10020#0 Odun wo ni wọn ṣe idije Olympiiki akọkọ? 10118#0 Orile ede wo ni Washington DC wà? 11164#0 Ipa wo ni Benito Mussolini se ni Ogun World War 2? 11194#0 ẹgbẹ wo ni Huey Newton da silẹ? 11419#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Poland 11610#0 Ọdún wo ni ẹlẹṣẹ ti a mọ sí Ray Robinson fi aiye silẹ? 11673#0 Ki ni oluiilu orile ede Japan? 12167#0 ọdún wo ẹlẹsẹ ti a mọ sí Dick Tiger ṣ'aláìsí? 12299#0 ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Mauritania? 13267#0 ta ni gomina ipinle yamoussoukro? 13308#0 kí ni olú ìlú orile ede Puerto Rico? 13499#0 Ile iwe eko giga wo ni Charles Soludo lọ? 13529#0 iru kemika wo ni won ni won fi n se batiri? 13593#0 Ki ni awon apẹrẹ kemika? 13681#0 Awọn akọrin wo ni wọn wá láti Detroit? 13888#0 ilu wo ni Lake Victoria wa? 13935#0 Awon orile ede wo ni won pe ni Balkani? 14719#0 Nibo ni ibùdó àwọn Ajagun ni ipinlẹ Borno wà? 14738#0 Ọdún wo ni wọn dá NASA silẹ? 14921#0 Kini orukọ ere ti Chris Tucker ba Jackie Chan ṣe? 15096#0 Odun wo ni Andy Ruiz ati Anthony Joshua ja? 15109#0 Ilu wo ni won bi Fyodor Dostoyevsky si? 15123#0 Omo odun meloo wo ni Nietzshe nigba to je alaga ni Yunifasiti Basel? 15124#0 ọmo orile ede wo ni John Locke? 15131#0 ọjọ meloo lo wa ninu oṣu february? 15306#0 Egbe agbaboolu wo ni Dwight Yorke gba bóòlù fún? 15329#0 Ọdún wo ni Namadi Sambo jẹ Gomina ipinle Kaduna ? 15415#0 Odun wo ni Alfred Landon je gomina ipinle Kansas? 15465#0 Asiko wo ninu ọdun lo da ju lọ lati lọ si ilu botswana? 15502#0 esin wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede Albania ? 15508#0 Ẹsin wo lo ga ju lọ ni orile-ede Armenia? 15512#0 Awon orile ede wo lo yika Austria? 15573#0 Omo meloo ni Victoria Beckham bi fun David Beckham? 15583#0 esin wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede India? 15770#0 Osu meloo ni Ernest Shonekan lo gege bi aare orile-ede Naijiria? 15776#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Bhutan? 15814#0 Orile ede wo ni won ti n so ede Lingala? 15826#0 ìyàwó mélòó ni anọbi muhammad fẹ? 15848#0 Odun wo ni orile-ede Grenada gba ominira? 15863#0 ọdún wo ni wọn bí akọwe Chinua Achebe ? 15973#0 Esin wo lo gbajumo ju ni orile-ede Lituenia? 16114#0 oṣù wo ni keresimesi má ń bọ́ sí? 16313#0 Aafaa wo lo kọ Abdul Qadir Gilani ni kewu? 16336#0 Èdè wo ni àwọn ará St Kitts and Nevis n sọ? 16348#0 Egbe oloselu wo ni Boris Johnson wa pẹlu? 16352#0 èdè mélòó ni wọn sọ ni orile ede singapore? 16361#0 ọdun wo ni awọn italy fun somalia ni ominira? 16384#0 ọdún wo ni Emomali Rahmon di ààrẹ Orile ede Tajikistan? 16397#0 Ede wo ni wọn sọ ni Tunisia? 16415#0 Ki ni orukọ Pope ti o wa ni'po nisin? 16780#0 Ki ni olu-ilu ipinle Osun? 16900#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni ipinlẹ Anambra? 16908#0 ara ilu wo ni christopher abani? 17043#0 Ipo wo ni Raji Fashola wa labe ijọba Buhari? 