_id
stringlengths
17
21
url
stringlengths
32
377
title
stringlengths
2
120
text
stringlengths
100
2.76k
20231101.yo_2130_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: (Enuwa Square) Eni tí ó te agboolé náà dó ni orúko rè ń jé Jétawo, Ìdí nìyí tí wón fi so ilé náà ní jétawo.
20231101.yo_2130_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Nígbàtí kò sí ààyè mó láti kólè sí mó ní ilé-Jétewo (Enuwa) Àwon omo Àkàntìokè wá lo sí Adugbo Ìtà-Òsun. Ìdí nìyí tí wón fi máa ń so wípé Enuwa kò gbàà yè, lówá yalémo ó lo Ìta-òsun.
20231101.yo_2130_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Àdúgbò yí jé ibi tí omí-odò kan tí won ń pè ní Atan wa, ìdí nìyí tí won fi ń pe Àdúgbò náà ní Òkè-Àtan.
20231101.yo_2130_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: (Enuwa Square) Oba Olófin pe sèru láti Ìta-ye mò ó wá sí agbègbè Enuwá láti wá tèdó. Ìdí nìyí tí wón fi so Àdúgbò náà ní Ilé-Sèru.
20231101.yo_2130_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Orúko eni tí ó te àdúgbò yí dó ni Ogua Ògìdigbo, O yè ti o jé ni Obaloran, isé ré nip é ó ní àse láti gbésè lé èsè késè ti àwon ènìyàn tàbí ará ìlú bá dá. èyí túmò sí Oba-ló ni òràn. Ìdí tí won fi so àdúgbò yí ni Agboolé Obàloràn.
20231101.yo_2130_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: (Ilódè-Oríyangí Square). Ní ayé àtijó, eni tí ó bá kó isé-Ifá, tí ó tó àkókò láti ní Odù-Ifá, ilé tàbí àdúgbò yí ni wón máa ń lo láti gba Odù-ifá náà.
20231101.yo_2130_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: (Láàkáyè) Láakáyè ni oruko eni tí ó te àdúgbò yí dó. Àdúgbò yí tún jé ibi tí won ti máa ń bo Oya. Ìdí nìyí tí won fi so àdúgbò náà ni Ògbón-Oya.
20231101.yo_2130_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: (Oríyangí) Eni tí ó te agboolé yí dó jé Aláwo. Ìdí nìyí tí won fi so ilé tàbí àdúgbò yí ní Ilé-Obàsa o.
20231101.yo_2130_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: (Èdènà) Orúko eni tí ó te àdúgbò láà dó ni Òpá, Ìdí nìyí tí won fi so agboolé náà ní ilé-Òpá.
20231101.yo_2130_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Orúko eni tí ó te agboolé náà dó ni won Ìdú-Oládère. Ìdí nìyí tí won fi so àdúgbò náà ní Ilé-Ìdú.
20231101.yo_2130_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Àdúgbò ibi yí jé ibi tí Ojúbo Obàtálá wà. Òpá tí won máa ń ta tabi ní gbàtí wón bá ń se odún Obàtálá. Ìdí nìyí tí won fi ń pe àdúgbò náà ní Igbó-Ìtàpá.
20231101.yo_2130_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ilé yìí jé agbo ilé tí won ti máa ń je oyè ní ayé àtijó, sùgbón nígbà tí ó yá won kò rí omo okùnrin tí yóò je oyè mó, nígbà tí ó pé òkan lára àwon ìyàwó agbo ilé náà bí omo Okùnrin kan, èyí tí won fi je oyè náà, tí won sì ń pe orúko rè ní Oláyodé orúko olóyè yìí ni wón fi so agbo ilé náà tí won fi ń pèé ní Oláyodé.
20231101.yo_2130_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ilé Olókó jé ilé tí a mò sí ilé àgbède tí ó jé pé isé okó ní isé tí won. Kò wá sí orúko tí àwon ènìyàn lè fi pè wón, wón bá so ilé won ní ilé Olókó.
20231101.yo_2130_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Agbo ilé yìí jé agbo ilé Eléégún, eni tí ó jé olórí àwon eléégún yìí ni a ń pè ní Ààre-òjè. Orúko rè ni àwon ènìyàn fi so agbo ilé yìí.
