10494#0 ọdun wo ni wọn pa funsho william? 10773#0 osu meloo ni oyun ma n lo nínú ikun obinrin ? 10981#0 Ki ni oruko ibilẹ ilu Port Harcourt? 11043#0 ipinlẹ wo ni gbenga Daniel ti jẹ gomina? 11172#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Burkina-Faso? 11296#0 Ki ni oluilu Bangladesh? 11435#0 Odun wo ni Nwankwo Kanu da pọ mọ Arsenal? 11775#0 Ki ni orukọ iyawo Babatunde Fasola? 11810#0 Ki ni oluilu orile ede Bulgaria? 12525#0 Ki ni oluilu orile ede Hungari? 12957#0 bawo ni sau Paulo ṣe jinna tó sí Rio De Janeiro? 12971#0 Ki ni orukọ ọmọ anọbi Idris ninu Kurani? 13297#0 ọmọ orílé ede wo ni Bill Gates ? 13307#0 orile-ede meloo ni o wa ni Europe? 13310#0 kini oluilu orile-ede Paraguai? 13342#0 Kí ni oluilu orile-ede El Salvador? 13361#0 Ta ni o da ile iṣẹ Innoson silẹ? 13541#0 Awon odun wo ni won ma n se ni orile-ede Bhutan? 13590#0 Orisi kemika wo lo wa? 13690#0 Ki no won ma n fi kemika iodine ṣe? 13760#0 iru awon eja wo ni eeyan le ri ninu odo? 13883#0 Orile ede wo ni Cape Town wa ? 13915#0 kí ni oluilu ipinle Akwa-Ibom? 14163#0 eya mélòó lo wa ni orile-ede Naijiria? 14498#0 Iṣẹ wo ni Sunday Igboho n ṣe? 14515#0 Ede meloo ni won so ni orile-ede Benin? 14681#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin awọn Giriki aye ijọun ati awọn ara Egypt? 14745#0 Orile-ede wo lo ni NASA? 14767#0 ọdún wo ni wọn dá NASA silẹ? 14783#0 Odun wo ni wọn pari ogun agbaye ikeji? 14787#0 Odo wo lo gun ju ni orile-ede Liberia? 14810#0 ọdún wo ni ọkọ ofurufu kọkọ tẹ'do sí Naijiria? 14826#0 ogagun wo lo ṣe aṣáájú àwọn ologun Biafra ni odun 1967? 14874#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa? 14970#0 awọn nkan wo lo lè fa ijamba ọkọ ofurufu? 15062#0 Ki ni oluilu ipinle akwa ibom? 15084#0 Ki ni oluilu orile ede Tonga? 15086#0 Orile ede meloo lo wa ni NATO? 15099#0 Orile ede wo ni ilu Alexandria wa? 15101#0 Ki lo pa Alan Turing? 15121#0 Iwe wo ni Immanuel Kant kọ? 15197#0 Iwe wo ni Ibn Battuta kọkọ kọ? 15241#0 Onimo mathematiki wo lo gbe Algebra jade? 15252#0 awọn ẹbun wo ni Roald Engelbregt gba ? 15256#0 Ibasepo wo lo wa laarin ede Latini ati ede geesi? 15265#0 Ta ni oba orile ede Bahrain? 15309#0 ara ìlú wo ni mama to bi Muritala muhammed? 15317#0 ki ni iye eeyan ti o wa ni abule Aliyu Amba ni Ethiopia? 15325#0 ẹgbẹ agbaboolu wo ni Kelechi Iheanacho wa pẹlu? 15335#0 Orile ede wo ni wọn bí Kamaru Usman sí? 15349#0 iru sistemu ìjọba wo ni wọn lo ni fransi? 15367#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni David Mark wa pẹlu? 15374#0 Egbe oselu wo ni Nicolas Sarkozy wa pẹlu? 15444#0 mosalasi wo lo tobi julo ni orile-ede Algeria? 15498#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni orile-ede Albania? 15511#0 Omo orile ede wo ni Kevin Durant? 15517#0 ọdún wo ni Hubert Ogunde da ilé iṣẹ tíátà rẹ silẹ? 15596#0 Omo orile ede wo ni Cheikh Diop? 15629#0 ọdun wo ni wọn kọkọ ṣe komputa? 15734#0 ilé iṣẹ radiio wo ni Tolu Oniru n ba ṣiṣẹ? 15777#0 Ṣe orile-ede Bhutan wa ni Asia? 15783#0 Ṣe orukọ Potugiisi ni Silva? 15787#0 Ki ni oluilu Burkina Faso? 15805#0 ọdun wo ni orile ede Kongo gba ominira? 15807#0 ipo wo ni Adolphe Muzito je labe ijoba Joseph Kabila? 15808#0 Ilu wo ni won bi Rafael Nadal si? 15809#0 ki ni iye eeyan to wa ni orile-ede kroatia? 15810#0 ile iṣẹ oniroyin wo ni Toke Makinwa wa pẹlu? 15819#0 Awọn orile-ede wo lo sunmo Djibouti? 15822#0 Awọn Orile-ede wo lo wa ni Soviet union? 15833#0 Kini iyatọ laarin awọn ara Ethiopia ati Eritrea? 15847#0 Osu wo ni odun keresimesi bọ si? 15868#0 Ilu wo ni agabọọlu Pepe n gba bọọlu fun? 15882#0 obinrin alawọ dudu wo lo kọkọ yege idije Miss World? 15884#0 ọdun wo ni agbani darego yege idije Miss World? 15892#0 Iṣẹ wo ni ọkọ Omotola Jalade n ṣe? 15898#0 Ki ni wọn n pe ni Eurasia? 15909#0 Ede wo ni won sọ ni orile-ede Ireland? 15919#0 Eeyan meloo lo n ṣe ẹsin kristeni ni orile-ede Jordan? 15922#0 Kí ni ìtúmò Karim ni ede lárúbáwá? 15954#0 Awọn ede wo ni wọn sọ ni Kuwait yatọ si Larubawa? 15970#0 Ara ilu wo ni Hans-Adam? 15974#0 ọdun wo ni a ma n ṣe ni oṣu December? 16001#0 kí ni olu-ilu orile-ede norway? 