní àtìmọ́lé fún ipa tí wọ́n kó nínú ìwádìí òfíntótó ìṣẹ̀lẹ̀ ìpanípakúpa àwọn olùgbée Rohingya kan ní gúúsù Myanmar . Reuters Lone Soe Oo Rohingya gúúsù Myanmar sentence: Àwòrán Òde . sentence: Àjùsẹ́wọ̀n fún yẹ̀yẹ́ sentence: Kò sí ìtọ́ka kankan sí Ẹgbẹ́ Olóṣèlú Ìjọba Àwa - ara - wa 89 nínú ìwé àkọsílẹ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ àtẹ̀yìnwá kankan , àwọn ọmọ ilé ìwé tí ó ga jù lọ ní China kò gbọ́ nípa ìpaninípakúpa náà , kò ta sí wọn létí rí . China sentence: Bí orin reggae àti dancehall ṣe ń lọ ni àwọn ìpolongo tí ó ń sọ nípa ohun gbogbo láti ọṣẹ ìfọṣọ àbùfọ̀ sí oúnjẹ àsèsílẹ̀ , orin ni ènìyán lè gbà dé ọkàn ọmọ Jamaica — èyí ló mú Panos Caribbean , ẹni tí ó ní ilé iṣẹ́ ìròyìn tí kì í ṣe ti ìjọba , láti fi orin kéde nípa ọ̀rọ̀ àyíká . Jamaica Caribbean sentence: Níbẹ̀ , ọ̀kọrin ọmọ Jamaica Aaron Silk darapọ̀ mọ́ àwọn olórin mìíràn — pẹ̀lú eléré Belizean Adrian Martinez — láti ṣe alágbàáwí ìdínkù fún ìgbóná àgbáyé sí ìwọ̀n - ọn ojúàmì 1 . 5 . Jamaica Silk Adrian Martinez sentence: Ní òní , lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún , àwa ọmọ ẹrú tí à ń jà fitafita fún àjogúnbá ìjọba amúnisìn . òní sentence: Àkọsílẹ̀ Àìsàn Pọ̀ Sí i Ní Osù Agẹmọ Osù sentence: Ka àwọn ọ̀ràn ìsàlẹ̀ yìí síwájú : sentence: Èyí ni àyíká tí ó mú ìkóròyìnjọ nira àti di ohun tí kò ṣe é ṣe nítorí gbogbo ìròyìn ní láti gba Asẹ́ Ńlá ìpalẹ́numọ́ orílẹ̀ èdèe China kọjá . China sentence: Wọ́n tú yàráa Deng Chuabin wò fún bíi wákàtí kan , wọ́n sì gbé ẹ̀rọ 20 àti agbaná sí ara ẹ̀rọ . Chuabin sentence: Òṣìṣẹ́ Àjọ Ìlú kan ti sọ wípé yóò tó ọ̀sẹ̀ mélòó kan kí egbògi ìdáààbòbò tí yó sì dín ẹ̀fọn kù . sentence: Zeyar Lwin ń tọ́ka sí ìwé òfin ọdún - un 2008 tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn atúnǹkanká gbàgbọ́ wípé a ṣe é to láti fi agbára fún ìṣèjọba ikọ̀ ajagun pàápàá lẹ́yìn tí alágbáda gba ìjọba . Lwin ọdún sentence: Jennifer Creery ni ẹni tí ó kọ ìròyìn yìí , tí Ilé Iṣẹ́ Atẹ̀wé Olómìnira Hong Kong sì tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọjọ́ 24 oṣù Èbìbí ọdún - un 2019 . Creery Ilé Iṣẹ́ Atẹ̀wé Olómìnira Hong Kong ọjọ́ sentence: Àwòrán láti ọwọ́ọ Shakil Ahmed . Ahmed sentence: Pẹ̀lú ìdásílẹ̀ àwọn akọ̀ròyìn - in Reuters , ẹ̀ṣẹ̀ ní òmìnira ọ̀rọ̀ sísọ ṣì jẹ́ ní Myanmar Reuters Myanmar sentence: Ayàwòrán náà gba ìpè àwọn ọlọ́pàá lẹ́yìn - in ọgbọ̀n ìṣẹ́jú lẹ́yìn tí ó túwíìtì àwòrán náà pẹ̀lú wípé lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ni ó mú un wálẹ̀ , bẹ́ẹ̀ ni CHRD ṣe ti sọ . ọgbọ̀n CHRD sentence: Ìgò ọtí - líle 64