20231101.yo_2130_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ilé Jagun ni ilé tí àwon ènìyàn mò gégé bíi ilé Olóógun, nígbà tí ayé sì wà láìsí omo ogun rárá. Eni tí ó je olórí Ogun nígbà náà ni Jagun. Wón wá so agbo ilé rè di ilé Jagun nínú ìlu.
20231101.yo_2130_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Bàbá kan ní agbo ilé yìí tí orúko rè ń jé òjó tí ó féràn láti máa jó ijó bàtá ni à ń pè ní Òjóbàtá tí a fi so agbo ilé yìí ní Òjóbàtá.
20231101.yo_2130_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Asé ni wón máa ń hun nínú ilé yìí bíi isé e won ìdí nìyí tí a fi so agbo ilé náà ní ilé Baba Alásé
20231101.yo_2130_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Agbo ilé yìí ni wón ti máa ń je Oyè Baálè-Àgbè ìdí nìyí tí won fi ń pe agbo ilé náà ní ilé Bálè-Àgbè
20231101.yo_2130_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ní ìgbà àtijó Okùnrin kán wà tí ó jé elégun tí àwon ènìyàn máa ń pè ní Baba-Elégun, nínú ilé náà ìdí nìyí tí àwon ènìyàn fi ń pe agbo ilé náà ni ilé Baba-Elégún.
20231101.yo_2130_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Eyelé ni wón ń sìn gégé bí ohun òsìn nínú ilé yìí, ìdí nìyí tí a fi ń pe ilé náà ní agbo ilé Eléyelé.
20231101.yo_2130_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìlé yìí jé ilé tí won ti máa ń lu sèkèrè, ìdí nìyí tí wón fi ń pe agbo ilé náà ní ilé Alusèkèrè.
20231101.yo_2130_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Okùnrin kan ní agbo ilé yìí ni à ń pè ní Ààre ìlù tí ó jé olórí àwon onílù, Orúko rè ni a fi so agbo ilé yìí.
20231101.yo_2130_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Agbo ilé yìí ní ayé àtijó ni àkóbí oba tí à ń pè ní Dáódù kó ilé sí, ìdí nìyí tí wón fi ń pe agbo ilé náà ní ilé Dáódù.
20231101.yo_2130_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Agbo ilé yìí ni ilé tí agbápò sango ń gbé, agbápò sàngó yìí ni à ń pè ní ìkólàbà, ìdí nìyí tí a fi n pe agbo ilé náà ní ilé Ìkólàbà.
20231101.yo_2130_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ní ayé àtijó eni tí ó jé baálé ilé náà onífá ni, sùgbón nígbà tí ó kú tán, gbogbo àwon omo ìlé náà àti ègbón àti àbúrò ni won ń se èsìn ifá yìí, ìdí nìyí tí wón fi so agbo ilé náà ní agbo ilé Arífájogún.
20231101.yo_2130_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Agbo ilé yìí ni àwon tí won máa ń ko ilà fún àwon ènìyàn wa. ìdí nìyí tí a fi ń pe ilé náà ní ilé Olóólà
20231101.yo_2130_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ní ayé àtijó ní agbo ilé yìí àwon egbé kan fi baba àgbàlagbà kan je baba ìsàlè inú egbé e won, ilé tí baba yìí ń gbé ní àwon ènìyàn so di agbo ilé Baba-ìsàlè.
20231101.yo_2130_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Agbo ilé yìí ni eni tí ó jé Olórí àwon alápatà tí à ń pè ni Séríkí ìnú ìlú náà wà, agbo ilé tí ó ń gbé ni à ń pè ní agbo ilé Séríkí.
20231101.yo_2130_34
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Orúko agbo ìlé yìí ń tóka sí ilé tí wón ti ń dá oko ju, tí won sì ní oko jù ní inú ìlú, ìdí nìyí tí a fi ń pe agbo ilé náà ní ilé Alókońgbó.
