text
stringlengths 23
128
| clean_label
stringclasses 7
values | clean_label_id
int64 0
6
| noisy_label
stringclasses 7
values | noisy_label_id
int64 0
6
|
---|---|---|---|---|
Coronavirus: Nàìjíríà sọ àgádágodo sí ilé ìtajà China l‘Abuja láti dènà ìtànkálẹ̀ Coronavirus | health | 2 | nigeria | 1 |
Oluwo: Oluwo fárígá pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀ lórí àgbékalẹ̀ iléèwé ẹ̀kọ́ṣẹ́ olùkọ́ni | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
AFCON 2019: Àmì ayò tí Nàíjíríà àti South Afrika gbá rèé | sport | 3 | sport | 3 |
Ajimobi: Orúkọ èmi, Akala, Ladoja, Adebayo Faleti àtàwọn míì | politics | 4 | entertainment | 6 |
Deji Adeyanju: Àwọn olólùfẹ́ Ààrẹ Buhari kọlu Deji Adeyanju àtàwọn ajàfẹ́tọ̀ọ́ tó wọ́de l'Abuja | politics | 4 | politics | 4 |
Tí mo bá rí obìnrin tó kò níṣẹ́ lápá, mó máa ń ní kí wọ́n wò mí ṣe àríkọ́gbọ́n | nigeria | 1 | world | 0 |
YCE: Ìpínlẹ kọ̀ọ̀kan ní àṣẹ láti dá ààbò bo àwọ̀n ènìyàn wọn | nigeria | 1 | world | 0 |
Davido: Àpètàn orukọ̀ ọmọ tuntun náà ní David Adedeji Ifeanyi Adeleke | entertainment | 6 | politics | 4 |
Daddy Freeze: 'Kátàkárà ni owó orí gbígbà lórí ọmọbìnrin jẹ́' | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Libya Refugees: Àtìpó 162 míì dé padà láti Libya | africa | 5 | africa | 5 |
Mínísítà 43 ni Ààrẹ Muhammadu Buhari ṣe ìbúra fún to yàn sípò | politics | 4 | politics | 4 |
ASSU Strike: Ìpàdé ASUU àti ìjọba tún forí sánpọ́n | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Yollywood: Odunlade fijó bẹ́ẹ, Lizzy padà sọ́dún 2012, Lateef gbàmì ẹ̀yẹ tuntun | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Sanwo-Olu: Àtàrí Àjànàkú ni àkóso Eko, kì í ṣe ẹrù ọmọdé | politics | 4 | politics | 4 |
Seyi Makinde: Gbogbo iṣẹ́ àgbàṣe tí Ajimọbi ṣe lẹ́yìn ìbò ní màá gbéyẹ̀wò | politics | 4 | politics | 4 |
Ondo police: Ìwádìí ń tẹ̀síwájú lórí ìjínigbé náà | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Nigeria Elections 2019: Dapo Abiodun, ǹkan márùn ún tó yẹ kẹ́ẹ mọ̀ nípa rẹ̀ | politics | 4 | politics | 4 |
Afenifere: Ìgbà wo ni Bola Tinubu di ọmọ ẹgbẹ Afenifere? | politics | 4 | politics | 4 |
Oluwo: Ó dàbí ẹni pé ọ̀tá pọ̀ fún mi, inú wọn kò dùn sí bí mo ṣe ń ṣakọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Gani Adams: Kò bá dáa tí INEC bá sùn ọjọ́ gbígba PVC síwájú | politics | 4 | politics | 4 |
Mọ̀ síi nípa Yakubu tó wọ bàtà tí Jẹ́gà bọ́ sílẹ̀ ni INEC | politics | 4 | politics | 4 |
Adewale Ayuba: Ogun ń ja àgbo Fújì, ni wọ́n ṣe ń jà | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
BOWEN: Àwọn adarí ti fásitì Bowen pa lẹ́yìn wàhálà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ | nigeria | 1 | world | 0 |
Lagos crime: Àáfà ní òun bu ọlọ́pàá jẹ nígbà tó fẹ́ yí òun lọ́rùn ní Mushin | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
NLC: Gbogbo òṣiṣẹ ló n fẹ́ ilọsiwaju Naijiria | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