16005#0 Orile-ede wo lo fẹ ju lo ni Europe? 16007#0 Ipinle wo ni Ilu Gbongan wa? 16009#0 Ta ni Aarẹ ikẹta orile-ede United States of America? 16019#0 Kilọọbu wo ni agbabọọlu Robert Lwandowski n gba bọọlu fun? 16238#0 orile ede wo ni Ilu Madrid wa? 16281#0 Ta ni iyawo Bill Clinton? 16288#0 Awọn orile-ede wo ni wọn ti n sọ ede faranse ni Afirika? 16297#0 Èdè wo ni àwọn ará orile ede Nepal n sọ? 16299#0 Ọmọ orílé èdè wo ni akọrin Peter Tosh? 16312#0 Ki ni orukọ iyawo Muhammad Ali? 16365#0 Ẹgbẹ wo ni agbaboolu ti a mọ sí Roberto Carlos bá gbá bọọlu gbẹhin kí ó tó fẹ̀hinti? 16373#0 Omo orile-ede wo ni onimo mathematiki Carl Friedrich? 16376#0 kí ni iye eniyan to wa ni orile ede switsalandi? 16382#0 Odun wo ni won bere ogun orile-ede Siria? 16391#0 ta ni ààrẹ akọkọ orílé èdè Togo? 16407#0 Odun wo ni Sultan Muhammadu Maccido ku? 16426#0 ara ìlú wo ni oludasile Google ti a mọ sí Sergei brin? 16427#0 Odun wo ni won bi onisowo Efunroye Tinubu? 16479#0 Ta ni ààrẹ orile-ede Ethiopia? 16656#0 awon apa ijoba meloo lo wa? 16664#0 Ilu wo lo tobi julo ni ipinle Anambra? 16727#0 Odun wo ni Samuel Peter ba Vladmir Klitschko ja? 16770#0 Ki ni oruko bibi alawada Frank Donga? 16781#0 Ki ni oluilu ipinle Ondo? 16798#0 Odun wo ni Ekiti ati Ondo ya sọtọ? 16801#0 Awon ẹya wo lo wa ni ilu Ẹlẹmẹ? 16861#0 ilu wo lo tobi julọ ni ipinlẹ rivers? 16956#0 Tani Philip Efiong ja fun ni Ogun Biafra? 17021#0 Omo ilu wo ni Ngozi Nwosu? 17024#0 Ipo oselu wo ni Lamidi Adesina di mu gege bi oloselu ? 17206#0 Omo ipinle wo ni Lateef Adedimeji? 17214#0 Gomina meloo lo wa ni orile-ede Naijiria? 17238#0 Bawo ni oju ojo se ma n ri ni ipinle Enugu? 17258#0 Tani gomina ipinle Ekiti? 17287#0 ṣe wọn ni epo ni ipinlẹ rivers? 17323#0 ilu wo lo tóbi jù lọ ní ipinlẹ ebonyi? 17325#0 Ki ni kapitaali ipinle Ebonyi? 17372#0 kí ni orúkọ ọba sultan ilu sókótó? 17476#0 Ọdun wo ni awọn ologun gba ijọba ni Naijiria? 17478#0 Ṣe papa ọkọ ofurufu wa ni Ipinle Enugu? 17485#0 Se Ile Ibo ni ipinle Enugu wa? 17518#0 Ede wo ni awon ara Imo n sọ? 17534#0 Lábé ìjọba aare Naijiria wo ni àwọn òṣìṣẹ́ ti ṣe àtakò occupy Nigeria? 17539#0 kí ni olú ìlú ipinlẹ Rivers ? 17558#0 Awon ile iwe wo lo wa ni agbegbe orumba? 17559#0 Ki ni olu-ilu ipinle Anambra? 17589#0 Ta ni ọba wọn ni Ilẹ Sokoto? 17600#0 Ta ni Sultan Sokoto ni odun 2003? 17612#0 Ọdun melo ni Shehu Shagari lo lori Aleefa? 17644#0 Ta ni gomina ipinle Sokoto? 17658#0 Ki ni itumo Enugu ni ede Igbo? 17695#0 Ta lo kọkọ jẹ Sultan ipinlẹ Sokoto? 17758#0 Awon esin wo lo gbajumọ ni orile-ede jemani? 17820#0 Ipo wo ni agbabọọlu Thomas Muller n gba fun Bayern Munich? 18094#0 Ta ni obinrin to kọkọ gba ebun nobel? 18226#0 Ilu wo lo tobi ju lọ ni ipinlẹ Ogun? 18307#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Olabisi Onabanjo wa? 18308#0 Odun wo ni Oladipo Diya je gomina ipinle Ogun l'asiko ijoba ologun? 18321#0 ati orile-ede wo ni pasta ti wa ? 18356#0 Awon eranko wo lo wa ni Australia? 18357#0 Awon orile-ede wo ni o wa ni Melanesia? 18397#0 Odun wo ni Fidel Castro kuro lori aleefa? 18519#0 Orile ede wo ni odo Amazon wa? 18548#0 Orile-ede wo ni ilu Houston wa? 18560#0 Ta ni Aare orile-ede Amẹrika? 18574#0 orile ede wo ni awọn elesin onigbagbo pọ si ju lọ? 18581#0 Orile ede wo ni Ras Al Khaimah wa? 18607#0 Ki ni olu ilu ipinle cross river? 18640#0 Ta ni ààrẹ Orile ede Tajikistan? 18642#0 kí ni oluilu orile ede Peru? 18665#0 Iru owo wo ni won na ni orile-ede Morocco? 18667#0 Odun wo ni orile ede Mozambique gba ominira? 18668#0 ọdun wo ni orile-ede Mozambique gba ominira? 18705#0 awon ipinle wo ni won yọ jáde lati ipinle gongola? 18809#0 Iru ounjẹ wo ni wọn ma n jẹ ni ipinle Akwa Ibom? 18839#0 Awon eya meloo lo wa ni orile-ede Nigeria? 18859#0 Ilu wo ni won bi Serena Williams si? 18964#0 ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Ibrahim Shekarau wa pẹlu? 19044#0 Ọdun wo ni wọn kọkọ ṣe iwari epo ni ipinlẹ Bayelsa? 19071#0 Ki ni oluilu ipinle kebbi? 19115#0 Ki ni oluilu ipinlẹ Niger? 19133#0 Odun wo ni Musilliu Haruna Ishola kọ soyoyo? 