20231101.yo_2130_35
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Láti ayébáyé ni onílé yìí ti ń sin adìe, kí ó tó kú, núgbà tí ó sì túnkú àwon omo rè náà tun ń sin adìe náà. ìdí nìyí tí àwon ènìyàn fi so agbo ilé náà ní ilé Aládìe
20231101.yo_2130_36
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Láti ayábáyé ní agbo ilé yìí ni a ti rí àwon àgbè tí ó jé pé isu kìí wón ní orí àjà won, títí tí àgbodò fi máa ń dé, ìdí nìyí tí won fi so agbo ilé náaà ní agbo ilé Anísulájà.
20231101.yo_2130_37
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ilé yìí ni ilé tí wón ti máa ń sin ajá lópòlopò fún títà, tí àwon ènìyàn sì ń pe agbo ilé náà ní ilé Alájá.
20231101.yo_2130_38
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ilé yìí ni ilé tí eni tí ó máa ń lu aro wà tí ó ń gbé, tí àwon ènìyàn sì ń pe agbo ilé rè ní ilé Alaro
20231101.yo_2130_39
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìlé yìí jé ilé tí baba kan àti ìyàwó re wá tèdó sí láti ìlú Tedé tí wón sì bímo sí ibè tí won sì di púpò ní agbo ilé náà. ìdí nìyí tí a fi ń pe agbo ilé náà ní ilé baba-Tedé.
20231101.yo_2130_40
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Bàbá ològùn ni ó te ibè dó, Orúko yi wá jásí aláki ajámopó, Bàbá olóógùn yi ma ń já omo nínú apó ni wón so di ajámopó.
20231101.yo_2130_41
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Òsun kan wà tí orúko re ń jé òjìyàn ibè ni okúka kán wá tóní ojú ihò méje gégé bi poón ayò tí enikéni kò mò enití ó gbe ìdí èyí ni wón fi sodi ìta òsun.
20231101.yo_2130_42
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Okùnrin kan lo ma ń gba ibè lo sí inú oko rè nígbà tí ń kan rè dàgbà tan olè ma ń wo inú oko rè lo, ìgbà yen ni bale la ojú ònà ibè ìdí èyí ni wón fi ń pe nì òkèsòdà.
20231101.yo_2130_43
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ibití oòni Ilé Ifè bòǹsè rè sí nígbà tí wón bá ń se odún òrìsà kan tí a ń pè ní jùgbè ìta ni wón sì ti ma ń se odún náà ni wón so di ìtasìn
20231101.yo_2130_44
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìdí tí wón fi ń pen í òkèrèwè nip é ògbón ni ojó, nígbà tí enití ó te ibè dó fi so pé òun á kó ilé òun sí orí òkè níbí ibè ni wón so di òkèrèwè.
20231101.yo_2130_45
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ògbón nì o náà ń jé ifájuyì ni wón ń pe ttélè nígbà tí enìkan kú tí wón sì dá Ifá níbè pé kí wón ma gbé òkúrè àfi tí wón bá sin sì ibè, bíwón se bèrè sip è ní fájuyì nìyàn.
20231101.yo_2130_46
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Omo aládé ni wón ń jé télè, nígbà tí wón dá Ifá tí ifá mú enití adé tósí ni wón sí bèrè sí pe ibè ni lúgbadé
20231101.yo_2130_47
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ògbón ni ibè ń jé ògbón Oya yen wón ti ibì kan ya wá ni wón wá te ibè dó ni wón fi kó ilé síbè bíwón se bèrè sí pè wón ni ògbón-oya.
20231101.yo_2130_48
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Àwon ará ilé òpá ni wón, níbè ni wón tí so pé àwon ń lo si oko àwon ni olórò ni wón fi ń pé gbogbo ibè ni ìlórò.
20231101.yo_2130_49
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Àwon ìdílé Obaláyè ni wón ní ibè sùgbón òkè kúta ni wón n pe ibè òkè kúta pò níbè ni wón fí so ibè di wánísánì òkè kúta
20231101.yo_2130_50
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Obu ìjéta ni ó je oba níbè ibi tí agbo ilé náà wa ni wón ń pe nì ìta-òtutù bí wón se so ibe di otutu niyen.