ICPC vs Kashamu: Irọ́ ni ICPC ń pa mọ́ Kashamu lórí ọ̀rọ̀ ọkọ̀ áńbúlàǹsì àti ẹ̀rọ amúnáwá | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Tinubu 2023': 'Èmi kọ́ lò rán ẹgbẹ́ 'Asiwaju Reloaded Ambassadors' níṣẹ́ o' | politics | 4 | politics | 4 |
Lassa fever: Ìjọba Eko ní akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Ebonyi tó wá kẹ́kọ́ ìmọ̀ òfin, ní wọ́n bá Lassa lára rẹ̀ | health | 2 | health | 2 |
Lagos Building Collapse: Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko gbé ìgbìmọ̀ olùwádìí kalẹ̀ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Man Utd Vs Man City: Kò ṣèlẹ́rí! àwọn alatilẹyin Liverpool yóò gbè lẹyìn Man Utd | sport | 3 | sport | 3 |
Akure Anglican Bursar: Àwọn agbébọn gbé owó sálọ lẹ́yìn tí wọ́n pa akápò ìjọ Anglican | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
NNPC: Ìwádìí ti bẹ̀rẹ̀ lórí ohun tó fa ìjàmbá iná ọ̀pá epo tó wáyé l'Abule Egba | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Herbal Medicine: Gbígboyè fásítì nínú iṣẹ́ ìṣègùn ìbílẹ̀ dára, àrídájú gbọdọ̀ wà lórí rẹ̀ | health | 2 | health | 2 |
Ìdílé kan gbé ilé iṣẹ́ ọkọ̀ òfurufú lọ ilé ẹjọ́ lẹ́yìn tí wọ́n léwọ̀n dànù nínú ọkọ̀ pé ara wọ́n ń rùn | world | 0 | nigeria | 1 |
Kogi Election: Dino Melaye náà pariwo pé àwọn apanìyàn ti gbòde ní ìbò ku ọ̀la | politics | 4 | politics | 4 |
Osun Politics: Aregbesola ní irọ́ n'ìròyìn tó ń sọ pé aáwọ̀ wà láàrín òun àti gómìnà Oyetola | politics | 4 | politics | 4 |
Atiku: Màá foríji àwọn tó bá dá owó ìlú tí wọ́n kó jẹ padà | politics | 4 | politics | 4 |
Yewande Oyediran: Kò sí ohun tó burú nínú bí Ajimobi ṣe dá Yewande tó pa ọkọ rẹ̀ sílẹ̀ | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
Ẹ̀ wo àwòrán ìgbé ayé Robert Mugabe! | africa | 5 | africa | 5 |
Illegal Orphanage: Ìjọba ti ayédèrú ilé ọmọ aláìlóbìí pa, ọmọdé mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gbòmìnira | nigeria | 1 | sport | 3 |
NLC Strike: Mínísítà fọ́rọ̀ òṣíṣẹ́ pe ìpàdé àwọn olórí òṣìṣẹ́ lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ìgbìmọ̀ iṣedajọ orílè-èdè Nàìjíríà NJC nikan lo le yọ adajọ-Amofin | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
DR Congo: Àwùjọ àgbáyé ń polongo àláàfíà nítorí èsì ìdìbò ààrẹ | africa | 5 | africa | 5 |
Chioma Ikeaza-Uzodinma tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ búra wọlé fún ọkọ rẹ̀ ní Imo | politics | 4 | entertainment | 6 |
Sex for Grades: Fásitì Eko ní kí olùkọ́ míì lọ fìdímọ́lé lori Fídíò BBC | nigeria | 1 | politics | 4 |
Lagos State: Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ní irọ́ ni àjọ EIU ń pa pé ìlú Eko ló léwu jùlọ láti gbé lágbàáyé | nigeria | 1 | world | 0 |
Ààrẹ Donald Trump: Qasem Soleimani ń gbìmọ̀ràn láti kọ lù wá l'Amerika la ṣe kọ́kọ́ yára pa á - Trump Ààrẹ | world | 0 | world | 0 |
Kogi àti Bayelsa: Gomina Yahaya Bello ti Kogi àti David Lyon ti Bayelsa gba ìwé ẹ̀rí INEC | politics | 4 | politics | 4 |