19232#0 Iyawo meloo ni Solomon fẹ ninu bibeli? 19245#0 Odun wo ni Aminu Tambuwal di gomina Sokoto? 19270#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin awọn Taliban ati Pakistan? 19408#0 Lati igba wo ni won ti n jagun ni orile-ede South Sudan? 19535#0 Ki ni oruko aare orile-ede Italy? 19661#0 Omo odun meloo ni Mike Tyson nigba to kọkọ gba oye heavyweight? 19971#0 Orile-ede wo ni ilu Dar es Salaam wa? 19976#0 Omo ilu wo ni Hassan Minhaj? 19977#0 Ise wo ni Benjamin Franklin ṣe? 20007#0 Ki ni awọn kan ti eeyan le ṣe ni Zanzibar fun isinmi? 20022#0 ede meloo ni won so ni orile-ede tanzania? 20041#0 Awon orile ede wo lo yika Tanzania? 20221#0 orile-ede wo ni a mo gẹgẹ bii Giant of Africa? 20240#0 Egbe agbaboolu wo ni agbaboolu Fernando Torres koko gba boolu fun? 20252#0 Kí ni iye èèyàn dúdú ti ó wà ní orílé èdè Brazil? 20255#0 nọmba wo ni a le pe ti a ba wa ninu ìṣòro? 20338#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Thomas Edison? 20440#0 Se Tibet sunmo orile-ede China? 20453#0 Ki ni asia orile-ede Morocco? 20467#0 Kí ni àwọ àsìá Orile ede Pakistan ? 20523#0 Ede meloo ni wọn so ni orile-ede Pakistan 20573#0 Kí ni orúkọ ilé ìjọsìn David Oyedepo? 20581#0 Awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni ọdun 1920? 20647#0 Ibaṣepọ wo lo wa laarin Michael Jackson ati Janet Jackson ? 20685#0 ile iwe eko giga wo ni Donald Trump ti jade? 20692#0 Akowe wo lo kọ iwe Arrow of God? 20772#0 Odun wo ni Ogun Agbekọya bẹrẹ? 20782#0 Kí ni oluilu ipinle Jigawa? 20982#0 ìyàwó mélòó ni osama bin Laden fẹ́? 21005#0 ọdún wo ni orile-ede Senegal gba ominira? 21115#0 Kí ni oluilu orile-ede Macedonia? 21197#0 Ki ni oluilu orile ede Albania? 21425#0 èdè wo ni àwọn ará Papua n sọ? 21498#0 Erekusu wo lo tobi ju lọ ni agbaye? 21520#0 Nibo ni ipinlẹ Enugu ni awọn oyinbo ti kọkọ ri eedu? 21578#0 Olukowe wo lo kọ iwe Jagua Nana? 21580#0 Ọdún wo ni ẹlẹsẹ Samuel Peter ba Klitschko ja? 21582#0 Ọdún mélòó ni Ike Ibeabuchi lo lẹ́wọ̀n? 21583#0 Ilu wo ni won bi Jaja Wachuku si? 21666#0 Ọmọ ipinle wo ni Uche Jombo? 21904#0 Odun wo ni orile ede Colombia gba ominira? 21915#0 Odun wo ni Ronald Reagan jẹ gomina California? 22000#0 Eya meloo lo wa ni orile-ede Uganda? 22034#0 Yunifasiti wo ni Bill Gates ti kàwé ? 22043#0 Ki ni Iṣẹ igbakeji aarẹ? 22066#0 kí ni orúkọ ọkọ Maria sharapova? 22133#0 Esin wo lo gbajumo ju lo ni orile-ede Ireland? 22144#0 Ki ni oluilu orile ede Uganda? 22218#0 Awọn orile-ede wo lo sunmọ Italy? 2230#0 Odun wo ni akọwe Adebayo Faleti bere si sise pelu WNTV? 22470#0 Awon orisi jeometri wo lo wa? 22498#0 Ta ni olori ẹgbẹ al-kaida? 22501#0 Orile ede wo ni ilu Boston wa? 22521#0 owo korensi wo wọn n ná ní orílé èdè Pakistan? 22522#0 Awon ipinle wo lo tobi julo ni orile-ede Amerika? 22525#0 Odun wo ni won bi oṣere Samuel Jackson? 22532#0 Oke wo lo ga ju ni orile-ede Australia? 22553#0 Ta ni o n je Edward Blyden? 22562#0 Se orile-ede Griisi dara? 22595#0 Ilu wo ni George Washington ṣe Aarẹ fun? 22654#0 Olorin wo lo ni okiki ju ni orile-ede Griisi? 22677#0 Orile ede wo ni ilu Athens wa? 22802#0 Ta ni o gba ẹbun Nobel fun litireṣọ ti ọdun 2016? 22860#0 esin wo ni John Maxwell n ṣe? 2291#0 ta ni Onkowe to ko iwe "The art of war'? 22917#0 Ilu wo lo tobi julọ ni orile-ede Jemani? 22955#0 Aarẹ wo ni Afrika lo fi'ra ẹ jẹ Field Marshall 23142#0 Ki ni olu-ilu orile-ede Argentina? 23186#0 Orile ede wo ni agbaboolu Roberto Carlos gba bóòlù fún? 23245#0 Awon eya wo lo tobi ju lọ ni orile-ede sierra leone? 23551#0 ọdún wo ni Carl Pauling gba ẹbun Nobel? 23562#0 Omo orile ede wo ni Karl Marx? 23567#0 elo ni wọn san fún àwọn tí wọn bá gba ẹbun Nobel ? 23599#0 Bawo ni orile-ede Kanada ṣe tobi to? 23647#0 Kí ni oluilu orile-ede Switzerland? 23706#0 Ilu wo ni won bi Maurice Bishop si? 23712#0 ilu wo ni won bi Joseph Stalin si? 23732#0 Ara ilu wo ni ẹlẹṣe felix trinidad? 23845#0 Ta ni eni to kọkọ lọ si space? 24197#0 Ki ni orukọ bibi Akọrin Afrika Bambaata? 24311#0 èdè wo ni wọn sọ ni orile-ede thailand? 24335#0 ta ni Alakoso ilu dubai ? 24910#0 Awọn ọunje wo lo da fun ilera ati alaafia? 