20231101.yo_2130_51
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìdí tí wón fi ń pe ibè ni látalè ni pé ilè ni wón ń tà níbè ni ayé àtijó, bí wón se so ibè di látalè (compound)
20231101.yo_2130_52
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìdí tí wón fi ń pé ni yèèkéré ni pé nígbà tí enití ó te ibè dó bèrè si pin ilé fún won ní won bèrè sí so pé yèèkéré ìdí èyí ni won fi ń pen i ìyékéré.
20231101.yo_2130_53
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ní ayé àtijó ènítí ó te igbó òyà dó ni okùnrin. Òyà ni ó sì ma ń pa nítorí pé kò sí isé nígbà náà ju isé ode lo bíwón se bèrè síí pe ibè ni ìgboyà.
20231101.yo_2130_54
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: wón ń pe ibè ní aroko nítorí pé oko ni wón ma ń jù ní gbogbo ojó ayé wón ìdí nìyen ti wón fi ń pen i aroko.
20231101.yo_2130_55
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìdí tí ó fi á jé orúko náà ní pé wón ma ń jòró opó ni àdúgbò náà ìdí nìyen ti ó fi ń je ìtáolopo
20231101.yo_2130_56
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìdí pàtàkì ti o fi á jé òrunobadó nip é ni ayé àtijó tí oba bá fé wàjà tí ó bá ti wo odò tàbí kànga náà á lo sí òrun bí wón se bèrè sip é ni òrunobado nìye
20231101.yo_2130_57
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ní ayé àtijó bàbá kan wá tí ó má ń gun esin yówá sí àdúgbò náà láti ìgbà yen ní wón ti bèrè sip e ibè ní agesinyówá.
20231101.yo_2130_58
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: àdúgbò ògbón àgbàrá yìí àgbàrá ma ń sàn níbè gan ti wón sì ma ń fi igbá gbón omi náà kúrò lónà, bí wón se so ibè di ògbón àgbàrá.
20231101.yo_2130_59
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9-If%E1%BA%B9%CC%80
Àwọn àdúgbò ìlú Ilé-Ifẹ̀
Ìtumò: Ìgbódò jé ìdílé tí wón ti ma ń gbé odó ìgbà tí enití ó ń gbé odó náà kú ni wón bèrè sí so ibè di igbódò.
20231101.yo_2131_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ìbí yìí ni àwon omo ogun Ìjèsà gbà lé àwon òtá won ni ìgbà ogun ni èyí, èka ède ló fà á tí ó fi jé Ìkótì.
20231101.yo_2131_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Orúko owá ketàlá tó jè ni Ilésà ni Bíládù Arère, ìrántí rè ni won fi so àdúgbò yìí ni orúko rè. Nìgbà tí ò ti dé orí oyè, ó wá gbajúmò débi pé fí àwon èèyàn ba n lo si àdúgbò yen, dígbò ki won so pe àwon n lo si ògbón wón á ni àwon n lo sí ilé Bíládù bí wón se so ó àdúgbò yìí di Bíládù nìyí
20231101.yo_2131_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: ibi tí àwon jagunjagun Ìjèsà pelu àwon omo Ogun Èkìtì ti pàdé ní ìgbà Ogun ni àdúgbò yìí torí pé ota ìbón pò ni ilè ibi yìí léyìn Ogun yìí ni won se so o ní ota pèté.
20231101.yo_2131_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Omi kan wà ni àdúgbò yìí tí won ń pè ni asorò tori omi yìí ni won se so àdúgbò yìí ni omi-asorò.
20231101.yo_2131_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àwon ènìyàn gbà pé igbó tí ó wà ni àdúgbò yìí ni ìgbà àtijó ni àwon abàmì lópòlópò eni tó sì mú ki won gbà pé òràn ni yóò ri, Orìn-ken-òràn (èdè Ìjèsà) O rìn kan òràn.
20231101.yo_2131_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibi yìí kojá ibi tí ìrókò kan wà díè, èyí ló fà á ti won fi so pe o-mu-iroko (èdè Ìjèsà) ìtumò-mu-iroko nip é ó kojá ìrókò mùrókò.
