_id
stringlengths
17
21
url
stringlengths
32
377
title
stringlengths
2
120
text
stringlengths
100
2.76k
20231101.yo_2121_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
ÒDODÒ: Àgbàrá san gba èhìnkùlé àdúgbò yi kojá. Gbogbo Ilé ti o wa ní àdúgbò yi ni won si n pè ni òdodò eyí tí o túmò si ode (ile)-odo Òde-ode tasí Ododo.
20231101.yo_2121_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
ÒLÁLÈ: Oloye ti o koko je ni àdúgbò yi ni o létòó lati máa pín ilè fún àwon ènìyàn. Ilè ni Akungba n pè ni alè. Ìdí nìyí tí won fi n pea won to leto lati tai le tabi latí pín ìlè ni alale ti adugbo won sì n jé Olale. Ni adugbo bi ni won sit i n je oba titi ji oni-Oloni eyi wá wà ni ìbámu pèla òrò Yorùba tó so pé Oba ló nile.
20231101.yo_2121_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
AROKUNPANLE : Oke pupo wa ni adugbo yi to béè gee bi ènìyàn ko ba jeun kánú dáadáa yoo maa fidi wo kó tó wolé míràn ni. Itumo arokunpanle ni afìdímólè.
20231101.yo_2121_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
APOLE: Eni ti o koko te àdúgbò yi do maa n mo ògiri yi àwon ilé ibè po. Awon ilé tí a bá sì mo ògiri yip o ni a n pè ní apolé lati ìgbà náà ni wón ti ń pe àdúgbò yìí ní apolé.
20231101.yo_2121_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
ÀLÙJÙ: Ni àràárò ni baba arúgbò kan máa n fi ìlù ji awon ara adugbo yòókù. Nigba ti won bi baba yi léèrè èrèdí to fi n lu ilu o ni o n mu oun larada ni. Lati igba naa ni won ti n pe àdúgbò yìí ni àlùjù.
20231101.yo_2121_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
OKOGBO: Inú igbó ni bàbá àgbàlagbà ti o te àdúgbò yi do ń gbé kí àwon ènìyàn to de ba a nibe ìdí nìyí ti awon ènìyàn fi n pe àdúgbò náà ni okogbó.
20231101.yo_2121_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
ODÈÈGBÒ: Àwon to kókó te àdúgbò yí dó máa n da agbàdo sise sinu omi to n sàn to wà níbè. Àgbàdo yìí ni won n pè ni ègbo tì won sì ń pe odò yìí ní odo-egbo ti wón sì so àdúgbò yin i odèègbo.
20231101.yo_2121_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%80k%C3%B9ngb%C3%A1-%C3%80k%C3%B3k%C3%B3%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92nd%C3%B3%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Àkùngbá-Àkókó, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà
ÒNÀKÈ: Ile pupa àti òpòlopò òkìtì-ògán wa ni adugbo yìí. Òpòlopo ona ni o sì já si ìlú yìí. Ona ti o wà ni ese òkè yi ni eni ti o te e dó ń gbé ìdí nìyí ti won fi n pe àdúgbò yí ní ònàkè.
20231101.yo_2122_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
1. Ìta oseìn: ibi tí àwon ajagun tí màa ń bo soìnmolè tí wón bá fé lò jagun, ni ìgbákìgbá tí wón bá ti boo shin náà wòn maánsègun.
20231101.yo_2122_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
2. Pansekè: igi kan ni tí ó ní èso, tì éso náà bá ti gbe yóò máa dun sékéséké, ibi tí igi na ise ni aso
20231101.yo_2122_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
11. Sàpón: Ní ayé àtijó ìyá a kan wà tí ó jé wípé èwà ní ó máa ń tà èyì sì se ànfàń púpò fún àwon àpón tí kòì tí láya, ní ìgbà kígbà tí ó wun àwon àpón yìó ní wón máa ń lo ra èwà tí ó sì jé pé wón á rí ìyá eléwà yìí níbè ìdí éléyìí ni a se ń pè ìyá eléwà yìí ní sàpón lóore.
20231101.yo_2122_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
13. Ìdí Àrà: Igi ńlá kan wàn ní àdúgbò yìí ní ayé àti jó tí ó jé wípé ìgbà túgbà tí àwon àgbè bá ń ti oko bò wón máa ń simi sí abé igi náà nítorí pé ibojì àti atégùn wà ní abé igi náà.
20231101.yo_2122_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
15. Ìmòré: Ní ayé àtijo igi kan wà tí ó ń so èso kan tí à ń pè ni òré, igi yìí pò ní àdúgbò yìí tí ó fi jé pé nígbà tí wón tèdó sí bè ni wón soódi imòòré.
20231101.yo_2122_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
17. Ojà Àgbó: Agboolé yìí jé ibi tí àwon tí ó kòkòtèdó síbè tí ń sé isé òsìn eran, wón dó ojà sílè tí won ti ńta àgbò, ní torú ìdí èyí ni wón se so ibè ní òjà àgbò.