17237#0 ọdún wo ni wọn kọkọ ṣe iwadi èédú ni ipinlẹ Enugu 17311#0 ipinlẹ wo ni Isiala Ngwa wa ni Nàìjíríà? 17516#0 Ati ibo ni awọn ara Oguta ti wa? 17552#0 Ipinle wo ni ilu Orlu wa? 17692#0 Ede won ni won sọ ni ipinle Plateau? 18031#0 Odun wo ni won da egbe World Health Organization silẹ? 18081#0 Ba wo ni oju ọjọ ṣe ri ni Gabon? 18270#0 Orile ede wo ni San Marino wa? 18317#0 Ta ni Aare orile-ede Zimbabwe? 18395#0 Ki ni iyato laarin UK ati Britani? 18542#0 Odun wo ni Mike Tyson ba Lennox Lewis ja? 19087#0 ọdún wo ni wọn dá ipinlẹ Nasarawa silẹ? 19105#0 Ipinlẹ wo ni a bi oloṣelu Bola Tinubu si? 19244#0 Odun wo ni Anthony Joshua di ọjọgbọn ẹlẹṣẹ? 19255#0 ara ìlú wo ni ẹlẹsẹ Andrew Tate? 19277#0 Ba wo ni oju ọjọ se ri ni ilu Miami? 19496#0 Ta ni Aarẹ orile ede Ivory Coast? 20042#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Tanzania? 20231#0 Odun wo ni Augusto Pinochet je aare orile-ede Chile? 20612#0 Ta ni gomina ipinlẹ Taraba? 20613#0 Odun wo ni Jolly nyame je gomina ipinle taraba? 20775#0 kí ni oluilu orile-ede griisi? 20823#0 ṣe igbakeji aarẹ ma n gba owo oṣu? 20950#0 Odun wo ni Ogun Agbaye keji ti a mọ si World War 2 pari? 20961#0 Omo orile-ede wo ni osere Yvonne Nelson? 21001#0 awọn ipo wo lo ṣe pàtàkì jù lọ ní ìjọba Kanada? 21336#0 Esin wo lo gbajumọ ju ni orile-ede Amerika? 22136#0 Ibasepo wo lo wa laarin India ati Pakistan? 22351#0 Awon osere wo lo wa lati orile-ede Vietnam? 22782#0 Odun wo ni Alessandro Del Piero bẹrẹ si gba bọọlu? 22785#0 Osere wo o se fiimu Selma? 22786#0 Ọdún wo ni Pope John Paul s'alaisi? 23435#0 ọdun wo ni Julius Caesar ku? 23490#0 ilu wo lo tobi ju lo ni ipinle Tamil Nadu? 23534#0 Odun wo ni King Leopold ṣ'alaisi? 23620#0 Ki ni oruko ṣọọsi Paul Adefarasin? 23625#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Egypt? 23682#0 ọdún wo ni wọn bẹrẹ ogun ni orile-ede Somalia? 24542#0 Odun wo ni Pope Francis ti di Pope? 24640#0 ọdun wo ni Pope John Paul ṣ'alaisi? 24860#0 Oṣù wo ni ọdún 1967 ni ogun Biafra bẹrẹ? 24913#0 Odun wo ni wọn da ẹgbẹ United Nations silẹ? 24925#0 Orile ede wo lo yege ni world cup ọdun 1986? 25355#0 Orukọ wo ni a n pe orile-ede Botswana ki wọn to yi pada? 25390#0 Ipinle meloo lo wa ni orile ede Amerika? 2560#0 Iwe wo ni akowe Chinua Achebe kọkọ kọ? 2578#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Afghanistan? 2580#0 Awon eya wo ni won ko l'eru ju ni Afrika? 2596#0 Ki ni oluilu orile ede Albania? 26086#0 Kí ni oluilu orile-ede Finland? 2661#0 Awon iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni Odun 1995? 27070#0 Odun wo ni won bi Otto von bismarck? 2734#0 Kí ni iye èèyàn alawọ dúdú tó wà ní orile ede Bahamas? 27390#0 bawo ni ọkọ ofurufu ṣe yára tó? 27708#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Antigua? 27744#0 Awon awari ati iwadi wo ni Burton Richter gbe jade? 27745#0 ọmọ orile ede wo ni Samuel Peters? 