20231101.yo_2131_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àwon tí won ón dá ara won sà sí ònà kan ni ìtumò ìdásà, àwon kan kúrò ni àárín ìgboro, wón sì lo da àdúgbò yìí sílè ni won ba so o ni Ìdásà.
20231101.yo_2131_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: (Páàdì) Ibi yìí ni àwon Òyìnbó ìjo Rátólíkì tí a gbà pé won mu ìgbàgbó wá ń gbé nígbà yen ni òkè-Páàdì.
20231101.yo_2131_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Eni tí ó kókó dá àdúgbò yìí sílè bínú kúrò láàrin àwon ènìyàn lo dá dúró síbè ni, èyí ni awon ènìyàn fì so ibè ní arágan torí pé, wón gbà pé ìwà eni tí ó kókó dé àdúgbò yìí kò jot i ènìyàn tó kù lò fàá to fi wá dá àdúgbò tirè sílè.
20231101.yo_2131_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Òtè ló gbé àwon tó kókó de adugbo yìí dé ibè torí pé wón ń gbèrò láti yan olóyè láàrin ara won, Owá gbó èyí ló bá lé won kúrò ni ibi tí won ti wá télè.
20231101.yo_2131_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àwon tí ó kókó dé adúgbò yìí jè ólòwó pàápàá àwon tí ó kókó jáde to se awo ni èyìn odi tí won fi wá n kólé sí ilé.
20231101.yo_2131_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: àdúgbò yìí ni won ti máa n ta aso àwon oyinbo nigba tí àwon kòráà kókó gbé aso títà dé Ilesa, ìdí niyi ti won fi n pè é ni Òkè-eso.
20231101.yo_2131_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibi tí àwon tó ma n se isé onà pò jù sí láyé àtijó, ìtàn so fún wa pé ibè ni won ti máa n hun òpá àse àti ìlèkè owá, tí àwon ìyàwó rè àti àwon olóyè.
20231101.yo_2131_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àwon désìn kinyó ló so àdúgbò yìí ni òkè ayò nígb`atí won kó ilé ìjósìn ati ibi ìsojí àti lé isun won síbè.
20231101.yo_2131_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ìtàn so pé àdúgbò yìí àwon omo ogun ti níláti gbéra lati sigun lo sibi ti won ti fé jagun. Béè náà ni won sì gbódò wá jábò ti won si pin enìati erú tí wón kó bò lójú ogun.
20231101.yo_2131_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: ìbi tí ará ìgboro ti má a ń wá pàdé àwon ará oko láti ra ojà lówó won èyí ló fà á tí wón fi so àdúgbò yìí ní Ìlájé.
20231101.yo_2131_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àdúgbò yìí jè ìbi titun tí òpòlopò àwon tí ó fi jáde nílùú tipé tipé ń gbé òpòlopò won lo ti Èkó wá kólé síle, ojú tì wòn fi wo ìkòyí Estate l’Ekoo ni won fi mu àdúgbò náà.
20231101.yo_2131_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibi tí àwon Ìbòkun dúró dí nígbà tí ogún parí ti won wá láti dúpé lówó Owá ti o ràn wón lówó láti segun òtá wòn (A-de-eti-owá) À dé tòsí ilé Owá Adètí Owá.
20231101.yo_2131_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àwon ará Òwò ló so adúgbò yìí lórúko yìí, àgbàdo ni won máa n tà níbè télè bóyá àgbàdo tí won máa n dàpè ní okà ló fa orúko yìí.
20231101.yo_2131_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ìkòkò ni àwonìjèsà máa ń dà á pè ní ìsà. Àdúgbò yìí sì ni wón ti máa ń ná oyà ìkòkò saájú kí ilésà tó di ilé-ìsà.
20231101.yo_2131_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ìsò okùn ló di ìsokùn yìí, ibè ni àwon àgbè àti elému ti máa ń wá okùn láti fid i erù tàbí òpe-emu won ní ìgbà láéláé.
20231101.yo_2131_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Igi osè ńlá kan ló wà ní ìbí yìí ni ìgbà láéláé tí àwon ènìyàn máa ń dúró ta ojà mí abé rè.
20231101.yo_2131_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ìbí yìí ni wón ti máa ń bo ògún owá ní ìgbà àtijó, wón sì máa ń pa ajá ògún sí ibé yìí títí di oní.
20231101.yo_2131_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibí yìí ni àwon ológun máa ń dúró sí de àwon òtá ní ìgbà láéláé, ìdí nìyí tí wón fi ń pè é ní ìta akogun.
20231101.yo_2131_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àgékúrín fún “A dé etí owá” mí èyí, ibè ni àwon ará ìbòkun dúró sé nígbà tí ogun parí tí wón fé wá dúpé lówó owá-omo-Ajíbógun tó ràn wón lówó láti ségun àwon Ìlàré.
20231101.yo_2131_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Òrúko akoni kan tó wá láti ìbòkun sùgbón tó wolè láàrin ìlésà àti ìbòkun nígbà tí ó gbó pé ogun ti pa ìyàwó àti omo òun mi ìbòkun.
20231101.yo_2131_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibi tí àwon tó má a ń se isé onà pò jù sí láyé àtijó ìtàn so fún wa pé ibè ni wón ti máa ń hun òpá ńlèkè owá, tí àwon Olóyè rè àti ti àwon ìyàwó rè.
20231101.yo_2131_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ìgi Isis ńlá kan ló wà ní ibí yìí télè tí àwon ènìyàn máa ń ta ayò ní idi rè èyí ló di ìtà-isin lónìí (Ìhnsin).
20231101.yo_2131_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Orúko tuntun ni orúko àdúgbò yìí nítorí pé àwon tó kókó dé ibè kò tètè kólé kan ara won, wón gbà pé àwon bá olórun dúrò.
20231101.yo_2131_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ní ìgbà ogun, Ibí yìí ni àwon Ológun ìjèsà gbà láti sá àsálà fún èmí won. “Ibi tí a gbà tí a fi yè”ni àpèjá rè.
20231101.yo_2131_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Orí ojà ni wón gé kúrú sí Eréjà, ibí yìí ló jé bíi oríta fún gbogbo àwon ìlú kékèèké ibè sì ni wón ti máa ń pàdé láti ta ojà won.
20231101.yo_2131_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àdúgbò tí omi tí àwon ènìyàn máa ń pon ní ayé àtijó, omo yìí wà ní ìtòsí ibi tí wón máa ń dá oko sí, èyí ni wón fi máa ń pè é ní omi-oko.
20231101.yo_2131_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àwon tí ó kókó dó àdúgbò yìí jé olówó, pàápàá wón jé òkan lára àwon tó kókó jáde lo sòwò ní òkè oya tí wón wá ń kólé sílé.
20231101.yo_2131_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àdúgbò yìí kò jìnà sí omi kan tí àwon ènìyàn máa ń mu, èyí ló jé kí àwon ènìyàn máa pe àwon tó ń gbé àdúgbò yìí ní òlómilágbàlá.
20231101.yo_2131_34
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àgbède kan wà ní àdúgbò yìí ní àkókò tí wón fún un ní orúko yìí, omo Èfòn alààyè ni àgbède yìí.
20231101.yo_2131_35
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Òrúko Babaláwo kan ni Jìgbà, àdúgbò yìí ló sì máa ń gbé tí ó ti ń se isé owo rè. ìdí nìyí tí wón fi ń pe àdúgbò náà ní òkè-jìgbà.
20231101.yo_2131_36
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Òmi kan wà ní ibí yìí tí wón ti máa ń fo irú ní ayé àtijó, ìgbà tí àwon ènìyàn téèrè sin í kólé omi irú.
20231101.yo_2131_37
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Oko kan wà ní ibí yìí ní ìgbà àtijó tí wón ti máa ń sin adie (poultry) omi kan sì wà ní ìtòsí oko yìí, èyí ló mú kí won máa pe omi yìí ní omi aládìe èyí tó di o’ruko àdúgbò náà lónìí.