20231101.yo_2122_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
19. Ìjejà: Ní ìgbà kan Oba kan náà ní àdúgbò yìí tí o burú tí ó sì jé wí pé àsé tí ó bá pa ní abé gé. Ó so fún àwon ará ìlú rè ní ojó kan wí pé tí won bá náa ojà sùgbón wok o, Oba pàsè kí wón lo je ojà náà run.
20231101.yo_2122_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
20. Láfénwá: Orúko eni tí ó kókó àdúgbò yìí ni oláféniwá ìdí èyí ni wón fi so àdúgbò yìí ni orúko eni tí ó kókó tebè dó.
20231101.yo_2122_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
21. Mókóla: Ní ayé ojo un ní ìgbà tí àwon ajagunlà ti ń jagun, wón jagun wón kérú wón kérù, ibi tí wón dé simi tí wón kó àwon erù won sí ni wón sinmi sí ibè tí wón pè ní omokólá.
20231101.yo_2122_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
22. Asérò: Abúlé yìí ni àwon kan kókó tèdó sí tí ogun fí léewá, nígbà tí wón dé ibè, bí tí n sì bò ní ibi tí wón lo gégé bí àwon èrò se pò tó ní wón ti sì dé ibi tí wón tèdó sí, ibi tí wón sit i sí kúrò ní wón ń pè ní Asérò
20231101.yo_2122_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
23. Ìgbésa: Àdúgbò yìí jé ibi kan tí ó jé pé igbó ni ó pò níbè télè sùgbón ìgbà tí àwon ènìyàn tèdó síbè ní ó di ìlú èyí ni wón se ń pè ní igbésà.
20231101.yo_2122_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
24. Ìkujà: Jé abúlé kan tí akínkanjú kan ti kòyá fún àwon ará abúlé lówó àwon adigun jalè Akinkanjú yìí máa ń jà, ìdí èyí ni wón fi ń pè é ní ìkijà.
20231101.yo_2122_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
25. Kútò: Ikútòmíwá ni àpè sale orúko yìí ní ìgbà kan okùnrin kan wà ní abúlé kan tí ó jé ohun nìkàn ni ó ń gbé ibè, ní ojó tí eranko búburu kan wá bá ní ibi tí ó ń gbé ni eran kò náà paá je kí ó tó kú ni ó ké tí enìkan fi gbó ohùn rè tí ó si sàlà yé fún ìdí èyí ni wón fi so abúlé ní kútò.
20231101.yo_2122_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
27. Ológùn-ún: Ìse Òde ni eni tí ó kókó dé bè n se tí ó sì máa ń bo ògún nígbà tí ó bá ti oko ode dé tí owó si de tí wón sì ń pèé ní ilé eni tí ó ń bo ògún, tí won ń dàpè ni ilé Ológùn-ún báyìí.
20231101.yo_2122_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
28. Ìbèrè kòdó: Okùnrin tí won fi ń be àpèjúwe ibí yìí kò dó sí ilé yìí, eni tí ó jé àbúrò rè ni ó wá padà dó sí ilè yìí. Béèrè ni won máa ń pe ègbón ni tiwon gégé bí ó se wà ní àwon ìlú tàbí agbègbè kòòkàn lode òní, tí okùnrin náà sì máa ń so fún òpòlopò ènìyàn pe ibí yìí ló ye kí béérè òun dó sí, sùgbón tí kò dó síbè, òun yóò wá máa pe ibí yìí ni “ìbi tí béérè kò dó sí” tí won ń dà pè ní Ìbèrèkòdó báyìí.
20231101.yo_2122_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
29. Ìgbórè: Bàbá kan àti ìyàwó rè ni wón ń rìn kiri tí wón fid é ibi tí àdúgbò yìí wa báyìí, wón gbé erèé lówó wón sì gbo ó ni ibè wón sì fi din àkàrà je, Báyìí ni wón ń se àpèjúwe ibe ni “Ibi tí àwon ti gbo erèé” tí o di Ìgbórè báyìí
20231101.yo_2122_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/Or%C3%BAk%E1%BB%8D%20%C3%80d%C3%BAgb%C3%B2%20n%C3%AD%20%C3%88gb%C3%A1%20%C3%A0ti%20%C3%80w%C3%B3r%C3%AC%2C%20%C3%8Cp%C3%ADnl%E1%BA%B9%CC%80%20%C3%92g%C3%B9n%2C%20N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0
Orúkọ Àdúgbò ní Ègbá àti Àwórì, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà
30. Ìbàsà: Ibí yìí jé ibì kan tí wón tí ń bo àwon àsà ilè Yorùbá ní ayé ìgbà náà, wón sì so ibè ní ilé “ibo àsà tí ó di Ibasa lónìí.
