sentence1
stringlengths
3
1.7k
sentence2
stringlengths
3
1.73k
lang
stringclasses
4 values
Best Nigerian movie seen in a long while. . Amazing movie that really l captures Nigerian culture and its movie industry
Fíìmù Nàìjíríà tí ó dára jù tí mo ti rí ní ìgbà díẹ̀ sẹ́yìn rèé.. . Fíìmù gidi tí ó dìídì sọ nípa àṣà Nàìjíríà àti ilé ișẹ́ fíìmù rẹ̀ ni.
en400-yo400
What a disturbing but engaging story. . . . This is a really disturbing story. I feel so sad for Enitan, I cannot possibly imagine what he went through in his childhood. His transformation is remarkable. In the final ending it reveals who Enitan is, and I'm shocked by the revelation. It brings the film to another level of emotional climax.
Irú ìtàn tí ó ń dani láàmú ṣùgbọ́n tí ó ń kóni ní papá móra wo ni èyí!. . . . Ìtàn yìí ń po ẹni nínú pọ̀ gan-an ni. Inú mi gan-an fún Eniìtàn, mi ò lè ṣàdédé fi ojú inú wo ohun tí ó làkọjá ní ìgbà èwe rẹ̀. Àyípadà rẹ̀ jọnilójú. Ìparí rẹ̀ fi eni tí Eniìtàn jẹ́ hàn, ìfihàn náà síì ṣe mí ní kàyéfì. Ó mú Fíìmù náà wá sí ìmọ̀sílára tí ó lé téńté ní ipele mìíràn.
en400-yo400
Incredible movie, great rendention and good story line.
Eré tó yani lénu, ìpinu dáradára àti ìtàn gidi.
en400-yo400
Romper Stomper with a twist and also a masterpiece drama. . . . Best Skinhead Cultural movie done in years...if you like movies like Romper Stomper, This is England, A Clockwork Orange...you will probably like this and if you like well made dramas also.... actors first movie produce and from peronal experience too....exellent work mate....loved it...so sad that people down grade this masterpiece in art form from a personal view, from a rookie of making movies... enjoy folks....
Romper Stomper pèlú Eré lílọ̀ àti àsetán. . . . Fíìmù àsà orí awo tí a gbé jáde ní ọdún séyìn…Tí mo bá féràn Fíìmù Rpmper Stomper, ‘‘This is England,A Clockwork Orange’’… O máa féràn èyí àti ọ̀pọ̀;ọ̀pò tí a ṣe dáadáa…Eré àkọ́kọ́ ṣe àwọn òṣèré máa ń jáde láti èrírí wọn…Fíìmù tó tayọ…Mo féràn rè… ó dunni láti rí bí àwọn ènìyàn ṣe ń fi ojú kékeré wò ó nítorí wípé ó jáde láti ọwọ́ ènìyàn tuntun… è gbádùn re è.
en400-yo400
Really great for women (and men too). . In a world where women are pressured to look better than they are, and live above their means, this show serves as a great tool of financial education to guide them into sensible organisation of their finances and the benefits of delayed gratification. Oh, and it's entertaining too! Fantastic acting!. . . . I don't know what's with the music production though, seems like the same songs were on repeat in every episode.
O dára púpọ fún àwọn obìnrin àti àwọn ọkùnrin náà. Nínú Ayé tí ó pọndandan fún àwọn obìnrin láti ṣe ju arawọn lọ, tí wọn sì ni gbé jù bí wọ́n ti mọ̀ lọ, eré yìí jẹ́ gẹ́gẹ́ bí irinṣẹ́ fún ìdánilékọ̀ọ́ nípa ètò ìṣúná tí o sí tún darí wọn sì Egbe ètò ìṣúná ti o dára àti ànfàní tí ó wà nínú ìserenílógo tí ó pẹ̀. Béèsìni, eré náà dún wò ó sí tún fakọyọ.. . Sùgbón o, orin inú eré nà kò dára tó.
en400-yo400
The use of proverbs, innuendos, and play on words, provides so many memorable one liners and quotes that will remain on our tongues for a long time. We will quote the lines and recall the pleasure of watching this series.
Àwọn akọ̀nlọ̀ èdè tí wọ́n lò ma jẹ́ ọ̀rọ̀ lẹ́nu wa fún ọjọ́ pípé. A má má sọ́ láti rántí eré na taa wò.
en400-yo400
Good for a first.. . A fairly straightforward plot that delivers nothing new, save being the first Nigerian Christmas themed movie. The casting was sweet.
Ó dára fún ìgbà àkọ́kọ́. . . Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀hun rẹ̀ já gaara díẹ̀, kò sí nnkan tuntun nínú eré náà. Ohun ni fíìmù àgbéléwò tó dá lórí Kérésìmesì ni Nàìjíríà. Ere yìí dùn díẹ̀.
en400-yo400
A very good movie with a good lesson!. . . . This is movie is about a coming of age comedy/drama about a young boy who wants to fix things with his hands rather sit behind a cubicle. In a broader sense, I think this is just celebrating how things are done in Africa, and how kids learn to be humble.
Sinimá tí ó dára tí ó sì kọ́ni lọ́gbọ́n rere ni.. . . . Sinimá yìí dá lórí ọmọ ọkùnrin kan tí ó ń dàgbà tí kò sì fẹ́ káwọ́ gbera. Tí a bá wò ó, mo wòye pé sinimá yìí ń fi bí ati ń ṣe ní ilẹ̀ Adúláwò hàn ni àti bí àwọn ọmọdé ṣe ń kọ́ bí a ti ń ní ìtẹríba.
en400-yo400
Citation delivers on giving us a logical representation of what happens in the real world to a large percentage of the youth, particularly students, and more particularly those of the female gender.
CITATION ṣe àfihàn ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí èyí tí ó pọ̀jú nínú àwọn ọ̀dọ́ wa, pàápàá àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti pàápàá àwọn tí ó jẹ́ obìnrin.
en400-yo400
Crazy,Lovely,Cool. . . . My favorite Nigerian actress Adesua Etomi-wellington brought me to this tv series and I was not disappointed, it was a pleasant surprise to see good acting, really good writing on top of seeing her, all main characters had substance and were not over the top cliché characters, each episode could stand on it's own with plot twists and reveals, if anybody is looking for a good binge watch you couldn't go wrong with this Nigerian gem
Òṣèré obìnrin tí mo féràn jù Adesua Etomi Wellington ló gbé mi débi eré onípele yii, mi ò sì kà bá mó rẹ̀. Ìdùnnú ló jẹ́ láti ri eré ṣíṣe tó dára, àti eré kíko pẹ̀lú rírí i, gbogbo àwọn òṣèré ṣe dára dára, ẹ́písòdù kò kan le dá dúró. Ti ẹni Kéni bá ń wá eré gidi láti wò, o le ṣàṣìṣe láti wo arábìnrin to yàtò ti Naijiria yìí.
en400-yo400
It’s a pity, because this could have been very interesting. But as it is, it's just total amateur hour.
Ó ṣe ni láàánú, nítorí èyí le jẹ́ ìyanilẹ́nu púpọ̀ . Ṣùgbọ́n bí ó ti jẹ́, ó jẹ́ àkójọ pọ̀ wákàtí tí kò gbéwọ̀n
en400-yo400
Was glued!!!!. . . . I enjoyed it. It was brilliant coming from the stables of Hollywood movies. Not a wasted time spent
Ó mu mí mólè !!!. . . . Mo gbádùn rẹ. Èyí jẹ́ eré àgbéléwò tó dára púpò to jáde wá lá́ti inú àwọn fíìmù Hollywood . Mi ò fi àkókò mi ṣòfò rara.
en400-yo400
Phenomenal!! Proud of this Nollywood Production!!
Ó ga jù.. . Mo fi Ògún Nọ́líwuùdù gbá orí fún àkójọpọ̀ ère yìí.
en400-yo400
An Amazing Movie. . . . A beautiful story, well told & portrayed. Everything from the locations to makeup, cast, costume, even language & and the showcase of culture was simply breathtaking. Well done Kunle Afolayan
Fíìmù to yanilenu. . Itan to rewa, siso daadaa ati sise daadaa. Gbogbo nkan lati ibi ti won ti se ere, kikun oju, awon osere, ede ati fifihan asa dara.. . Ku ise nKunle Afolayan
en400-yo400
Super Recommended! 'Gold Statue' is Magnificent Excellence. It promises a mountain of fun. And with that mountain, comes rivers of quality and an avalanche of Perfect acting performances. This movie is worth every penny you will spend and more.
Eré yìí dára gan ó sì sée fii yangàn àti pé àṣeyọrí ńlá ni ó jẹ́. Eré orí ìtàgé yìí dára gan ni mo sì gbádùn wíwòo rẹ̀. Oun ìdárayá ní sinima yìí jé, gbogbo ìpele rẹ ní wọn ṣe iṣẹ takuntakun láti le mú kó wú ni lórí. Mo gbà pé mí ò fowó Jóná lórí sinimá àgbéléwò yìí.
en400-yo400
Hands down the best Nigerian movie I have ever seen..
Láì sí ijiyan rárá eré orí ìtàgé yìí ní ó tíì dáa jù nínú àwọn eré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
en400-yo400
Good but Kinda Cheesy. . I liked this murder mystery from Nigeria. . . The plot was thick and readable part way in but far enough in to keep my interest.
O dára sùgbọ́n ó rújú díè. . Mo féràn àdìtú nípa ìpànìyàn ti orílè-èdè Nàìjíríà. Àwọn ìsèlè da sùgbón ènìyàn tilè mọ ibi tí eré náà ń lọ àmọ́ mo ní ìfé síí eré náà.
en400-yo400
Interésting. . . . This movie was interésting from start to finsh. The acting was world class.
Ó dùn . . eré yìí dùn láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin. eré ṣíse náà dára gáan.
en400-yo400
What it means to be Nigerian.. . . . Well done Genevieve Nnaji: a movie for all to see. Kudos Naija, keep improving.
Ohun tí o jẹ́ pàtó láti jẹ ọmọ Nàìjíríà, Genevieve Nnaji kú iṣẹ́. Fíìmù tí ènìyàn gbogbo gbúdọ̀ wò, Naijiria saara rẹ,má tẹ̀síwájú.
en400-yo400
Only one problem
Ìṣòro kan ṣoṣo
en400-yo400
Lionheart is a solid film that effectively portrays sexism in workplace in Nigeria. It is very straightforward, highly predictable and also quite weakly directed by Genevieve Nnaji. But on the opposite side of things, her acting performance is terrific, and she successfully elevated both the character and the overall material. The movie is clichéd, but charming. It would have been a perfect potential nominee for the Academy had they not stupidly eliminated it due to it being filmed in the English language.
Lionheart jẹ́ fíìmù tí o lágbára tó sì fi ìbálòpọ̀ hàn dáradára ní ibi-iṣẹ́ mi orílè-èdè Nàìjíríà. Ó wá ní ọ̀nà òtítọ́, àsọtẹ́lẹ̀ gíga àti ní ìtọ́sọ́nà ní ye aláìlágbára nípasẹ̀ Genevieve Nnaji. Ṣùgbọ́n ní ọnà ìdákejì, iṣẹ́ ṣíṣe rẹ̀ kò jẹ lásán àti wípé o fi iṣẹ́ ìgbéga hàn fún òṣèré ati awọn òun èlò òṣèré. Fíìmù nàà jẹ́ oun ìwúrí. Yíò o dára láti yàn án fún ilé - ẹ̀kọ́ fíìmù,tí kò bá n se wipe wọ́n ṣe ní èdè gèésì.
en400-yo400
Mind blowing!!!!. . . . This is one of the best movies I have ever watched! I LOVE it!!!!!
Ìyànílenu!!!. . Eré yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn eré tí mo ti wò láyé. Mo fẹ́ràn rẹ̀!!!
en400-yo400
A wonderful film experience! Substantial storyline.. . The suspense would keep you on your toes, and the comic relief would make you chuckle. It is definitely worthwhile.
Eré orí ìtàgé tí mo gbádùn wíwò rẹ ní, ìtàn eré náà dára púpọ̀. . Ài mọ oun tókàn nínú eré yìí máa mú kí o fojúsọ́nà, lẹyìn ìgbà náà wàá tún rérìn lẹyìn ìgbà tó bá rí abajade iṣẹlẹ kan nínu eré yí.. . Àkókò tí mo fi sile lati wo eré orí ìtàgé kò sòfò dànù
en400-yo400
A good sequel but a remake would have been far better for good story buildup. . . . I must say I commend the director and his acting too ( Ramsey Nouah).
Ere ònídàákúrekú ṣùgbọ́n àtúnṣe rẹ̀ ìbá dára fún ìtàn gidi. . . . . Mo gbóríyìn fún olùdarí ere yìí (Ramsey Nouah) àti ọ̀nà ìṣeré rẹ̀
en400-yo400
100% on point. So accurate n so well played. Everyone was fantastic. Makes one proud ure Nigerian 👏👍😘
Eré orí ìtàgé yìí dára gan-an. Kòsí àbàwọ́n kankan bóti wù kó mọ. Gbogbo ènìyàn tó lọ́wọ́ sì fíìmù yìí gbìyànjú gan. Wọ́n sì mú orí mí wú pé orílè-èdè Nàìjíríà tèsíwájú nínú eré oríìtàgé
en400-yo400
It is beautiful to see Sam Dede on our screens again, and to see he is still a master of his craft, giving us a stellar performance. Where there is Stella Damasus, you can be sure to see some genuine tears, with emotional scenes, and she seems ageless.
Ohun ìdùnnú ni láti rí sam dédè lójú pátákó ìṣeré àti lasi tún tí rí pé ó ṣì meré ṣe ibi kí bi to bá tí ri Stella Damascus, ó dá mi lójú pé omi ẹkún ma jáde lójú ẹ. Ko ti ẹ jọ pé ó ń dàgbà.
en400-yo400
Perfection. . . . This is a must watch movie!. I can't even say more. I'm short of words.
Pípé. . . . Kòṣemawo ni sinima àgbéléwò yìí!. N ò tiẹ̀ lè sọ púpọ̀. Ọ̀rọ̀ tán lẹ́nu.
en400-yo400
Interesting how open the characters are to speaking about their relationships and with restraining anger during such emotional circumstances.
Ó wúni lórí àwọn pẹ̀lú ọ̀nà tí àwọn osere gbà láti sọ nípa ìbásepọ̀ wọn pẹ̀lú ìbínú tí kò farahàn rárá.
en400-yo400
It was pretty interesting to actually find out how the hymn Amazing Grace was actually written.
Ó dùn móni gidigidi láti mọ bí orin Amazing Grace ṣe di kíkọ
en400-yo400
This movie really touched my heart in regards to God's AMAZING GRACE! A MUST SEE!!!
Nípa ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run tí ó ga jù, sinimá yìí fi ọwọ́ tọ́ ọkàn mi gidi ni. À gbọdọ̀ wò ni.
en400-yo400
Not only does the plot fail to grip the viewer's attention, but the acting is the poorest, most unconvincing ever.
Kìí ṣe pé ìtàn náà kùnà láti di àkíyèsí olúwo náà nìkan, ṣùgbọ́n ṣíṣe rẹ̀ ló jùlọ, tí kò ní ìdánilójú láíláí.
en400-yo400
This movie is long and dull. Even the background music is tepid. And there's nothing that can do to save the movie.
Eré yìí gùn s̩ùgbón kò dùn. Kódà, orin ti wó̩n ń ko̩ ní abé̩lè̩ gan-an kò wúlò. Kò tilè̩ si ́nǹkankan tí a lè s̩e láti s̩àtúns̩e eré yìí.
en400-yo400
A fine way to completely ruin your day
Ọ̀nà tó dára lati ba ọjọ́ èyàn jẹ́ tán yányán.
en400-yo400
unsettling
Kò farabalẹ̀.
en400-yo400
The subjects in Swallow would make anyone cry -- poverty, sexual harassment, drug dealing, systemic corruption -- but the movie and all the characters are flat and emotionless.
Àwọn kókó-ọ̀rọ̀ tí ó wà nínú Swallow yóò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni kígbe - òṣì, ìfipábánilòpọ̀ ìbálópọ̀, ìṣòwo ogun olóró, ìbàjẹ́ ẹ̀tọ́ - ṣùgbọ́n fíìmu náà àti gbogbo àwọn ohun kíkọ jẹ́ aláìlérò àti àìbìkítà.
en400-yo400
Though the central performance is impressively raw Farming's uncompromising bleakness drowns out the fascinating story, making it a far tougher watch than it needs to be.
Bótilẹ̀jẹ́pé iṣẹ́ àárín jẹ́ ìwúnilórí àìse àìbalẹ̀ àìbìkítà tí àgbẹ̀ bigbé e rì ìtàn tí ó fanimọ́ra náà, tí ó jẹ́ kí ó jẹ́ wíwú tí ó nira púpọ̀ ju tí ó nílò láti jẹ
en400-yo400
Story inconsistencies and the mystical balderdash were too appalling to be saved
Àwọn ìdákú dájí inú ìtàn yìí àti àwọn ohun bíi òògùn àti awo tí kò mú ọgbọ́n kankan dání tí pọ̀ ju kí ènìyàn tọ́jú sinimá yìí lọ.
en400-yo400
There wasn't a single person that wasn't insulting this as we trooped out. Even cinema staffers who didn't pay, were hissing. Horrible
Kò sí ènìyàn kan tí kò gàn èyí bí a ṣe ń ja ogun jáde. Pàápàá àwọn òṣìṣẹ́ sinimá tí kò sanwó, tí ń rẹ́ẹ̀rín. Ìríra!
en400-yo400
Equally powerful and uncomfortable, Farming is a stark reminder of the dangerous lengths that self-loathing can lead to.
Bákánnà ni agbára àti àìbalẹ̀, Ọ̀gbìn jẹ́ olùránnilétí tí ó wuyì tí àwọn gígùn tí ó léwu ti ìkóríra ara ẹni lè já sí.
en400-yo400
A terrible way to start the year; 'Akpe' is a mess.
Ọnà tó burú láti bẹ̀rẹ̀ ọdún, 'Apke' ò já mọ ǹkankan
en400-yo400
You might not hate yourself for seeing 'SuperStar' but you will leave feeling numb & comatose.
Ọ lè máa kórira ará pé ọ pàdé ṣùgbón ọ kúrò bi ẹni pe ọ ọpọlọ rẹ kú.
en400-yo400
It would definitely be unfair to the entire cast and crew if I left this one out. Totally unfair!
Ìyà jẹ ní fún àwọn tí ó kópa nínú eré tí mo bà yọ èyí kúrò. Kò dáa rárá.
en400-yo400
Like other misguided projects like it, 'Knock Out Blessing' was made primarily for the purpose of massaging its producers' ego rather than pleasing its Nigerian audience.
Bíi àwọn eré tó kùnà ókù, 'Knock Out Blessing' ń polongo àwọn tó gbé e jáde kìí se fún àwọn tó ń wòó ni Nigeria.
en400-yo400
Akinnuoye-Agbaje's slightly numbed screenplay never gets to grips with who Eni is
Eré Akínnùóyè-Agbájé fẹ́rẹ̀ kú kò gbà láti díi mu ẹnití Ẹ̀ní jẹ́.
en400-yo400
Fifty minutes is spent advertising a holiday resort in Lagos, Movie closes. Money down the drain. Not recommended
Àádọ́ta ìṣẹ́jú ni a fi wọ ìpolówó ilé ìgbafẹ́ ní èkó, ère parí. Owó wọ'gbó. Kò ṣeé ròyìn.
en400-yo400
Such a shame really; 'The Island' is a waste of amazing talent.
Ojútì gbáà, 'The Island' fi àkókò àti tálẹ́ńtì ṣòfò
en400-yo400
if I said to you, that this was a spectacular movie, I would be telling a lie.
tí mo bá sọ fun ọ pé fíìmù ìyàlẹ́nu ni èyí, irọ́ ni èmi yóò sọ.
en400-yo400
Its lateness aside, the real problem with 'Funke' is that it is boring and unexciting.
Yàtò sí pípe rè, ìṣòro 'Funke' ni pey kò dùn.
en400-yo400
Not recommended! Crispy dry and terribly banal,
Ẹ má wò o.. . Ó ṣá, kò dáni lára yá. Eré tẹ́ńbẹ́lú ni.
en400-yo400
Ultimately, this is a crappy offering that shouldn't have been brought to cinema.
Níkẹhìn, èyí jẹ́ ẹ̀bùn ìnira tí kò yẹ kí ó mú wá sí sinimá.
en400-yo400
Production is fine, above average. Colour is sharp. And acting isn't horrific. The problem is the complete lack of intellectual strength in the story & the story-telling. A quick example will suffice:
Ní ti ìgbékalè̩ is̩é̩, ó dára. Àwòrán rè̩ jáde dáadáa. Kíkópa àwo̩n òs̩èré náà kò fi bé̩è̩ burújáì. Ibi tí wàhálà wà ni àìsí àpe̩re̩ ìmúlò o̩gbó̩n inú nínú ìtàn àti ìtàn síso.
en400-yo400
the amount of felonies this 6 year old committed over the course of this film became too many to count
Ìwà ìkà tí ọmọ ọdún mẹ́fà yí ti ṣe lórí pàápàá ti yí fíìmù di púpọ̀ láti kà
en400-yo400
Suitable for 14 year olds. . Performed like a very clean Disney story. Limp and vacuous.
Ó dára fún àwọn ọmọ ọdún mẹrinla. Ìṣe eré nà dàbi ìtàn Disney tó mọ.
en400-yo400
There are some funny touches and moments of freewheeling energy, but it is too broad, with acting and directing styles that are a little like afternoon TV.
Díẹ̀ nínú àwọn fọwọ́kàn alárinrin àti àwọn àkókò tí agbára ọ̀fẹ́, ṣùgbọ́n ó gbòòrò púpọ̀, pẹ̀lú iṣé àti àwọn ìtọ́sọ́nà tí ó jẹ́ díẹ̀ bíi tẹlifísọ̀n ọ̀sán.
en400-yo400
Average. . The plot is just too short and predictable.
Àpapọ̀ . . àpéjọ eré jẹ́ kúkurú púpọ̀ àti àsọtẹ́lẹ̀.
en400-yo400
But unfortunately, these shining moments were just to few and far between for them to justify paying serious money to see this
ṣùgbọ́n, àkókò dídán yí kéré ósì jìnà fún won láti san owó tójọju láti fi wo yí
en400-yo400
moreover the drama between Joseph to his wife is played naturally but I feel like this is more documentry then a movie…
Àti pé dirama tí ó wà láàrín Jósẹ́fù àti aya rẹ̀ àṣẹ bí àdáyébá ṣùgbọ́n idà í ìgbà wípé àṣẹ bí dọkumẹ́tìrì
en400-yo400
Consequently, rhythms of long and short hisses echoed intermittently from the audience
Nítoríbẹ́ẹ̀, àwọn rídìmù ti gígùn àti kúkúrú wọ́ òsé ṣe ń fọhùn láìpẹ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn olùgbọ́
en400-yo400
No one deserves to watch this shitty movie
Kò sí ẹnì kankan tí ó yẹ kí o wo eré rádaràda yìí.
en400-yo400
snooze fest, not much story, ridiculous soundtracks
Dídùn hàn, Ìtàn tí kò pọ̀, ohun agbohùn burúkú
en400-yo400
add horrible ADR, and average to really bad acting, and you have —- a nightmare.
Ìlò ohùn àwọn òșèré mìíràn lórí tí àwọn tí à ń wò ní ọ̀nà tí kò dára rárá ní èyí àti ìṣọwọ́ ṣeré tí kò kún ojú òṣùwọ̀n dé orí pé kò dára rárá. Àlákálàá ni èyí yóò fún ọ
en400-yo400
It doesn't go wholly wrong all at once, but damned if the filmmakers don't lose the thread and stumble and lurch and pad this thing until their Nollywood film is Bollywood length, without the wit, warmth or content to justify it
Kí í ṣe è̩è̩kan náà ni gbogbo rẹ̩̀ dojúrú. Kí í ṣe dandan ni kí àwo̩n tó ń gbé fíìmù jáde jẹ́ kí Nollywood gún bí í tí Bollywood láìsí ìtàn, ọgbọ́n àti nǹkan tó yẹ láti jẹ kí a gbádùn rẹ.
en400-yo400
Grotesque and sub-standard. Boring and downright stupid!
Ǹkan tódáa àti ìhà-bóṣewà. Aláìdùn àti ìsàlè òmùgọ!
en400-yo400
A flawed first feature film, but it shows a great deal of promise
Fíìmù ẹ̀ya àkọ́kọ́ tí ó ní àbàwọ́n, ṣùgb́ọn ó fihàn àdéhùn ńlá kan.
en400-yo400
Concerning this popular movie #KOB I can't say it better or worst than the rest of nollyhood,
Nípa eré to gbajúmọ̀ yí #KOB nko lè sọ pé ó dára tàbí burú ju àwọn ìyókù nollyhood lọ
en400-yo400
Made in Heaven' is a stupid movie. It is so stupid, it will irritate you to the point you will start laughing out of sheer frustration. You will grow so weary seeing it, you will suddenly find yourself feeling as though you just might be enjoying the foolishness of this foolish movie. Very ridiculous movie. Complete rubbish!
Ere àwọn òpònú tí kò mú ọpọlọ lọ́wọ́ rárá ní eré "Made in Heaven" jẹ́. Ẹni tó bá wo ère yìí kò ni í mọ ìgbà tí òun yóò máa ré̩rìn in látàrí ìbínú tí ere náà lè fà. Ère tó lè fà ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn ni. Réderède tó kún inú ère náà tó láti pá ènìyàn lẹrin-in. Òsì pátápátá gbáà ni ère yìí.
en400-yo400
Slow moving, great acting and contains a few chills but the ending was unforgiving
Gbígbé lọ́ra, ìṣeré ńlá àti pé ó ní àwọn bíba díẹ̀ nínú, ṣùgbọ́n ìparí kò ní ìdáríjì.
en400-yo400
. In the absence of such a perfect storm, avoid stabbing your wallet in the heart with this 'Dagger'.. . Definitely not recommended
Ní àìsí ohun tí òní láárí kan tí a lè rí dì mú, má wulẹ̀ fi owó rẹ ṣòfò pé ò ń ra sinimá Dagger.. . N kò gbà ọ́ ní ìmọ̀ràn láti wò ó rárá.
en400-yo400
When I say that the drive for comedy is turning our content to shit, this is a prime example.
Tí mo bá sọ wípé kìràkìtà pé a fẹ́ ṣe eré apani lẹ́rìn-ín ti wá ń sọ kókó inú àwọn fíìmù di rádaràda, èyí gan-an ni àpẹrẹ àkọ́kọ́.
en400-yo400
If you watched Chief Daddy: Going For Broke on its New Year Day release on Netflix and immediately thought it to be a contender for the worst movie of the year, know that the fault isn't yours;
Tí o bá ti wo sinimá Chief Daddy :Mò ń lọ wo Broke ní ọjọ́ ọdún tuntun tí wọ́n gbé e jáde, léṣẹ̀kẹsẹ̀ ni mo gbà á lérò pé ó yẹ kí ó díje fún sinimá tó burú jù nínú ọdún yìí. Mọ̀ pé ìwọ kọ́ ni o ni ẹ́bi.
en400-yo400
Lazy and depressing!
Ọ̀lẹ àti ìrẹ̀wẹ̀sì!
en400-yo400
snooze fest, not much story, ridiculous soundtracks
Sún kẹẹrẹ, kò fi bẹ́ẹ̀ sí ǹkankan nínú eré yìí, àwọn orin tí wọ́n lò kò dára rárá.
en400-yo400
The movie wasn't great, a bit of overreaching of the actors (maybe over-directed?) but the context was great.
fíìmù kó jẹ́ ńlá, díẹ̀ nínú àwọn òsère ń seré ju bóti yẹ lọ (bóyá lórí-ìdarí?) Ṣùgbọ́n ibi tí wọ́n ti yà á dára
en400-yo400
Low quality for Such a High Budget
Iṣé̩ ye̩pe̩re̩ tó kéré sí adúrú owó tí a ná lé e lórí.
en400-yo400
A good plot. Terrible post-production.
Ìpìlẹ̀ ère díída lẹ́yin ìgbèjàde rẹ̀ tó buru
en400-yo400
Not recommended.
Kò ṣeé dá l'ábàá
en400-yo400
Great story, poor acting.
Ìtàn ńlá, ṣíṣe tí kò dára.
en400-yo400
A star studded movie that made stars look like they were acting a kindergarten play
Eré tí ó kún fún àwọn gbajúmọ̀n tí ó wà dàbí wípé wọn ń ṣe eré ọmọdé.
en400-yo400
Not recommended.
àìfọwósí
en400-yo400
Preposterous! Horrendous! Disgraceful! A glowing shame.
Ìbànújẹ́! ìtìjú! Ìtìjú didan.
en400-yo400
This movie's lineup makes me want to like it desperately, but it's difficult to relish amid the dim screenwriting by Genevieve Nnaji.
Àkójọpọ̀ eré yi ló jẹ́ kín fẹ ní gbogbo ọ̀nà, ó sòro láti m'ójúkúrò nítorí isé ribiribi ti Genevieve Nnaji ṣe síbẹ̀.
en400-yo400
By sure, one on the worst horror movies ever made...
ní dídájú, ọ̀kan lára eré tí ó bani lérù tí wón ṣe
en400-yo400
Talk about the acting though, the story script, it's something out of this world
Tí a bá ń sọ̀rọ̀ ní́pa eré síse, ìko̩sílé̩ ìtàn, nǹkan ìyàlẹ́nu tó jó̩ni lójú ni.
en400-yo400
Though falsely classified as "Horror", 'Bridal Shower' is in actual fact not a Horror-movie. It is a Stupid-movie- Completely and utterly stupid!
Bó tilè je pe wón kà á sí eré tó ń ba ni lẹ́rù, 'Bridal Shower' kìí se eré bẹ́ẹ̀. Ereé rádaràda ni, kò ní ìtumò rárá.
en400-yo400
it is wholesomely pointless - A desperate money grab.
ó jẹ́ ọ̀nà tó dára àmọ́ kò ní tumọ̀ - wíwá owó kíá kíá
en400-yo400
Major Disappointment
ìjákunlẹ̀ ní pàtó
en400-yo400
Boring
Ìdáni lágara ni
en400-yo400
Charming but incompetent
Ó n dùn ṣùgbọn kò kún ojú òṣùwọ̀n tó.
en400-yo400
Ruined by technical malfeasance, 'The Perfect Picture' proves to be miles away from being perfect.
ló bàájẹ, 'àwòrán ti dára jùlọ' fi dáni lójú pé eléyìí jìnà púpọ̀ sí ohun tó dára.
en400-yo400
Slow moving predictability. . This film definitely belongs in the junior high circuit.
Ó lọ́ra gbígbé àsọtẹ́lẹ̀ Eléèyí fíìmù pàtó jẹ́ ti ní àwọn high junior Circuit.
en400-yo400
but the sound and music was so bad that it destroyed anything good
Ṣùgbọ́n ohun àti orin rẹ̀ burúkú tí ó tilẹ̀ ń bá ohunkóhun tí o dáa jẹ́
en400-yo400
Did not watch all of this crap. Not even second rate, obviously racially inclined crap from an African nation with no film industry.
Nkò wo gbogbo ìranù yíí.. . Kò yẹ fún ìgbóríyìn rárá,. . Ìranù láti ilè aláwò dúdú tí kò ní àkójopò àwọn òