sentence1
stringlengths
3
1.7k
sentence2
stringlengths
3
1.73k
lang
stringclasses
4 values
Dig to stole your time!
Gbẹ láti jí àsìkò
en400-yo400
What a Mess
Ìsekúse gbàá
en400-yo400
Only in broad Nollywood comedy mode does it feel truly convincing.
Àwàdà Nollywood gbòòrò nìkan ni ipò ṣe ni ò dání lójú nítòótọ́.
en400-yo400
Charmed' is not charming. No how!
Charmed kò fa ni mọ́ra. Rárá
en400-yo400
Horrible. . The show lingers on and on seeming to go no where at times.
Ó burú jù . . Ìran náà dúró bẹ́ẹ̀ sì ni àti si ti ó dàbí pé kò lọ sí ibì kan .
en400-yo400
The fact that it's a musical makes it absolutely TERRIBLE.
Torí pé ó dá lé orin jẹ́ kó burú jáì
en400-yo400
Utter fiction. The acting is awful and the story unbelievable.
Ọ̀rọ̀ ìtàn . Ìtàn náà burú àtipé Ìtàn náà kò ṣe gbàgbọ́
en400-yo400
LMAO
Mo rẹ́rìn dákú
en400-yo400
A sore disappointment, 'Levi' is drama without purpose.
Ìbànújẹ́ ọgbẹ́, 'Levi' jẹ eré tí kò ní ìdí.
en400-yo400
The film is remarkable for its lack of self-pity, but it makes the experience of "Farming" a merciless one for the audience too.
Fiimu naa jẹ iyalẹnu fun aini aanu ara ẹni, ṣugbọn o jẹ ki iriri “Ogbin” jẹ alaanu fun awọn olugbo paapaa.
en400-yo400
I am convinced it would have fared better as a 10 to 30 minute short movie to test the waters.
Mo dá mi lójú pé yóò tí dára jùlọ bíi fíìmù kúkúrú ìṣẹ́jú mẹ́ẹ̀wá sí ọgbọ̀n láti ṣe ìdánwò omi náà.
en400-yo400
drama without purpose.
eré tí kò ní ìdí.
en400-yo400
Well intentioned but amateurish attempt to move the viewer.
Ti ìpinnu dáradára ṣùgbọ́n ìgbìyànjú má gbowó láti gbé olùwò náà.
en400-yo400
Imagine trying to make indomie without spice. . This movie is soo bad that 5 minutes to the end you're still wondering what's going o.
Ronú àti ṣe Indomie láìsí oun àdídùn. Eré yi kò da débi pé, óku díè kó parí nkò mọ oun ton sẹ̀lẹ̀.
en400-yo400
The screenplay is ridiculous
Bíi àwàdà kẹríkẹrì ni wọ́n ṣe to eré yii.
en400-yo400
They just sewed together different jokes, memes and videos of little known comics that have gone viral on Nigerian social media, called it their own movie and brought it to cinema. If you are Big on social media, you will have seen many of them, many times before. And you are not likely to find them to be very funny here as the producers even fail to excel at plagiarism, leaving 'Social Media 101' plagued by bottom of the barrel acting, very boring dialogue and particularly horrible scene lighting. This is all round ridiculous!
Wó̩n kàn s̩e àtòpò̩ ò̩kan-ò-jò̩kan ẹ̀fẹ̀, àwọn àwòrán apanilérìn-in tó ti wà lórí ìtàkùn abánidó̩rè̩é̩ lásán ni. Wọ́n tó gbogbo rẹ papọ̀ wọn sì pè é ní eré tiwọn. Tí ó bá jẹ́ ẹni tó wà lórí ìtàkùn abánidó̩rè̩é̩ ni, wà á ti ṣe àkíyèsí ọ̀pọ̀lọpọ̀ won bẹ́ẹ̀ni kò sì dájú pé wo̩n yóò pa ọ́ lé̩rìnín. Ìkùnà pátápátá ni "Social Media 101". Ìdójútì ńlá ni!
en400-yo400
This movie is ugly. "Ugly" must be the word.
eré yí kò dún
en400-yo400
Another Nigerian Movie With Lot of Hype but Very Empty.. . I won't recommend this to anyone.
Eré Nigeria míràn pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àsọdùn ṣùgbọ́n tó jẹ́ kòròfo. Nkò lè sọ pé kí ènìyán wòó
en400-yo400
It's not really that bad - but the script and directing suffers overall.
Kìí ṣe pé ó burú bẹ́ẹ̀ náà ṣùgbọ́n ìṣọwọ́ kọ eré àti ìdarí rẹ̀ ni kò ní àbójútó tí ó péye
en400-yo400
The movie’s opening is jarring. There is no backstory for Laila’s appearance
Ìbẹ̀rẹ̀ fíìmù yí kàn dàbí ìgbà tí ènìyàn bá kó ẹyẹlé pọ̀ mọ́ adìyẹ ni.. . Kò sí àlàyé nípa bí Laila kàn ṣe fara hàn.
en400-yo400
Very poor story telling... and a massive rewrite of history for the sake of the movies plot.