20231101.yo_2124_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni àwon ìjòyè Oba ìlú yìí tí a ń pè ni olówá tè dí, ti won si ń se ìjoba lórí àwon ènìyàn tó wà ládùgbó yìí
20231101.yo_2124_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni ojúbo òrìsà òsù wa. ni tori pe ibí yìí ni wón ti ń bo òrìsà yìí ni wón se ń pe e ni ìta òsù.
20231101.yo_2124_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni òkan lára àwon akoni ode to máa ń ye ojó ogun ti awon olóde yòókù bá ti dá síwájú tè dó ìdí niyìí tí won fi ń pe àdúgbò yìí ni Ayegun.
20231101.yo_2124_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Awon ounje orisirisi tí a dì sínú àpò bii àgbàdo, ìyo, ni àwon ara àgbègbè máà ń gbé wá si àdúgbò yìí wá lati tà kí ó tó di àdúgbò. Wón si máà ń na ojà ni àdúgbò yìí títí di òní yìí .
20231101.yo_2124_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni àwon Olósùgbó ti máà ń se ìpàdé. Níbè ni ilé ìpàdé wón wa, kí ó tó di pé won te ibè dó.
20231101.yo_2124_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ibí yìí ni ójúbo osi esi wà télètélè kí o to di pé won te ibè do tí o si dí àdúgbò ojúbo osi yìí si wa níbè títí dònìí.
20231101.yo_2124_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àwon Opó ni won máà ń na ojà yìí ni alaalé. Òríta ti wón ń náà yìí ni o di adúgbò, ti wón si ń pe ni ìtà opó. Wón si máà ń ná ojà alé ni àdúgbò yìí títí dònìí
20231101.yo_2124_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Okunrin kan tó mú opà dání ló te apá ibí yìí dó. Ìtàn so fún wa pé àpá ase Oba ìlú ibòmíìràn ló mu dàni nígbà tí o ń bo, àwon kan tilè so pé Àremo oba ìlú náà ni. Nígbà tí o, fé te àdúgbò náà do ó mú òpá yìí dá ni, Ìdí niyìí tó fi je pé won ń je oba ni àdúgbò náà títí di òní yìí
20231101.yo_2124_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ìtàn so fún wa pé omi nigbogbo àdúgbò yìí teletélè kí ó to dí pe wón te ibè do. Okunrin akoni ti a ń pè ni òró ni o pé ofò tí ó sì le omi náà lo. Ìdí nìyìí ti a fi ń pé àdúgbò náà ni Ìtóòró.
20231101.yo_2124_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ibí yìí ni òkan lára àwon akoni tó te ìlú yii dó kokó dúró si kó tó dip é ó wo àárin ìlú lo. Nígbà ti ijà dé láàrin òun àti àwon tí wón fo wo ìlú yìí, o bínú pàdà si ibi yìí o si wolè. Ìdí niyìí tí wón fi ń pe àdúgbò naa ni Olóde. Oórì okùnrin yìí si wà níbè títí dòníì.
20231101.yo_2124_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Eégún kan ti won ń pè ni obrinrin ojòwú ní o te ibí yìí dó. Èégún Odoodún ni eégún máà ń jáde ni àdúgbò yìí títí donii. Ìdí igi ìrókò ni won fi se ojúbo eégún yìí Igi ìrókò yii wà níbè títí dónì yìí.
20231101.yo_2124_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Isé epo ni àwon to te àdúgbò yìí yàn láàyò léyìn tí wón ti dó síbè. Bí o tilè jé pé won kò se ise epó níbè mó, won si ń ná ojà epo níbè titi dò níí.
20231101.yo_2124_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Lára àwon ìjòyè oba Gbélébùwà àkókó tí won kò fara mo on pé kí wón pa Oba náà ni won wa te àdúgbò yìí dó léyìn ti wón kúrò ni ààfún.
20231101.yo_2124_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Oríta yìí ni àwon ìjoyè Oba Gbétebùwá àkókó péjo sí láti bi ara won ohun ti o ye kí àwon se fún oba náà.
20231101.yo_2124_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ìtàn so gún wa pé nígbà tí wín fe te ibí yìí dó, wón bá òrìsà kan níbè tó dé adé sórí tó sì fi èwòn onírin se ileke owó àti tí esè. Ìdí ni yìí ti à fi máà ń yan Oba láti ìdílé enití ó te àdúgbò náà dó. Ìdílè yìí náà tílè ni ààfún tí a ń pè ni ààfin Òba ìdéwon.
20231101.yo_2124_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ìtàn so fún wa pé bí ó tilè jé pé èrúktí o té àdúgbò yìí do kii se àfín, sùgbón gbogbo àwon omo tí won bi láti ìdílè enití o te àdúgbò náà do je àfín. Nígbà ti won lo bi ifá wo, Ifá ni ki won máà bo Obàtálá ni ìdílé náà, láti ìgbà náà lo ni won ti ń bo Obàtálá ni ìdílè yìí. Ti o bad i àsìkò odún òrìsà yìí, àríyá ni fún gbogbo àwon omo àdúgbò yìí àti fún ìlú pàápàá.