Toyin Abraham: Àwọn ohun tó yẹ ko mọ̀ nípa Toyin Abraham | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Omolola Ajayi: Gloria Bright ní ọ̀gá òun kọ̀ láti sanwó oṣù fún òun lẹ́yìn oṣù mẹ́ta | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Female Driver: Sokunbi ni obìnrin àwakọ̀ Dáńfó l‘Eko, tó ń lọ̀ láti ìpínlẹ̀ kan sí òmíì | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Amotekun: Ìjọba Eko kéde pé òun ní ẹ̀ṣọ́ aláàbò tẹ́lẹ̀, òun kò sí ní yí orúkọ rẹ̀ padá sí Amotekun | nigeria | 1 | politics | 4 |
Irú kí leyi,iná jó òkú méjìlá mọ inú ílé ìgbókúpamọ́sí OAU | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Ibadan High Chiefs: Àwọn Olóyè Ibadan mọ́kànlélógún tó ń pe ara wọn lọ́ba ń fi ẹ̀wọ̀n run imú | entertainment | 6 | world | 0 |
Prophecy 2020: Primate Ayodele, Baba Adeboye àti Father Mbaka sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa 2020! | nigeria | 1 | entertainment | 6 |
University of Transportation Daura: Nǹkan mẹ́wàá tó yẹ ní mímọ̀ nípa fásitì ẹ̀kọ́ ìrìnnà | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Amẹrika dá akẹ́kọ́ọ̀ Harvard pada sí orílẹ̀-èdè rẹ̀ nítori ǹkan ọ̀rẹ́ rẹ̀ kọ lóri ayálujára | world | 0 | world | 0 |
Ooni: Mo rọ àwọn àgbẹ̀ àti darandaran láti gba ìrẹ́pọ̀ láàyè | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Kaduna Kidnapping - Ọmọ iléèwé mẹfà pẹlú Olùkọ méjì ni wọn jígbé ni Kaduna. | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Akitoshi Okamoto: Òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì, wọ gbaga ọlọ́pàá torí pé o pé ní 24,000 | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Yollywood: Àwọn èèyàn fèsì pé Kemi ń díbọ́n ni, tórí ọ̀rọ̀ ọkùnrin ni | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
PDP: A ò fẹ́ ẹ̀jẹ̀ Buhari gẹ́gẹ́ bí alábojútó ìbò kíkà | politics | 4 | politics | 4 |
#Zamfarakillings: Ìjọba pàṣẹ kí wọn dáwọ́ ìwakùsà ní Zamfara | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
R Kelly: Èmi kò jẹ̀bi ẹ̀ṣùn fífi ipá bá ọmọdé lòpọ̀ | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
America: Ẹ má dúró ju ìṣẹ́jú mẹ́wàá lọ níta ìlú yóò tutù kọjá àlà | world | 0 | nigeria | 1 |
Lizzy Anjorin: Ẹ má bú mi, ọ̀pọ̀ òṣèré tíátà ni kìí bá mi yọ̀ fún ire mi | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Ìtàn Mánigbàgbé: £100, tíí ṣe ₦42,150 àsìkò yìí, nìjọba fun Taiwo Akinkunmi lówó iṣẹ́ lọ́dún 1959 | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Kí gan an ni ẹgbẹ́ NURTW ní ṣe pẹ̀lú òṣèlú Nàìjíríà? | politics | 4 | politics | 4 |
El-Zakzaky pé ìpàdé pẹ̀lú àwọn àgbẹ́joro India àti àwọn àjọ ti kìí ṣe ti ìjọba | nigeria | 1 | world | 0 |
Marriage Certificate: Bí o ṣe lè mọ ìgbéyàwó tí kò bá òfin mu | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
Aláàfin ìlú Oyo ti bímọ okùnrin tuntun lẹ́ni odún 81 | entertainment | 6 | nigeria | 1 |
N11trn subsidy: Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé owó ìrànwọ́ epo lè kọ Second Niger Bridge méjìléláàdọ́ta? | nigeria | 1 | world | 0 |
Burger: Kunle Afod, Sindodo, Lola Alao se ìdárò ẹni to lọ | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Àjọ Fifa fòfin de Samson Siasia títí láíláí | sport | 3 | sport | 3 |