27854#0 Egbe oloselu wo ni Goodluck Jonathan wa pẹlu? 27945#0 erékùṣù wo ni a ti le ri ẹranko tí a mọ sí komodo? 28208#0 ọdún wo ni wọn kọkọ bẹrẹ ẹbun Nobel ? 28245#0 Awo wo ni Akorin Kanye West kọkọ gbe jade? 28633#0 Osu wo ni odun easter ma n bọsi? 28994#0 Asiko wo ni awọn musulumi ma n ki irun ọsan? 29344#0 Ta ni o gba Ebun Nobeli fún Kemistri ọdún 2002? 29560#0 awọn awari sayensi wo ni Renato Dulbecco gbe jáde? 29679#0 Ara ilu wo ni Maurice Bishop? 3017#0 Nibo ni Naijira ni Nok wa? 30269#0 ọdún wo ni alpha conde jẹ ààrẹ Orile ede guinea? 30270#0 Ta ni aare orile ede equitorial guinea? 30627#0 ọdun wo ni ẹlẹṣẹ Joe Louis ba Max Schmeling ja? 30684#0 Ilu wo yunifasiti of Carlton wà? 30974#0 Ki ni idi ti a se n pe Lekki ni Peninsula? 31023#0 ṣe awọn Musulumi wa ni orile-ede India? 31034#0 Iwe meloo ni Mary Anne Evans kọ? 31099#0 Odun wo ni Adekunle Ajasin fi aiye silẹ? 3331#0 ọjọ meloo lo wa ninu oṣu August? 33524#0 Nibo ni poland ni ilu Krakov wa? 33551#0 Awon orile-ede wo lo sunmo Tunisia? 33553#0 Odun wo ni won Bill Gates da ile iṣẹ Microsoft silẹ? 3361#0 nọmba wo lo kere ju lọ ní mathimatiiki? 33661#0 Ọdún mélòó ni Ashley Cole ṣe gba bọọlu fún ẹgbẹ agbaboolu Chelsea? 33958#0 oniyẹyẹ wo lo gbajumọ julọ ni Naijiria? 34147#0 ọdun wo ni awọn agbabọọlu orile-ede jeman ru World cup? 3545#0 Ọmọ ìlú wo ni òṣèré Genevieve Nnaji? 35580#0 awọn ẹbun wo lo dara julọ fún ọlọjọ ibi? 35932#0 ọdún wo ni Martin Delany wá sí ilẹ abeokuta 36761#0 ọmọ orílé èdè wo ni akọrin Mya Harrison 36841#0 Ile iṣẹ iroyin wo ni Funmi Iyanda ba ṣiṣẹ? 36871#0 Iru orin wo ni Salawa Abeni kọ? 36921#0 awọn irin iṣẹ wo ni àwọn oni Sákárà ma n lo? 37045#0 Ilu wo ni wọn ti n ṣe ọtí Heineken? 37174#0 Ẹsin wo lo gbajumọ ni Orile-ede Sierra Leone? 37178#0 Awon ilu wo lo tobi julọ ni orilẹ ede Spain? 37220#0 Ede wo ni won n so ni orile-ede Spain? 37221#0 ẹsin wo lo gbajumọ ju ni orile-ede Spain? 37319#0 Ki ni iye eniyan to wa ni orile-ede Bolifia? 37639#0 ọdún wo ni won da yunifasiti Oxford silẹ? 37663#0 Ẹlẹṣẹ wo ni a mọ si Cassius Clay? 37677#0 Odun wo ni Agbaboolu Roberto Carlos fehinti? 37700#0 Irawo meloo lo wa lara aṣia orile-ede Amerika? 37746#0 Ilu wo ni wọn bi Bobby Benson si? 37764#0 Egbe oloselu wo ni Maxine Waters wa pẹlu? 38048#0 Ọdún wo ni Napoleon Bonaparte ṣ'alaisi? 38275#0 kí ni oluilu orile-ede Haiti? 3952#0 Awon orisi atomu wo lo wa? 3954#0 awọn agbara wo ni gomina ni ni orile-ede Naijiria? 4008#0 Onimọ fisisi wo lo ṣe iwadi X-ray? 4078#0 ṣe ipinle Ọṣun ni Ile Ife wa? 41815#0 Planeti meloo lo wa ni agbaye? 48995#0 kí ni o ma n fa arun Parkinson ? 49384#0 Ki ni itumo asteroidi? 5024#0 Odun wo ni won da Yunifasiti of Ife silẹ? 53825#0 kí ni orúkọ àwọn ọmọ ti anọbi Adam bi? 53850#0 Ilu wo ni won bi agbaboolu Oxlade Chamberlain si? 54114#0 Odun meloo ni Frank Lucas lo ni ewon ki o to s'alaisi? 