20231101.yo_2124_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
C.O. Ọnanuga (1981), ‘Ìlú Ìjẹ̀bú-Òde’, láti inú ‘Ọdún Òrìṣà Agẹmọ ní Agbègbè Ìjẹ̀bú-Òde.’, Àpilẹ̀kọ fún Oyè Bíeè, DALL. OAU, Ifẹ̀, Nigeria, ojú-ìwé 3-6
20231101.yo_2124_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Oríṣìíríṣìí ni ìtàn tí à ń gbọ́ nípa ìṣẹ̀dá ìjẹ̀bú Òdẹ. Ṣùgbọ́n èyí tí ó wọ́ pọ̀ jù nínú àwọn ìtàn náà ni mo mẹ́nu bà yìí;
20231101.yo_2124_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Aládùígbò ni Odùduwà àti Alárẹ̀ jẹ́ ni apá ilẹ̀ Lárúbáwá. Odùduwà ni a gbọ́ pé ó kọ́kọ́ ṣí kúrò ní agbègbè náà wá sí Ilẹ́-Ifẹ̀. Lẹ́hìn rẹ̀ ni Alárẹ̀ kúrò ní ilẹ̀ Wàdáì; tí ó gba aṣálẹ̀ Núbíà dẹ́ Ilé-Ifẹ̀, tí ó sì ṣe “ẹ-ǹlẹ́-ń bẹ̀un o” fún Odùdùwà. Alárẹ̀ fi ọmọbìnrin rẹ̀ kan Gbórowó, fún Odùduwà láti fi ṣe aya. Lẹ́hìn èyí, ó gba ọ̀nà Ìṣẹri dé Ìbẹsẹ̀, títí ó fi dúró ní Ìjẹ̀bú-Òde. Ajẹ̀bú àti Olóde jẹ́ lára àwọn àtẹ̀lé Alárẹ̀. Fún iṣẹ́ ribiribi wọn fún ìlú ni a ṣe sọ Ibùdó náà lórúkọ wọn - Ajẹ̀bú-Olóde. Àpèjá orúkọ yìí ni ó di Ìjẹ̀bú-Òde lónìí yìí.
20231101.yo_2124_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Lẹ́hìn Alárẹ̀ ni Lúwà (OLÙ-ÌWÀ) náà dé láti aṣálẹ̀ Núbíà. Òun náà gba ọ̀nà Ilé-Ifẹ̀, ó sì yà kí Odùduwà. Lúwà àti Àlárẹ̀ bí ọmọkùnrin kọ̀ọ̀kan. Osi ni ọmọ Lúwà; Eginrin sì ni ọmọ Alárẹ̀. Ní àsìkò yìí. Ọṣìn tàbí Ọlọ́jà ni à ń pe Olórí Ìjẹ̀bú-Òde.
20231101.yo_2124_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Èdè àìyédè bẹ́ sílẹ̀ láàárín Alárẹ̀ àti Lúwà lórí, i ẹni tí yóò jẹ ọlọ́jà. Nígbà tí wọ́n tọ Ìfá lọ lórí ọ̀rọ̀ yìí, ó fí yé wọn pé ẹni tí yóò jẹ olórí kòì tíì dè!.
20231101.yo_2124_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Kò pẹ́ kò jìnnà, lẹ́hìn ikú Alárẹ̀ àti Lúwà, ni àjèjì kan tí o múrá pàpà-rẹrẹ wọ̀lú. Ọ̀nà Oǹdó ni àjèji yíí gbà wọ ìlú. Kò pẹ́, ìròhìn ti tàn ká pé àjìji kán fẹ́ gbọ́gun wọ̀lú. Èyí ni ó mú Apèbí (Olóyè pàtàkì kan ní ibùdó yìí) lọ báa bóyá ijà ni ó bá wá ní tòótọ́. Àjèjì yìí kò fèsì lọ báa bóyá ijà ni ó bá wá ní tòótọ́. Àjèjì yìí kò fèsì ju pé “Ìjà dà?. láti fi hàn pé òun kò bá ogun wá. Àjèjì náà fi yé wọ́n pé Ògbòrògánńdá-Ajogun ni orúkọ òun. Ó jẹ́ ọmọ Gbórówó tí í ṣe ọmọbìnrin Alárẹ̀ tí ó fún Odùduwà fẹ́ ní Ilé-Ifẹ̀, Ipasẹ̀ àwọn ẹbí ìyáa rẹ̀ ni Ògbòrògánńdà tọ̀ wá, lẹ́hìn ikú bàbá rẹ̀. Títí di òní, àdúgbò tí Apèbí tí pàdé Ògbòrògánńdà ni à ń pè ní ÌJÀDÀ.