25182#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré Taiwo Hassan ? 25231#0 Awọn òpìtàn wo lo kọ nípa ìtàn Nàìjíríà? 25394#0 Awọn ẹya meloo lo wa ni orile-ede kongo? 2567#0 Ede wo ni won so ni orile-ede Afghanistan? 25674#0 ọdún wo ni asiwaju Bola Tinubu kọkọ jẹ gomina ipinle Eko? 2571#0 elo ni wọn ta oruka ti ìgbéyàwó? 25763#0 ọdún wo ni Keshi di mọnija ẹgbẹ agbaboolu Naijiria? 25952#0 orile-ede wo ni agbaboolu Pele gba bọọlu fún? 25953#0 awon ere idaraya wo lo gbajumo ni orile-ede Naijiria? 2598#0 ṣe ede larubawa ni wọn n sọ ni orile-ede Algeria? 26004#0 Odun wo ni Augusto Pinochet fi aye silẹ? 26090#0 Aare Amerika wo lo da eru kiko duro? 26145#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo lo tóbi jù lọ ní orile ede Kroatíà? 26186#0 awọn orile ede wo ni àwọn komunisti pọ sí jù? 26190#0 Ara Ilu wo ni Rosa Luuxemburg? 26237#0 ọdún wo ni orile-ede Nàìjíríà di republiki? 26342#0 ki ni itumo keynesian economics? 26401#0 Ọdún wo ni Joseph Stalin fi ayé silẹ? 26468#0 Ilu wo ni won bi Alfred Hitchrock si? 26876#0 kí ni ìjọba Buhari ti ṣe fún ìdàgbàsókè orile-ede Naijiria? 27059#0 Ilu wo ni wọn bi Wilson Oruma si? 27063#0 Fiimu wo ni Chadwick Boseman kọ́kọ́ ṣe? 27067#0 Iwadi wo ni Sir George Thomson gbe jade? 2709#0 Odun wo ni DO Fagunwa kọ iwe Ogboju Ode? 27113#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Tinubu ati Fashola? 27120#0 ṣe lootọ ni wipe omi agbara lo gbe Metusela lọ? 27373#0 Ilu wo ni won bi Adam Smith si? 2741#0 Awọn onisayensi wo ni wọn wa lati orile-ede Armenia? 2749#0 Ki ni oluilu Andorra? 27746#0 Ipinle wo ni Phillip Edward Island wa ni Canada ? 27753#0 Odun wo ni Mohammad Abdus Salam gba ẹbun nobel? 27782#0 Ki ni oruko eni to kọkọ gba ebun nobel fun kemistri? 27802#0 kí ni orúkọ ilé iṣẹ ti jack Dorsey da silẹ 27804#0 Ki ni oruko bibi olorin Roy Chicago? 27815#0 Ara ilu wo ni ẹlẹṣẹ Vitaly Klitschko? 28166#0 egbe oṣelu wo ni Barack Obama wa pẹlu? 28209#0 Ara ilu wo ni Ralph Lauren? 28404#0 ede wo ni won so ni orile-ede virgin islands 2853#0 Nibo ni Afirika ni Madagascar wa? 28626#0 Oṣu wo ni ọdun Easter bọ si? 28630#0 Ojo melo lo wa ninu oṣu Februrari? 28770#0 Ki ni anfani ogẹdẹ jijẹ? 2901#0 Ta ni eniyan akọkọ ninu bibeli? 29099#0 Awọn iṣẹlẹ wo lo ṣẹlẹ ni Ọdún 1975? 2925#0 awọn èdè wo ló ṣòro láti kọ́ jù? 29322#0 Awon iwe wo ni Henry James ko? 29343#0 Ise wo ni Ludwig Van Beethoven ṣe? 29350#0 Iwadi wo ni otto warburg ṣe to fi gba ebun nobel? 29601#0 Onimọ sayensi wo lo gbe alaye evolution jade? 29796#0 ọdun wo ni Bill Gates da ile-iṣe Microsoft silẹ? 2988#0 Orile ede wo ni won ti n so ede Bijago? 30023#0 Ile-ise wo ni Ezra Olubi da sile? 30046#0 ki ni iye eeyan alawodudu to wa ni orile-ede Argentina? 30054#0 Esin wo ni awọn Tuareg n ṣe? 30081#0 Olorin wo lo kọ orin "African Queen"? 30203#0 Ta ni o gba Ebun Nobel Fisiiksi odun 1999? 30205#0 Awon awari ati iwadi wo ni onimosayensi Albert Einstein gbe jade? 30208#0 ọdún wo ni Dominique Pire gba Ebun Nobel? 30242#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Morocco? 30365#0 Ọdun wo ni oṣere Jeff Bridges ṣe sinima "The Fisher King" ? 30366#0 Kí ni orúkọ inagijẹ onisowo orin Sean Combs ? 30369#0 Awọn ẹbun wo ni Jack Nicholson ti gba fún eré ṣíṣe? 30374#0 ọdún wo ni robert De niro bẹrẹ sí ṣe òṣèré? 30416#0 àwọn òṣèré wo lo ṣe fiimu "The avengers" ? 30459#0 Odun wo ni Josehine Baker fi aiye silẹ? 30516#0 Iwadi wo Baron de montesquieu gbe jade? 30579#0 Egbe agbaboolu wo ni Luis Figo ba gba gbehin ki o to fehinti? 30703#0 Ibaṣepo wo lo wa laarin Pakistan ati India? 31085#0 Tani Baba Jccob ninu Bibeli? 31331#0 Pilaneeti wo lo tobi ju ̀lọ? 3171#0 Ki ni olu ilu orile-ede Cameroon? 3178#0 Awon orile-ede wo ni won ti n so Yoruba yato si Naijiria? 32899#0 Iwe wo ni Umberto Eco kọkọ kọ? 32946#0 Ojise olorun meloo ni o wa ninu kurani? 32958#0 Ọdun wo ni wọn pari Ogun Biafra? 3327#0 iru kalẹnda wo ni àwọn ará Ethiopia n lo? 33282#0 Ki ni itumọ Homo Sapien? 3346#0 Ki ni iyatọ laarin "odd nomba" ati "even nomba"? 33463#0 ṣẹ alawọ dudu ni baba to bi Lewis Hamilton? 