Isọ itan ti ko dara pupọ… ati atunkọ itan-akọọlẹ pupọ nitori ìtàn fiimu naa
en400-yo400
Retarded. Gratuitous. And senseless.
Ìdádúró. Ọ̀fẹ́. Àti àìmọ́gbọ́nwá.
en400-yo400
Not a great movie
Kìí ṣe eré gidi
en400-yo400
This movie was an eyesore
Ìbànújé̩ o̩kàn gbáà ni eré yìí.
en400-yo400
it tells a piecemeal story one could swear was hurriedly written by a primary school pupil for last year's Cultural Day drama presentation
óṣo nípa ìtàn kékeré kan èyàn lé búra pé ọmọ ilé èkọ́ alákó bèrè lósáré kọ́ fún eré ìbílè ọdún tókojá
en400-yo400
If you value your time, work hard to dodge this at a premium.
Tí àkókò rẹ bá jẹ ó lógún,tẹ'pá mọ' ṣẹ́ kí o lè yẹra fún eléyìí.
en400-yo400
Can a movie be bad, but important?
Ǹjẹ́ fíìmù le jẹ́ búburú, ṣùgbọ́n pàtàkì?
en400-yo400
If I were a film prof trying to get away with torturing my students, I truly cannot think of a better fit for a required screening.
Tí ó bá jẹ́ wípé mo jẹ́ aṣàkíyèsí fíìmù tí mo wá ọ̀nà láti má kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mí, mi olè roun fún ohùn kan tó dára nítòótọ́ oun tí a nílò fún àyẹ̀wò
en400-yo400
Too long, bad acting, too much irrelevance
Ó pẹ́ jù, Ìṣeré tó burú ,àìbáramu tó pọ̀ wà níbẹ̀
en400-yo400
. Forceful story-telling and embarrassingly bad acting are the hallmarks of this shabby pretender.
ìtàn sísọ tipátipá àti eré orí ìtàgé tí óún dójú tini ní ìwà eni afìwàpamọ́ yí.
en400-yo400
How does a movie with this subject matter wind up being this slow and boring?
Báwo ni eré kan tó ní kókó ọ̀rọ̀ yìí ṣe máa ń tètè dà rú?
en400-yo400
this is a story that has the potential for critical acclaim, but the execution is poor and makes it easily forgettable.
èyí jẹ́ ìtàn tí ó ní agbára fún ìyìn pàtàkì, ṣúgbọ̀n ìpànìyàn kò dára àti kí ó jẹ́ kí ó rọrùn gbàgbé.
en400-yo400
This movie has less charisma than the 'Third Eye' series from the nineties with Pa Olu Jacobs. Stay away from this.
eré yí ní ọpọlọ ju 'ojú kẹta'' lọ tí ó jé pé ara eré àtijó pẹ̀lú 'Pa OluJacobs. yà gò fùn èyí
en400-yo400
nollywood keeps disgracing us
Àwọn òṣèré ìtàgé túbọ̀ maa n dójú tini
en400-yo400
Survival of Jelili' is a pageantry of the absurd and a flagrant eyesore.
SURVIVAL OF JELILI jẹ́ àfihàn aláyẹ̀yẹ rúdurùdu àti ohun tí kò yẹ kí ojú máa rí.
en400-yo400
At the conclusion of the original Chief Daddy movie, the introduction of a new character in the last scene hinted at a sequel, but Chief Daddy 2 takes the sophomore curse to a new level of low.
Ni ìpárí fíìmù Chief Daddy àkọ́kọ́, ṣíṣe àfihàn òșèré tuntun ni abala tí ó gbẹ̀yìn tọ́ka sí apá kejì ṣùgbọ́n Chief Daddy apá kejì tún wà fi ègún àwọn sinimá apá kejì lọ́nà tó tún bụrụ jáì.
en400-yo400
Wasn't supposed to end there.. unprofessional screenwriter
Kò yẹ kí ó tán síbẹ̀ yẹn. Àwọn tí ó kọ́ ọ́ ò kún ojú òsùnwọ̀n.
en400-yo400
The plot was totally unrealistic and it was all over the place.
Ìdìtẹ̀ náà kò jẹ́ òtítọ́ pátápátá àti pé ó wà ní gbogbo ibi.
en400-yo400
A colossal waste of time and money
ìfowò àti àkókò ṣòfò
en400-yo400
this movie is so lame, even children will not like it.
Eré yìí kò dùn rárá, kódà kò ní wu ọmọdé.
en400-yo400