20231101.yo_2124_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Àpàbí lọ fi tó olóyè àgbà Jaginrìn tí ó rán an níṣẹ́ pé ọwọ́ ẹ̀rọ̀ ni àjèjì náà mú wá. Nígbà tí Jaginrìn bi Apèbí ibi tí àjèjì náà wà, Apèbí dáhùn pé “Ọba-ńníta” (Ọba wà ní ìta) nítorí ipò Ọ́ba ni ó rí i pé ó yẹ ẹni pàtàkì bí i tí Ògbòrògbánnńdà-Ajogun. Láti ìgbà yìí ni a tí mọ Ògbòrògánńdà ní Ọbańníta, tí àjápè rẹ̀ di Ọbańta di òní. Agbègbè tí Ọníṣeémù ti lẹ́ ọ̀sà lọ tí a fún Ògbòrògánńdà láti máa gbé ni ó júwe pé” ó tóó ró”- (Ibí yìí) tó láti dúró sí) ni à ń pè ní Ìtóòró di òní. Àdúgbò yìí ni a ṣe ọ̀wọ́n kan sí ní ìrántí Ọbańta, nítorí a kò mọ bí ó ṣe kú. Inú igbó kan ni tòsí Orù-Àwà ni a gbọ́ pé ó rá sí.
20231101.yo_2124_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ògbórògbánńdá Ajogun (Ọbańta) gbé Winniadé, ọmọ Osi níyàwó. Ósi yìí, bí a ti mọ̀ ṣáájú jẹ́ ọmọ Lúwà. Ọbáńta sì jẹ́ ọmọ-ọmọ Alárẹ̀. Wọ́n bí ọmọkùnrin kan tí ó ń jẹ Mọnigbùwà. Síbẹ̀ aáwọ́ tí ó wà láàárín Lúwà àti Alárẹ̀ nípa óyè jíjẹ kò í tán láàárín àwọ́n ẹbí méjèèjì.
20231101.yo_2124_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Láti fi òpin sí aáwọ̀ yìí, àwọn ará ìlú ní kí Monigbùwà, ọmọ Ọbańta, jáde rẹ̀ ti ṣe ní ọjọ́ kìíní. ‘Mọnigbùwà gbà láti ṣe bẹ́ẹ̀. Ó lọ sí ìletò kan tí a mọ̀ sí Òdo, láti ibẹ̀ ní ó sì ti padà wọ ìlú pẹ̀lú ìfọn àti orin. Ọjọ́ yìí ni a gbé adé fún Mọnígbùwà. Oùn ni ó jẹ́ ẹni àkókó ti ó jẹ oyè Awùjalẹ̀ - ‘A-mu-ìjà-ilẹ̀’-èyí ni ẹni tí ó parí ìjá tí ó bá nílẹ̀. Àpápè oyè yìí ni ó di Awùjalẹ̀ dòní yìí. Títí di òní yìí ni ẹnikẹ́ni tí a bá yàn gẹ́gẹ́ bí ọba tuntun gbọ́dọ̀ jáde ní ìlú lọ sí Òdo, kí ó sì wọ ìlú padà gẹ́gẹ́ bí i Mọnigbùwà àti Ọbańta kí ó tó ó gbadé.
20231101.yo_2124_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Lára àwọn olóyè pàtàkì-pàtàkì ní Ìjẹ̀bú-Òde ni Olísà Ẹgbọ̀, Àgbọ̀n, Kakaǹfò, Jaginrìn àti Lápòẹkùn, tí wọ́n jẹ́ óyè ìdílé. Àwọn oyè bí i Ọ̀gbẹ́ni Ọjà kìí ṣe oyè ìdílé.
20231101.yo_2124_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Àwọn Ìjẹ̀bú fẹ́ràn láti máa jẹ kókò àti ọ̀jọ̀jọ̀. Wọ́n tún fẹ́ràn lati máa fi ògìrì sí obẹ̀ àti oúnjẹ wọn mìíràn bíi ikọ́kọrẹ́ láti fún un ní adùn àjẹpọ́nmulá.
20231101.yo_2124_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ ni àwọn ènìyàn Ijẹ̀bú Òde ní ìgbà láíláí. Wọ́n máa ń bọ oríṣìíriṣìí òrìṣà tí a ń bọ ní gbogbo ilẹ̀ Yorùbá bí i Ògún, Ifá, Èsù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn òrìṣà ìbílẹ̀ bíi Agẹmọ, Òrò, àti Obìnrin-Òjòwú wà pẹ̀lú.
20231101.yo_2124_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Lọ́de oní àwọn ẹ̀sìn ìbílẹ̀ wọ̀nyí kò ranlẹ̀ bíi ti àtijọ́, síbẹ̀ a ṣì ń bọ wọ́n lójú méjèèjì. Ẹ̀sìn Mùsùlùnì ni ọ̀pọ̀ àwọn ará Ìjẹ̀bú-Òde ń ṣe báyìí. Mọṣáláṣí kan wà ní àdúgbò Òyìngbò tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú mọ́ṣáláṣí tí ó tóbi jù ni apá ìwọ́ oòrùn Afríka.