33519#0 Orile ede wo ni won bi Karl Marx si? 33566#0 Ta ni eni to koko gba ebun Nobel fun kemistri? 33568#0 Ile-ise iroyin wo ni Benjamin Franklin ba ṣiṣẹ gege bi akọwe? 3360#0 Ki lo de ti Imọ mathematiki ṣe le pupọ? 33626#0 Egbe agbaboolu alapere wo ni Kareem Abdul Jabbar gba fún? 33682#0 Eeyan meloo ni King Leopold pa ni orile-ede Congo? 33692#0 Ilu wo ni won bi onkowe Wiliam Shakespeare si? 33857#0 Omo orile ede wo ni Maria Sharapova? 33953#0 Awon awari sayensi wo ni John von Neumann gbe jade? 33976#0 Odun wo ni Joseph Stalin s'alaisi? 33997#0 ọdun wo ni wọn da orile-ede Amerika silẹ? 34094#0 Obinrin wo lo kọkọ jẹ adajọ ni orile-ede Naijiria? 34105#0 ipò wo ni Teslim Elias jẹ ni International court of justice? 34135#0 egbe agbaboolu afesegba wo ni Joachim low n gbe lọ si World Cup? 34138#0 Ki ni o fa iku Giordano Bruno? 34140#0 Omo orile-ede wo ni akowe Walter rodney? 34150#0 awọn àṣà wo ni a mọ yoruba fún? 3487#0 kí ni nọmba ọlọpa ti a le pe ta ba wa ninu ọrọ òjìji? 35524#0 Awon orile-ede wo ni Afrika ni awon somali wa? 35534#0 Odun meloo ni Freddie Ljumberg lo ni Arsenal? 35546#0 Ise wo ni Whoopi Goldberg n se? 35579#0 Ọdún wo ni Ronald Reagan jẹ ààrẹ Orile-ede Amẹrika? 35617#0 Ilu wo ni wọn bi Colin Powell si? 35909#0 ile ise rekoodu wo ni Barbra Joan wa pẹlu? 35915#0 Odun wo ni Diane Keaton bere si se fiimu? 35926#0 Awọn oṣere wo lo ṣe sinima "Black Panther" ? 35927#0 Ta ni ọkọ Laura Ikeji? 36817#0 Odun wo ni Bola Tinubu di Seneto? 36873#0 Iru orin wo ni Segun Adewale n kọ? 36877#0 Ta ni onilu Àlàmú Tatalo? 36889#0 iru orin wo ni Majek Fashek kọ? 36893#0 Ilu wo ni wọn bí Kelechi Iheanacho sí ? 36898#0 ile iṣẹ wo ni Peter Thiel da silẹ? 36940#0 Agbegbe wo ni Senator Abaribe n ṣe aṣoju fún? 37099#0 Ki ni Nnamdi Kanu n ja fun? 37133#0 Ki ni idi ti Suka Dimka ṣe fẹ pa Murtala? 37145#0 ọmọ mélòó ni òṣèré samuel jackson ni ? 37162#0 Ki ni orukọ owo ti wọn na ni orile ede Spain? 37171#0 Ki ni oluilu orile-ede spain? 37182#0 Awon ilu wo lo tobi ju lọ ni Spain? 37197#0 orile ede wo ni ilu San Francisco wa? 37202#0 Awọn oloṣelu wo lo gba ominira fun orile-ede Ghana? 37245#0 ọdún wo ni orile-ede venezuela gba ominira? 37271#0 Ilu wo ni won bi Crristobal Hurtado si? 37276#0 Awon nkan ilẹ adayeba wo ni won ni ni orile-ede Venezuela? 37479#0 Odun wo ni oṣere Moses Olaiya fi aiye silẹ? 37591#0 orile-ede wo ni arturo Vidal n gba bọọlu fún ? 37653#0 ọdun wo ni George washington ṣ'alaisi? 37671#0 Odun wo ni George Bush di Aare orile-ede Amerika? 37697#0 Ilu wo ni won bi Alexander the Great si? 37738#0 ọdún wo ni Colin Powell fi ayé silẹ? 37773#0 Iwari wo ni Albert Einstein gbe jade? 37854#0 awọn òṣèré wo lo ṣe fiimu "black panther" ? 37991#0 ọdún wo ni ẹlẹsẹ ti a mo si oscar De la hoya ba Floyd Mayweather ja? 38035#0 Kini oluilu orile-ede Paraguay? 38050#0 ṣe awọn eeyan alawọ dudu wa ni orile-ede Trinidad? 38051#0 Ki ni koodu orile-ede Trinidad? 38162#0 Agbegbe ijjọba Ibilẹ wo ni Desmond Elliot n ṣe aṣoju fun? 38221#0 Ki ni oluilu orile-ede Belarusi? 38541#0 Oloselu wo lo ba MKO abiola dije ni ibo odun 1993? 38694#0 ipinlẹ wo ni wọn pe ni bendel tẹlẹ? 42261#0 Planeti meloo lo wa? 4410#0 Iru aso wo ni awon Yoruba ma n wọ? 44432#0 Ọdun wo ni ẹlẹṣẹ Buster Douglas ba Mike Tyson ja? 47009#0 Odun wo ni awon onimosayensi se awari 141 Lumen? 48503#0 ọdun wo ni Thutmose jẹ Farao ni ilu Egypt? 51063#0 bá wo ni àwọn Yorùbá ṣe má ń ṣe ọsẹ dúdú? 5126#0 Ki ni orukọ ọọni Ile Ifẹ? 5223#0 Ọdún wo ni Adesoji Aderemi jẹ Ọọni Ile Ifẹ? 53626#0 orisa wo ni orisa ibeji? 53718#0 Odun wo ni Chang Myon je Minisita orile-ede Korea 53740#0 Kí ni oluilu orile-ede Kenya? 53823#0 Iwadi wo ni Dan Shechtman se ti o fi gba ebun Nobel? 53830#0 Odun wo ni Bruce Lee se fiimu "Enter the dragon" ? 53881#0 Ilu wo ni won sin Octave Mirbeau si? 53890#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Corey Booker wa pẹlu? 5392#0 Odun wo ni Olagunsoye Oyinlola di gomina Osun? 53994#0 Ta ni aare Egypti ni ọdun 2010? 54187#0 Kí ni orúkọ inagijẹ Andre Young ? 54188#0 Ki ni orukọ akọrin Curtis Jackson? 