Lórí ọ̀rọ̀ Pásítọ̀ COZA àti Dakolo, Ìwadìí ń tẹ̀ síwájú, ṣùgbọ́n a kò mọ ohunkohun nípa rẹ̀ mọ́- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èkó | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Sasa Market: Seriki Hausa ní ogún èèyàn ló farapa nínú ìjà Ṣasa | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Àwọn agbófinró ń wá ọlọ́pàá tó yìnbọn lu olólùfẹ̀ẹ́ méjì, lẹ́yìn tí wọ́n gbé akẹgbẹ́ẹ̀ rẹ̀ | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Lagos Fire Service: Ẹ máse tan àbẹ́là lórí ike tàbí pákó | nigeria | 1 | world | 0 |
Birth tourism: Ẹ̀yin obìnrin tẹ́ẹ fẹ́ wá bímọ ní America, ọ̀nà ti tì pa látònì! - Trump | world | 0 | world | 0 |
INEC: Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú yóò dìbò àbẹ́lé lóṣù Kẹjọ | politics | 4 | politics | 4 |
Kunle Afod: Ohun mẹ́wàá tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa Kunle Afod ti Yollywood | entertainment | 6 | entertainment | 6 |
Olùkọ kan àti àwọn mẹ́ẹ̀dógún míràn ni wọn ti yẹgi fún ní Bangladesh | world | 0 | world | 0 |
9th Assembly: Èrò ṣe ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lórí ẹní tí àṣẹ ilé aṣòfin àgbà Nàìjíríà yóò já mọ́ lọ́wọ́ | politics | 4 | sport | 3 |
Adio Atawẹwẹ: Orin Fuji ló gba iwé kíkà lọ́wọ́ mi | entertainment | 6 | politics | 4 |
Sebótimọ Ẹlẹ́wà Sàpọ́n - Ó ń rọ̀ wá láti má se kọjá agbára wa | entertainment | 6 | world | 0 |
Carabao cup: Iheanacho gba góòlù wọlé láti ra Leicester city padà lọ́wọ́ ìfìdírẹmi | sport | 3 | sport | 3 |
Supreme court judgement: Ta ni Gómìnà Bala Mohammed? | nigeria | 1 | politics | 4 |
Ilé Aṣòfin Eko: A fẹ́ mọ̀ bí Ambode ṣé nà ₦45b tó fi ra BRT | nigeria | 1 | politics | 4 |
Kogi àti Bayelsa: Èsì ìbò tó jáde láti ìpínlẹ̀ Kogi | politics | 4 | nigeria | 1 |
ECOWAS: Buhari nàka àbùkù s'orílẹ̀èdè Libya látàrí aàbò tó mẹ́hẹ l'Afrika | africa | 5 | africa | 5 |
#BBCNigeria2019: Ààrẹ Buhari ní ìdìbò ọjọ́ Àbámẹ́ta yóò lọ n'ìrọwọ́ rọsẹ̀ | politics | 4 | politics | 4 |
Gas Explosion: Ènìyàn márùn ún ti jáláìsí látàri ìjàmbá afẹfẹ gáàsì Kaduna | nigeria | 1 | world | 0 |
Léyìn òpọ̀lọ̀pò ọdún àgbàọ̀jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù ọmọ Cameroun ní òun ti dé wáàsimi | africa | 5 | entertainment | 6 |
Amole festival in Akure: Deji pàṣẹ kí gbogbo ọjà àti ṣọ́ọ̀bù wà ní títì pa | entertainment | 6 | world | 0 |
Atiku vs Buhari: Adájọ́ yóò ṣẹ̀dájọ́ lóní lórí ìbò ààrẹ Naijiria | politics | 4 | politics | 4 |
Nigeria swearing-in 2019: Wo àwòrán tó jẹ ojú ní gbèsè nípa ìbúra ààrẹ àtàwọn gómìnà | politics | 4 | politics | 4 |
Aregbesola: Ó se bẹbẹ ní ọdún mẹ́jọ tó fi sèjọba l‘Ọ́sun | politics | 4 | entertainment | 6 |
Wo àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá tuntun mẹ́tàlá tí àjọ ọ̀hún fọ́nka síta | nigeria | 1 | nigeria | 1 |
Organisation of Islamic Cooperation: Àǹfààní wo ló wà nínú ẹgbẹ́ OIC? | world | 0 | nigeria | 1 |
Shiite: Ilé ẹjọ́ gíga Kaduna sún ìgbẹ́jọ́ adarí Shiite síwájú | nigeria | 1 | nigeria | 1 |