20231101.yo_2124_29
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Àwọn ẹlẹ́sìn àtẹ̀lé Krístì Lóríṣìíríṣìí kò gbẹ́hìn. Àwọn náà pọ̀ ní iba tiwọn. Àwọn ìjọ Àgùdà tilẹ̀ fi Ìjẹ̀bú Òde ṣe ibùjúkóó fún dáyósíìsì ti ẹkùn Ìjẹ̀bú.
20231101.yo_2124_30
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni àwon ìjòyè Oba ìlú yìí tí a ń pè ni olówá tè dí, ti won si ń se ìjoba lórí àwon ènìyàn tó wà ládùgbó yìí
20231101.yo_2124_31
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni ojúbo òrìsà òsù wa. ni tori pe ibí yìí ni wón ti ń bo òrìsà yìí ni wón se ń pe e ni ìta òsù.
20231101.yo_2124_32
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni òkan lára àwon akoni ode to máa ń ye ojó ogun ti awon olóde yòókù bá ti dá síwájú tè dó ìdí niyìí tí won fi ń pe àdúgbò yìí ni Ayegun.
20231101.yo_2124_33
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Awon ounje orisirisi tí a dì sínú àpò bii àgbàdo, ìyo, ni àwon ara àgbègbè máà ń gbé wá si àdúgbò yìí wá lati tà kí ó tó di àdúgbò. Wón si máà ń na ojà ni àdúgbò yìí títí di òní yìí .
20231101.yo_2124_34
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àdúgbò yìí ni àwon Olósùgbó ti máà ń se ìpàdé. Níbè ni ilé ìpàdé wón wa, kí ó tó di pé won te ibè dó.
20231101.yo_2124_35
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ibí yìí ni ójúbo osi esi wà télètélè kí o to di pé won te ibè do tí o si dí àdúgbò ojúbo osi yìí si wa níbè títí dònìí.
20231101.yo_2124_36
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Àwon Opó ni won máà ń na ojà yìí ni alaalé. Òríta ti wón ń náà yìí ni o di adúgbò, ti wón si ń pe ni ìtà opó. Wón si máà ń ná ojà alé ni àdúgbò yìí títí dònìí
20231101.yo_2124_37
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Okunrin kan tó mú opà dání ló te apá ibí yìí dó. Ìtàn so fún wa pé àpá ase Oba ìlú ibòmíìràn ló mu dàni nígbà tí o ń bo, àwon kan tilè so pé Àremo oba ìlú náà ni. Nígbà tí o, fé te àdúgbò náà do ó mú òpá yìí dá ni, Ìdí niyìí tó fi je pé won ń je oba ni àdúgbò náà títí di òní yìí
20231101.yo_2124_38
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ìtàn so fún wa pé omi nigbogbo àdúgbò yìí teletélè kí ó to dí pe wón te ibè do. Okunrin akoni ti a ń pè ni òró ni o pé ofò tí ó sì le omi náà lo. Ìdí nìyìí ti a fi ń pé àdúgbò náà ni Ìtóòró.
20231101.yo_2124_39
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ibí yìí ni òkan lára àwon akoni tó te ìlú yii dó kokó dúró si kó tó dip é ó wo àárin ìlú lo. Nígbà ti ijà dé láàrin òun àti àwon tí wón fo wo ìlú yìí, o bínú pàdà si ibi yìí o si wolè. Ìdí niyìí tí wón fi ń pe àdúgbò naa ni Olóde. Oórì okùnrin yìí si wà níbè títí dòníì.
20231101.yo_2124_40
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Eégún kan ti won ń pè ni obrinrin ojòwú ní o te ibí yìí dó. Èégún Odoodún ni eégún máà ń jáde ni àdúgbò yìí títí donii. Ìdí igi ìrókò ni won fi se ojúbo eégún yìí Igi ìrókò yii wà níbè títí dónì yìí.
20231101.yo_2124_41
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Isé epo ni àwon to te àdúgbò yìí yàn láàyò léyìn tí wón ti dó síbè. Bí o tilè jé pé won kò se ise epó níbè mó, won si ń ná ojà epo níbè titi dò níí.
20231101.yo_2124_42
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Lára àwon ìjòyè oba Gbélébùwà àkókó tí won kò fara mo on pé kí wón pa Oba náà ni won wa te àdúgbò yìí dó léyìn ti wón kúrò ni ààfún.
20231101.yo_2124_43
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Oríta yìí ni àwon ìjoyè Oba Gbétebùwá àkókó péjo sí láti bi ara won ohun ti o ye kí àwon se fún oba náà.
20231101.yo_2124_44
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ìtàn so gún wa pé nígbà tí wín fe te ibí yìí dó, wón bá òrìsà kan níbè tó dé adé sórí tó sì fi èwòn onírin se ileke owó àti tí esè. Ìdí ni yìí ti à fi máà ń yan Oba láti ìdílé enití ó te àdúgbò náà dó. Ìdílè yìí náà tílè ni ààfún tí a ń pè ni ààfin Òba ìdéwon.