20231101.yo_2131_38
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Àdúgbò yìí ti wà láti ìgbà láéláé sùgbón àwon ènìyàn kò tètè wá ko ilé sí ibè, nígbà tí ó sì yá ààrin ìgbà díè ni àwon ènìyàn kó òpòlopò ilé sí ibè, èyí ló mú kí won pè é ní Olórunsògo.
20231101.yo_2131_39
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibí yìí ni àwon àgbè tó bá ń bò láti oko ti máa ń já imò òpe láti di erù won ibè ló di Ìjámò nígbà tí ilé bèrè si ní de ibè.
20231101.yo_2131_40
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Orúko akíkanjú kan ni ìgbà ogun ògèdèǹgbé ni èyí, ní ìrántí rè ni wón se so àdúgbò yìí ní ògúdù.
20231101.yo_2131_41
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Òmi kan wà ní àdúgbò yìí télè tí àwon ènìyàn ti máa ń do nǹkan, torí omi yìí ni wón se so àdúgbò yìí ní Ìfofín.
20231101.yo_2131_42
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20Il%C3%A9%E1%B9%A3%C3%A0
Àwọn àdúgbò ìlú Iléṣà
Ìtumò: Ibi tí àwon ìyá àgbà ti máa ń se àdín ní ìgbà àtijó ni wón ń pè ní Umàdín ní èka èdè ìjèsà, èyí ló sì di Imàdín lónìí
20231101.yo_2135_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Ìbàdàn
Ìbàdàn jẹ́ olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìlú Ìbàdàn ni ìlú tí ó tóbí jùlọ ni apá ìwọ̀òrùn Afríkà, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ olú ìlú ìjọba fún ìpínlè Ọ̀yọ́. Ìbàdàn jẹ́ ilú àwon jagunjagun tí wọ́n dá sílẹ̀ẹ̀ lẹ́yìn tí ìjọba Ọ̀yọ́ Kátúnga túká nígbà tí Àwọn Fúlàní ṣe ìkọlù sí ìjọba Ọ̀yọ́ nígbà náà. Orúkọ tí wọ́n ń pe ilú yí (Ìbàdàn) ní ó túmọ̀ sí ẹ̀bá ọ̀dàn.
20231101.yo_2135_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Ìbàdàn
Ìtàn fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wí pé wọ́n da ìlú Ìbàdàn sílẹ̀ ní nǹkan bí ọdún 1829 látàrí àwọn ogun àti rògbòdìyàn tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá nígbà náà. Àsìkò yí ni àwọn ìlú tí wọ́n ṣe pàtàkì Ilẹ̀ Yorùbá nígbà náà bíi: Ọ̀yọ́ ilé, Ìjàyè àti Òwu ń kojú ogun lọ́tún lòsì, nígbà tí àwọn ìlú tuntun míràn náà ń dìde. Lára àwọn ìlú tí wọ́n ń dìde ni: Abẹ́òkúta, Ọ̀yọ́ Àtìbà àti Ìbàdàn. Ibadan dide lati dipo won. Gege bi awon onitan Lágelú tí ó jẹ́ Jagun ìlú Ifẹ̀ ló da Ìbàdàn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àgọ́ fún àwọn jagunjagun tí wọ́n bá ń bọ̀ láti Ọ̀yọ́, Ifẹ̀ àti Ìjẹ̀bú. NÍ ọdún 1852, àwọn Church Missionary Society rán David àti Anna Hinderer láti tán ìhìnrere àti láti kọ́ ilé ìjọsin ní Ìbàdàn tí wọ́n bá dé ní ọdún 1853. Ibadan bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ìpínlẹ̀ jagunjagun tí ó sì wà bẹ́ẹ̀ títí di ọdún kẹ́wàá tí ó gbẹ̀yìn sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún.
20231101.yo_2135_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Ìbàdàn
Ní ọdún 1893, Ìbàdàn di ìlú amọ́nà/ìlú tí ó wà lábẹ́ àṣẹ bírítéènì lẹ́yìn tí Fìjàbí tí ó jẹ́ baálé ìlú Ìbàdàn fí ọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú ẹni tí ó ń ṣe iṣé gomìnà ìlú amọ́nà George C. Denton ní ọjọ́ Kàrúndínlógún oṣù kẹjọ