54270#0 Iṣẹ wo ni Rosa Parks ṣe? 54280#0 awọn Orile ede wo ni wọn ti n sọ Swahili? 54282#0 Kontinenti wo ni orile-ede Komoro wa? 54445#0 akọwe wo lo kọ iwe Harry potter? 5452#0 Orile-ede wo ni Ásíà ni a ti le ri amọtẹkun? 54886#0 ẹkọ wo ni a le mu lo lati aye Jésù kristi? 55034#0 Ta ni o pa Martin Luther King? 55084#0 Ta ni ẹni to da ile iṣẹ Space X silẹ? 55585#0 Awon oloselu wo lo wa lati ipinle Jigawa? 55834#0 Odun wo ni Nelson Mandela kuro ni ẹwọn? 55868#0 Ede meloo ni won n so ni Ghana? 55988#0 Iwadi wo ni Isaac Newton gbe jade? 58427#0 ki ni idi ti ede igala fi jo ede Yoruba? 58461#0 Ounjẹ wo ni awọn South Afrika fẹran ju lọ? 58469#0 Ede wo lo l'okiki ju lọ ni Afrika? 58528#0 Iṣẹ wo ni Margaret Etim n ṣe? 58529#0 Ta ni Aarẹ orile-ede Russia? 58543#0 Ta ni ààrẹ orile-ede Saina? 58608#0 Odun wo ni Sam Amuka Pemu da ile iṣẹ iroyin Vanguard silẹ? 58616#0 ọjọ wo ni idije olympiki to n bọ ma bọ sí? 58639#0 ilu wo lo kere jù lọ ní orílé-ede fransi? 58653#0 Akorin wo lo kọ "Billie Jean" ? 58689#0 Odun wo ni wọn bi Elon Musk? 58694#0 ki ni oruko ilé iṣẹ ti Andy Rubin da silẹ? 58699#0 Ilu wo ni a bi agba oṣere Robin Williams si? 58921#0 awọn ẹranko wo lo wa ni ipinlẹ Florida? 58949#0 Awon orile ede wo ni Afrika ni won n sọ ede French? 59044#0 Odun wo ni jelena jankovic fehinti? 59086#0 Awọn akewi wo ni wọn wa lati orile-ede Romania? 59095#0 orile-ede wo ni ilu Fort Murray wa? 59165#0 ẹya mélòó lo wa ni orile-ede Kroatíà? 59166#0 awọn orilẹ-ede wo lo sunmọ Australia? 59178#0 Ki lo fa ogun ti Russia ati Ukraine? 59204#0 ilu wo ni won bi Tommy Haas si? 59313#0 Odun wo ni Sloane Stephens yege US open? 59530#0 Odun wo ni Gloria Macapagal di aare orile ede Fillipines? 59623#0 Awon iwadi wo ni onimo sayensi Stephen Hawking gbe jade? 59694#0 Ki ni itumo elimenti ni imo sayensi? 59736#0 awọn wo ló dá ẹgbẹ ọmọ oduduwa sí lẹ̀? 59753#0 iru metali wo ni aluminiomu? 59787#0 Orisi elimenti wo lo wa ? 59878#0 oríṣi atomu wo ló wà? 59915#0 ọdun wo Saddam Hussein ṣe alaisi? 59947#0 Ati orile ede wo ni Reggae ti wa? 60024#0 ilu wo ni wọn bí onkọwe Franz Fanon sí? 60031#0 Iru orin wo ni John Lennon kọ? 60037#0 ìwé wo lo ṣe pàtàkì jù lọ laarin gbogbo iwe ti Walter Rodney kọ? 60042#0 Awon orile ede wo lo sunmo Rọṣia? 60106#0 Ki ni orukọ inagije Charles Olumọ? 60131#0 Ise wo ni Jackie Aina n ṣe? 60184#0 Ilu wo ni wọn bi Serena Williams si? 60316#0 Egbe oloselu wo ni Doug Ford wa pẹlu? 60324#0 òṣèré wo lo ṣe fiimu Jẹnifa? 60349#0 ẹgbẹ agbaboolu alapere wo ni Kobe Bryant gba bọọlu fún gbẹhin? 60417#0 Ki ni oju ọjọ ni Ilu Florence? 60477#0 Egbe agbaboolu wo ni Ambrose Vanzekin n gba bọọlu fun? 60493#0 Onkowe wo lo kọ Harry Potter? 60527#0 Abala OPC wo ni Frederick Fasheun da silẹ? 60529#0 Odun wo ni agbaboolu Ji Sung Park fehinti? 60571#0 Odun wo ni won bi onimo sayensi Isaac Newton? 60709#0 Omi adagun meloo lo wa ni ipinlẹ Minnesota? 60756#0 Ilu wo ni won bi Nicki Minaj si? 60761#0 Odun wo ni Christopher Colombus se iwadi Amerika? 60767#0 ọdún wo ni wọn da ilé iṣẹ redio Lagos silẹ? 60777#0 ọmọ ìlú wo ni Linda Ejiofor? 60828#0 Ara ilu wo ni olusare Noah Lyles? 60879#0 Ọdún wo ni ẹlẹsẹ James Toney bá Samuel Peters jà? 60893#0 ọmọ meloo ni Serena Williams bi? 60980#0 Yunifasiti wo ni Akọwe Wọle Ṣoyinka ti kawe? 61045#0 àwọn akọrin wo lo wa lati orile-ede Korea? 61165#0 Ki ni orukọ iyawo ti Efrem Zimbalist kọkọ fẹ? 61169#0 Ọmọ mélòó ni Eve bi fún Adam ? 61172#0 Ki ni inagijẹ Dwayne Carter ? 61180#0 òṣèré wo lo ṣe fiimu True Lies? 61239#0 agbaboolu wo lo gbajumọ julọ ni orile-ede bulgaria? 61243#0 Ki ni awọ asia orile ede Naijiria? 61249#0 Ọdún wo ni wọn bí òṣèré Sofia Vergara? 61257#0 iru owo wo ni wọn ná ní Bulgaria? 61344#0 Kí ni ìtúmò Safari ni ede Swahili? 61412#0 Odun wo ni Telifisan kọkọ de Naijiria? 61423#0 ọdun wo ni wọn bi aarẹ Muhammadu Buhari? 61442#0 Awon ile iwe ẹkọ giga wo lo wa ni Santiago? 61517#0 ogun wo ni èèyàn lè lo fún àrùn malaria? 61676#0 Ta ni o da iwe iroyin El Marino silẹ? 61771#0 kí ni a mọ ilu Salamanca fun? 61775#0 kí ni o ma n fa àrùn onígbáméjì? 