20231101.yo_2124_45
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cj%E1%BA%B9%CC%80b%C3%BA-%C3%92de
Àwọn àdúgbò ìlú Ìjẹ̀bú-Òde
Ìtùmò: Ìtàn so fún wa pé bí ó tilè jé pé èrúktí o té àdúgbò yìí do kii se àfín, sùgbón gbogbo àwon omo tí won bi láti ìdílè enití o te àdúgbò náà do je àfín. Nígbà ti won lo bi ifá wo, Ifá ni ki won máà bo Obàtálá ni ìdílé náà, láti ìgbà náà lo ni won ti ń bo Obàtálá ni ìdílè yìí. Ti o bad i àsìkò odún òrìsà yìí, àríyá ni fún gbogbo àwon omo àdúgbò yìí àti fún ìlú pàápàá.
20231101.yo_2127_0
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ilé ńlá kan tí ìjoba kó sí ìbàdàn ló ń je mòpó. Mapo Hill gangan ni orúko ibi yìí sùgbón ìgbà tó yá àwon ènìyàn bèrè sí ní pè nì òkè mòpó
20231101.yo_2127_1
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìbùdókoo kan ni èyí ní ìbàdàn; orúko èèyàn kan ni wón fi so. orúko eni náà ni Alhaji Múfútàù Oláníhùn. Ìbùdókò yìí wà ní ònà Gate.
20231101.yo_2127_2
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Èbá-Òdàn ni wón kókó ń jé télè nítorí pé ní èbá-òdàn ni àwon ògúnmólá tó té Ìbàdàn dó kókó de si kí wón tó ó bó sí àárín ìlú nígbà tí ojú ń là ni wón yí orúko náà padà sí Ìbàdàn.
20231101.yo_2127_3
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìyàwó méjì ni won jo wà lóòdò Oko gbogbo ìgbà ni ìjà ma ń wáyé láàrin àwon méjéèjì èyìn ìyàwó si ni oko ma ń gbèè sí Ìyàálé ka èyí sí àrínfín ló fi bínú dodo èyí ni wón fi ń pe odò yìí ní Orógún orúko yìí náà ni wón fi ń pe àdúgbò yen.
20231101.yo_2127_4
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Orúko ode kan ni wón fi ń pe ibí yìí kò sí ìgbà tí ènìyàn lè kojá níbè ti kò ní í bá odè náà níbè ìdí nìyí tí wón fi ń pe òdúgbò náà ni Ajíbóde.
20231101.yo_2127_5
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Adé ti àwon omo Osòrun gbé wá láti òyó ni wón kó sí ìlé kan ní àdúgbó yìí ni wón bá so ibè ní Adéòyó.
20231101.yo_2127_6
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìrísí bàbà kan tí ń jé Yusuff ni wón fi so agboolé yìí ilé bàbá yìí ni ó wà ní àkókó kàn ní àdúgbò náà. Bí ó sé tééré ló mú won so àdúgbò náà béè
20231101.yo_2127_7
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Odò àgbàrá tó ma ń dégún sí àdúgbò yìí tí ó ma ń dún gbodagbùdù ni wón fi so àdúgbò yìí ní agbedàgbùdù.
20231101.yo_2127_8
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ode ni Okùnrin yìí ni àsìkò ogun ti àwon èèyàn bá ń sá sógùn ún sósì ó wá pe àwon ènìyàn pé tí àwon dijo dúró síbí ìdí nìyí tí wón fi ń pè é ní àgbolé Bánjo ibi tí àwon ènìyàn jo sí.
20231101.yo_2127_9
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Àrèmo Obo kan ló yòó ti orúko rè ń jé Lándànì ló wá te ibí yìí dó nítorí ti ibè jé orí-òkè ni wón fi só di òkè-Àrèmo.
20231101.yo_2127_10
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìdílé Osòrun òyó ló wá te àdúgbò yìí dó ni wón fi so orúko oyè ti ìdílé won ń je lóyòó so àdúgbò náà.
20231101.yo_2127_11
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Nínú àwon tí wón ma ń mo ilé-pàálábàrá láyé ìgbà yen bàbá kan wà ládùgbó yìí tó jé ìlú mò-ón-ká nínú ìsé òmòlé ló jé kí wón so àdúgbò náà ní ilé-olómo.
20231101.yo_2127_12
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Igi ló ń jo osè yìí àwon ènìyàn ma ń dúró sídìí rè láti won okò nígbà tí ó wá dip é àwon ènìyàn ń kí ilé sí agbègbè yìí ni wón wá á fi igi yìí so àdúgbò náà.