54186#0 Odun wo ni Calvin Klein da ile iṣẹ rẹ silẹ? 54221#0 Bawo ni eeyan ṣe le kọ iṣẹ akọrin? 54493#0 ọmọ ilu wo ni baba to bi Lewis Hamilton? 54938#0 ọmọ orile ede wo ni Gloria asunmu? 54948#0 ẹbun Grammy mélòó ni Mary J Blige ti gbà? 55811#0 Ilu wo ni wọn bi alawada Eddie Murphy si? 58532#0 Ibasepo wo lo wa laarin Bill Clinton ati Monica Lewinsky? 58609#0 orile-ede wo ni ilu Birmingham wà? 58900#0 Koopu meloo ni Sir Alex Ferguson gba gẹgẹ bi monija Manchester United? 58909#0 Awon erekusu wo lo sunmo orile-ede Faranse? 59033#0 Yunifasiti wo ni wọn kọko da silẹ ni Naijiria? 59455#0 ọdún wo ni Mariah Carey kọkọ gbé àwo jáde? 59526#0 ọdun wo la da ile iṣe naijirian tẹlefisan authority silẹ? 59902#0 Ilu wo lo tobi ju ni orile-ede Korea? 60238#0 Omo orile ede wo ni Li Lianjie? 60297#0 Awọn gbajumo wo lo lọ wo ija Pacquiao ati Mayweather? 60299#0 Odun wo ni Eddie Murphy bẹrẹ si ṣe fiimu? 60314#0 Ki ni orukọ ogbontarigi oṣere ti a mo si Baba Suwe ? 60352#0 awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ní ọdún 1922? 60391#0 Ki ni orukọ ile iṣẹ ti Dapo Abiodun da silẹ? 60406#0 ati ilu wo ni ede geesi ti wa ? 60435#0 Kontinenti wo ni Jamaika wa? 60451#0 Ilu wo ni won bi Victor Anichebe si? 60638#0 Ibaṣepo wo lo wa laarin Peter ati Jesu ninu Bibeli? 60675#0 Eniyan meloo lo n gbe ni Villeneuve-d'Ascq? 61003#0 ilu wo lo tibi julọ ni ipinle Bahia? 61062#0 Ki ni orukọ ẹgbẹ oloṣelu ti Herbert Macaulay da silẹ? 61263#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Bulgaria? 61267#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile ede Bulgaria? 61282#0 Kin ni awọ asia orile-ede Bahamas? 61830#0 oṣu meloo lo wa ninu ọdun? 61865#0 Awọn oogun wo ni eeyan le lo lati fi wo aisan oju san? 61883#0 Ki lo ma n fa arun malaria? 61953#0 Awon sistemu meta wo lo wa ni ede Japanese? 62019#0 Oogun wo ni eeyan le lo fun taifọọdu? 62111#0 Ki ni o ma n fa arun Meningococcal? 62211#0 Erekuṣu wo ni a ti le ri Alangba Komodo? 62223#0 awon ẹya alangba meloo lo wa? 62234#0 awọn ẹranko wo ni wọn ma n gbe'le aiye pẹ́ jù? 62364#0 ẹranko wo lo tobi ju lọ nile aiye? 62459#0 olorin wo lo kọ "Billie Jean" ? 62473#0 Bawo ni Esther ṣe jẹ ninu bibeli? 62487#0 Ta ni ẹni tó dá Linux sílẹ̀? 62585#0 Ọsu wo ni akọkọ ninu ọdun? 62594#0 ọdún wo ni Bola Tinubu jẹ gomina Eko? 62597#0 Igba wo ni wọn ma ṣe idibo ni orile-ede Amerika? 6505#0 ọdun wo ni ọkọ ofurufu Sosoliso ja lulẹ ni Naijiria? 65770#0 Odun wo ni wọn bi elere idaraya ti Jamaika ti a mọ si Yohan Blake? 65781#0 Ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede Taiwan? 65947#0 Yunifasiti wo ni Bukola Saraki ti ka'we? 66449#0 Omo odun meloo ni Alan Turing nigba ti o ku? 66454#0 Egbe agbaboolu wo ni Willy Caballero n gba boolu fun? 66883#0 Ara ilu wo ni Niyi Akinmolayan? 67530#0 Yunifasiti wo ni Dapo Abiodun ti ka'we? 67648#0 Ọmọ mélòó ni Odùduwà bí ? 