61798#0 ki ni o ma n fa arun ti a mo si atọsi? 61829#0 ki ni o ma n fa arun Onchocerciasis? 61835#0 Odun wo ni Cassius Clay yi oruko si Muhammed Ali? 61876#0 Erekusu wo ni Wakiki wa? 61880#0 erekusu wo lo tobi ju lo ni agbaye? 61882#0 Orile ede wo ni Tenerife wa? 61928#0 oríṣi mọ́tò wo ló wà? 61930#0 orisi ẹfọri wo lo wa? 61950#0 Orile ede wo ni ilu Hachinohe wa? 61975#0 Ki ni idi ti won se n pe Chile ni orile-ede awon Akewi? 62011#0 Bawo ni Moscow se jinna to si Saint Petersburg? 62015#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ? 62016#0 Oogun wo ni eeyan le lo lati fi pa kokoro? 62130#0 Ki ni orukọ iyawo Will Smith? 62168#0 Iye eniyan meloo lo wa ni orile-ede Scotland? 62175#0 kí ni o ma n fa arun ọpọlọ? 62183#0 Egbe agbaboolu afesegba wo ni Paolo maldini gba boolu fun? 62192#0 Ẹbun fiimu mélòó ni Stephen Spielberg ti gba ? 62194#0 Awọn akọwe ni wọn wa lati Vienna? 62218#0 kí ni ìdí tí alangba ṣe ma n mi'ri? 62227#0 Ki ni idi ti alangba ṣe ma n mi ori? 62229#0 awon eya wo ni won ma n je Edikan Ikong? 62231#0 Iru alangba wo ni Geico? 62257#0 ki ni itumo enzyme? 62295#0 idile wo ni Awujalẹ Sikiru Adetona ti wá? 62300#0 ọdun wo ni wọn da ẹgbẹ PDP silẹ? 62388#0 Ki lo pa elere idaraya ti a mọ si Florence Joyner? 62397#0 Iru awon alangba wo lo wa ni Afrika? 62424#0 Awọn iṣoro wo lo wa gẹgẹ bi obinrin ni Naijiria? 62444#0 Odun wo ni Lateef Adedimeji bẹrẹ si ṣe fiimu? 62453#0 Awon aami wo lo ma n han wipe obinrin ti ni oyun? 62461#0 Awọn ounjẹ wo lo ni protein ninu ju? 62465#0 Ilu wo ni wọn bí akọrin Tyler the creator sí? 62569#0 Ere wo ni oṣere Jackie Chan kọkọ ṣe? 6536#0 Iru orin wo ni akọrin Wizkid n ko? 65712#0 Ilu wo ni wọn bi ẹlẹṣẹ Roy Jones si? 65763#0 kí ni oluilu orile-ede Gambia ? 65767#0 ẹya wo lo tóbi jù lọ ní orile ede Liberia? 65784#0 Awo meloo ni Sikiru Ayinde Barrister ṣe ki o to ku? 65791#0 ilu wo ni wọn ti n ṣe awọn ẹṣọ Calvin Klein? 65821#0 Kí ni oluilu orile-ede Bẹljiọm? 65842#0 ọdún wo ni akorin Victor Olaiya ṣ'alaisi 65851#0 Awọn oniṣowo wo lo gbajumọ laiye ijọun ni ilu Ibadan? 66015#0 Ki ni oruko iyawo rotimi akeredolu? 66019#0 Ki ni oluilu orile-ede Israeli? 66023#0 kí ni orúkọ ile-iṣẹ ti Richard Branson da silẹ? 66100#0 Ki ni oruko ile-ise tI Sean Combs da sile? 66110#0 Ipo wo ni Bamanga Tukur jẹ labẹ ijọba Sani Abacha? 66113#0 Ipinle wo ni Aliyu Wamakko ti jẹ gomina? 66120#0 Ipò Ajagun wo lo tobi ju lọ ní Naijiria? 66342#0 ounje wo ni awon Hausa fẹran ju lọ? 66435#0 Awo meloo ni olorin Adewale ayuba ti ṣe? 66437#0 ọmọ ilu wo ni Lawrence Anini? 66443#0 Elo ni ijọba n san fun awọn agbofinro? 66445#0 Ara Ilu wo ni Bimbo Akintola? 66562#0 Orile-ede wo ni agbabọọlu Gabriel Jesus n gba bọọlu fun? 66876#0 Awon tira wo ni Sheik Adam Al Ilory kọ? 66945#0 ọdún wo ni wọn pa Tafawa Balewa? 66987#0 ile iṣẹ wo ni Femi Otedola da silẹ? 67007#0 bawo ni moremi ṣe tú àṣírí àwọn ará Igbo? 67036#0 Alaafin Oyo wo ni a mo si Orompotoniyun? 67047#0 Goolu meloo ni Muda Lawal gba wole fun Naijiria? 67317#0 Ta ni ẹni to kọ fiimu Ovy's voice? 67362#0 Odun wo ni 9ice gbe awo Gongo Aso jade? 67416#0 Ati ibo ni Aṣọ Ofi ti wa? 67527#0 Yunifasiti wo ni Funsho Williams ti kàwé? 67557#0 ile-ise wo ni Tara Fela-Durotoye da silẹ? 67562#0 Ọdún wo ni Wahab Folawiyo fi aiyé silẹ? 67610#0 Ki ni oluilu orile-ede Kenya? 67616#0 ọjọ wo ni Valentine bọ si? 67649#0 Odun wo ni won da OGBC silẹ? 67675#0 Awọn orile ede wo ni wọn ti n sọ Urdu? 67686#0 Awon irin ise wo ni akorin Prince lo? 67688#0 ọdún wo ni akọrin Fatai Rolling Dollar ṣ'àláìsí? 67760#0 Ilu wo ni won bi Immanuella Samueli si? 67764#0 Ọdún wo ni Chioma Ajunwa gba ẹbun ni ìdíje òlímpíkì? 67775#0 Ki lo pa Samuel Okwaraji? 67786#0 Odun wo ni Gbenga Daniel je gomina ipinlẹ Ogun? 67886#0 Ta ni ọba awọn ogu ni Badagry? 67907#0 Ki ni oruko iyawo Odunlade Adekola? 67942#0 Ipò wo ni Surajudeen Ajibola jẹ ni ipinlẹ Ọsun ? 67949#0 Ọdún wo ni Haruna Ìṣọ̀lá fi aiyé silẹ? 67956#0 yunifasiti wo ni gomina Dapo Abiodun ti kàwé? 67961#0 Odun wo ni olorin tupac shakur s'alaisi? 67991#0 ipo wo ni Robert Adeyinka je ni Western Region 68015#0 kí ni orúkọ ìyàwó Yemi Osinbajo? 68024#0 Ta ni Akran ilu Badagry? 68035#0 ilé iṣẹ wo ni Tony Elumelu da silẹ? 68047#0 Ọdún wo ni George Weah di ààrẹ orile ede Liberia? 68053#0 ọdún wo ni Bukky Wright bẹrẹ sí ṣe eré itage? 68058#0 Ta ni Baba Kunle Afolayan? 68059#0 ibaṣepọ wo lo wa laarin Gabriel ati Kunle Afolayan? 68234#0 Odun wo ni won da ile ifowoppamo Wema silẹ? 68240#0 Awon ile-ise wo ni Mark Zuckerberg da sile? 68242#0 Àwọn Gómìnà wo lo da ẹgbẹ amọtẹkun silẹ? 68250#0 awọn wo lo ko samuel crowther l'ẹ́rú? 68301#0 Kí ni èèyàn lè fi ata ṣọ̀mbọ̀ sè? 68376#0 Ipinle wo ni Samuel Ortom ti je gomina? 68427#0 kí ni olúìlú ìpínlẹ̀ Abia? 68435#0 Orile ede wo ni ilu Phoenix wa ? 68532#0 ta ni aṣoju agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Badagry? 68664#0 Ki ni o fa iku Tolulope Arotile? 68728#0 nibo ni abule faransé wa ni Badagry? 68737#0 Ki ni awon aami wipe eeyan ti ni ni arun Coronavirus? 68841#0 Ta ni oludari NCDC? 68861#0 Ọjọ meloo lo wa ninu oṣu Februrari? 68882#0 Odun wo ni Kemi Adetiba gbe fiimu King of Boys jade? 69261#0 Ile iroyin wo ni Aisha Falode ba ṣiṣẹ? 69404#0 Ki ni orukọ abisọ alakitiyan Malik El Shabazz? 69661#0 Ki ni orukọ abisọ Burna Boy? 69674#0 Ki ni a n pe ni pythagoras theorem ni Matimatiki? 69736#0 ati ilu wo ni COVID 19 ti kọkọ bẹrẹ? 69944#0 Ile-ise wo ni Bode Akindele da silẹ? 70088#0 olorin wo lo ko "African Queen" ? 70147#0 Fiimu wo ni Rahama Sadau ṣe pẹlu Ali Nuhu? 70174#0 ere mélòó ni òṣèré eniola ajao ti ṣe? 70219#0 Iṣẹ wo ni Sandra Ezekwesili ń ṣe? 70228#0 Awo meloo ni akọrin Tunde Nightingale ṣe ki o to fi aiye silẹ? 70236#0 Odun wo ni Mike Bamiloye da Mount Zion sile? 70240#0 Ki ni oluilu orile ede Morocco? 70265#0 Oye wo ni fi Gani Adams jẹ? 70287#0 ere wo ni Bukky Ajayi kọkọ gbe jade? 70355#0 Ara ìlú wo ni Ààfáà Muyideen Bello? 70363#0 Ta ni ọkọ Thelma Okoduwa? 70419#0 Ipinle wo ni Yunifasiti Ahmadu Bello wa? 70433#0 Ise wo ni Margaret Etim n ṣe? 70450#0 Kí ni orúkọ inagijẹ òṣèré tí a mọ sí Taiwo Hassan? 70460#0 Ile-iwe ko giga ẹwo ni Yvonne Orji ti ka'we? 70493#0 Ipo wo ni won fi Kemi Adeosun si labe ijoba Muhammadu Buhari 70503#0 Ilu wo ni won bi Agnes Osazuwa si? 70557#0 Ede wo ni wọn sọ ni orile-ede Burkina? 70571#0 Omo ilu wo ni Mercy Johnson? 70576#0 Ipinle wo ni Ibrahim Shekarau ti jẹ gomina? 70598#0 ọdún wo ni Ogun àdùbí bẹrẹ? 70614#0 Odun wo ni Chioma Ajunwa yege ni idije olympiiki? 70629#0 Fiimu meloo ni Ini Ikpe ti ṣe? 70633#0 ọdún wo ni akọwe Frances Welsing fi aiyé silẹ? 70656#0 Orile ede wo ni Marina Niava to wa? 70693#0 Ọdún wo ni Leopold Senghor di ààrẹ orile-ede Senegal? 70713#0 Ta ni ọkọ Flora Shaw ki o to fi aiye silẹ? 70729#0 Ta ni o se oludari fiimu Mionga ki Obo? 70783#0 ọdún wo ni wọn bí Anọbi Muhammad? 70864#0 ipinle wo ni ilu Igboho wa? 70918#0 Ki ni orukọ inagije Temilade Openiyi? 70933#0 Ẹgbẹ olóṣèlú wo ni Adeniran Ogunsanya bá ṣe? 70964#0 Odun wo ni Akiwunmi Ambode jẹ gomina ipinlẹ Eko? 70974#0 Ta ni o da ile iṣẹ Mainframe silẹ? 70993#0 ipò ìjọba wo ni Femi Adesina wa labẹ ijoba Aare Buhari? 70994#0 Orile ede wo lo yege idije World Cup ti 2006? 71068#0 Awọn nkan wo ni wọn fi n ṣe Baba Ghanoush? 71092#0 Awo wo ni Temi Dee kọkọ gbé jade? 71178#0 Ipinle wo ni Ayodele Fayọse ti ṣe gomina? 71200#0 Ọdún wo ni Ezra Olubi da ilé iṣẹ Paystack silẹ? 71202#0 Iṣẹ wo ni Tiwalola Olanubi n ṣe? 71220#0 yunifasiti wo ni denrele ti kàwé? 71252#0 ki ni anfani ere idaraya? 71280#0 Ta ni ọkọ Naa Ashorkor? 71282#0 Ọdún wo ni ọgbẹni Rauf Aregbesola jẹ gomina ipinlẹ Ọsun? 71307#0 ọdún wo ni Michael Jackson gbe awo Thriller jáde? 71352#0 konsonanti mélòó ló wà nínú èdè Yorùbá? 71424#0 Odun wo ni Oluwaseun Osewa da Nairaland silẹ? 71511#0 oṣu wo ni odun 1999 ni Olusegun Obasanajo di Aarẹ orile ede Naijiria? 71529#0 Odun wo ni Vivica Fox bẹrẹ si ṣe ere itage? 71554#0 Odun wo ni Facebook ra Whatsapp? 71569#0 Odun wo ni arun coronavirus bẹrẹ? 7183#0 orile ede wo ni odo mississipi wa? 7208#0 Ọjọ mélòó ló wà nínú oṣù Dìsẹ́mbà? 7523#0 Kí ni orúkọ abisọ Kwame Ture? 8837#0 ẹgbẹ oloṣelu wo ni Boris Johnson wa pẹlu?