20231101.yo_2127_13
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Egúngún ló ń jé Adábaálé láti ìlú òyó ni wón ti gbé eégún yen wá síbè, orúko eégún yìí ni wón fi ń pe àdúgbò yìí
20231101.yo_2127_14
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ìyá kan wà lágbègbè yìí tó ń ta etu, ti àwon ènìyàn bá ń lo sódò ìyá yìí won á so pé àwon ń lo sílè yèyé metu, èyí ni wón súnki di Ìyemetu.
20231101.yo_2127_15
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Odò kan ló ń jé onà àwon ìyá kan ma ń ta ewé lápákan ibi tí odò wáà ti sàn kojá idí nìyí ti wón fi ń lo ewé láti yán an kí ènìyàn lè mo ibi tí à ń tóka sí lápá odò náà.
20231101.yo_2127_16
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Okùnrin kan tó jé àáfà mùsùlùmí ló ma ń kínrun níbi yìí yóò wàá lé téńté èyin ló jé kí wón máa wi pé ìmòle lé téńté èyí ni wón se àsúnkì rè sí mòlété.
20231101.yo_2127_17
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Òde ni bàbá yìí ìlú Abéòkúta ló ti sode wá sí Ìbàdàn ibi tí ó wá tèdó sí tó ń gbé ni wón ń pé lábè ògúntulà.
20231101.yo_2127_18
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Odò kan ló sàn kojá ládùgbó yìí ti orúko rè ń jé àgbèré èyí ni wón so di orúko fun àdúgbò náà.
20231101.yo_2127_19
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: ní àdúgbò yìí kò sí omi kankan ní be tó jé pé tí wón bá gbé kànga kò lè kan omi èyí ló mú won so àdúgbò yìí ní kosódò.
20231101.yo_2127_20
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: gbogbo àwon tí wón kókó wá láti ilú ìbòmíran sí Ìbàdàn agbègbè yìí ni wón kókó dúró sí kí wón tó ó fónká ló sí ìgboro orísìírìsìí àwon èyà ní ilè-Yorùbá la lè bá pàde nib í ìdí nìyí tó fi ń jé Ayékalè.
20231101.yo_2127_21
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Orúko ìnagije tí wón fún jagunjagun kán tí àwón ènìyàn rè rò pé ó ti kú sójú ogún nítorí won kò gbúròó rè fún ìgbà pípé. Ojó tó dé ó ua àwon ènìyàn lénu ni wón ba so pé omólàde tó di orúko àdúgbò yìí
20231101.yo_2127_22
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ní ayé àtijó, a maa n ní odi ìlú, bákan náà ni a máa n ní bode ìlú. Nígbà tó di ojó kun, àwon omodé tó ń dègbé bá seesi finá sí oko. Báyì ni odi ìlú se bèrè sii jóná. Enìkan sáré wádè sáàrín ìlú láti so fún wón pé odí ìlú ti ń jóná. Báyi ni gbogbo ènìyàn se ń pari wop e Odíńjo odíńjó tí `dúgbò náà sì dí odíńjó loni
20231101.yo_2127_23
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ojúbo òrìsà yemoja wà ni àdúgbò náà, ti kò sì sí onà míràn láti gbà dé ibè yàtò sí ojú ònà kan soso. Nítorí ìdí èyí ni won se ń pe ojú ònà yìí ní òpópó yemoja
20231101.yo_2127_24
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ibi tí ojà Bodè wà lónì yìí ní enu odì ìlú nígbà náà. Ibè ni àwon omibodè maa ń dúró sí láti máa só ìlú náà.
20231101.yo_2127_25
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ènìyàn ni ó n jè òrániyàn yìí, tí ó di odò pèlú ìbínú ńlà. Ojúbo odò náà ni wón fi so àdúgbò ibè ní orúko tó ń jé láti máa fi se ìránti rè.
20231101.yo_2127_26
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Akínkanju Ológun kan ni ó di odò láyé àtijó. Ìdí nìyí tí wón fi ń pe odò náà ní orúko re Ògùnpa, ti oruko náà sì di orúko àdúgbò náà.
20231101.yo_2127_27
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ojúbo èsù ńlá kan wa ni ibi tí wón ń pè ni èsù àwèlé lorni. Ìdí sì nìyí tí wón fi ń pé àdúgbò náà ni orúko yìí.
20231101.yo_2127_28
https://yo.wikipedia.org/wiki/%C3%80w%E1%BB%8Dn%20%C3%A0d%C3%BAgb%C3%B2%20%C3%ACl%C3%BA%20%C3%8Cb%C3%A0d%C3%A0n
Àwọn àdúgbò ìlú Ìbàdàn
Ìtumò: Ibi tí a ń pè ní ilé-tuntun lónì jé igbó ń lá télètélè ti kò sì sí àwon ilé oní bíríkì kankan níbè. Àdúgbò yìí ni wón kókó kó ilé oní bíríki sí ní ìlú Ibadàn. Ìdí nìyí tí a fi ń pé é ní Ilé-tuntun.