67726#0 kí ni oluilu orile-ede South Sudan ? 67866#0 Kini oruko ṣọọsi ti David Oyedepo da silẹ? 67944#0 Ile-iwe eko giga wo ni Tam David West ti kawe? 68042#0 Ta ni ẹni tó ní ilé iṣẹ soundcity ? 68128#0 Iṣẹ wo ni Lizzy Anjorin ṣẹ? 68177#0 iru orin wo ni Fela Kuti kọ? 68257#0 Odun wo ni Frederick Fasheun ṣ'alaisi? 68332#0 Ta ni o da ilé iṣẹ Instagram silẹ? 68382#0 Odun wo ni Aremu Gbadebo je Alake? 68412#0 Ta ni o da ile iṣẹ Daar Communications silẹ? 68449#0 Bawo ni awọn Hausa ṣe n ṣe Fura ti wọn? 68452#0 Ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ Facebook silẹ? 68729#0 Awon eya wo ni Ghana ni won sọ ede Akan 68921#0 Odun wo ni ogun Kiriji bẹrẹ? 69129#0 Ilu wo ni wọn bí Yvonne Nelson si ? 69146#0 Iṣẹ wo ni Aisha Buhari n ṣe?? 69209#0 Omo orile ede wo ni William Onyeabor? 69258#0 Ibasepo wo lo wa laarin Oluremi ati Bola Tinubu? 69260#0 ilé iṣẹ iroyin wo ni Eugenia Abu bá ṣiṣe? 69301#0 Akọwe wo lo kọ "Things fall apart"? 69308#0 ọdún wo ni oba rilwanu Akiolu di ọba eko? 69396#0 Odun wo ni Botswana gba ominira? 69434#0 Kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti Alhaji Razaq Ọkọya da silẹ? 69691#0 oṣù wo ni àjàkálẹ̀ àrùn COVID dé Nàìjíríà? 69708#0 Orile ede wo ni àwọn Xhosa pọsi jù lọ? 70116#0 Ilu wo ni Moshood Abiola Politekniki wa? 70124#0 ọdun wo ni orile-ede Naijiria gba ominira? 70144#0 Ki ni oruko bibi osere Ade Love 70154#0 Ebun fiimu wo ni Nse Ikpe-Etim gba ni odun 2014? 70169#0 Awọn orukọ wo ni a n pe ni orukọ amutorunwa? 70186#0 Ọdún wo ni Ayo Fayose di gomina ipinlẹ Èkìtì? 70298#0 Omo ilu wo ni Kemi Adeosun? 70317#0 Ọdún wo ni òṣèré Rachel Oniga bẹrẹ sí ṣe eré itage? 70430#0 Odun wo ni Stella Obasanjo s'alaisi? 70487#0 Omo meloo ni Bose Ogulu bi? 70501#0 ọdun wo ni Teniade Aofiyebi kopa ninu fiimu Flower Girl? 70508#0 Ara ilu wo ni Lisa Omorodion? 70580#0 oṣere wo ni a mọ si Hubert Ogunde? 70588#0 awon fiimu wo ni Rosaline Meurer ti se? 70604#0 Omo orile ede wo ni Kamaru Usman? 70639#0 Ile iṣe wo ni Ugonna Umerou da silẹ? 70723#0 Ọmọ orile ede wo ni Kansiime Anne? 70727#0 onkowe wo lo kọ Igbo olodumare? 70760#0 Ibasepo wo lo wa laarin Tariro ati Emmerson Mnangagwa? 70931#0 Kontinenti wo ni Peru wa ? 71075#0 Ta ni o kọkọ jẹ aare orile ede Tunisia? 71133#0 Orile ede wo ni Kunqu Opera ti wá? 71225#0 Orile-ede wo ni wọn bi Elon Musk si? 71253#0 Awon oṣere wo lo se ere Love Castle? 71290#0 Odun wo ni Nana Akufo Addo je aare orile ede Ghana? 71301#0 Odun wo ni Erica Nlewedim kopa ninu ere Big Brother? 71355#0 Orile ede wo ni Sacramento wa? 71373#0 Orile ede wo ni ilu Ghadames wa? 7147#0 Agbegbe wo ni Eko ni Desmond Elliot n se asoju fun? 7148#0 ọdun wo ni wọn bẹrẹ Ẹbun Nobel? 9149#0 Ki ni oluilu ipinle Ọsun? 9441#0 Odun wo ni Stella Obasanjo fi aiye silẹ? 9505#0 Odun wo ni wọn bi akọrin Adekunle Gold? 9593#0 Kí ni orúkọ bibi akọrin Naira Marley?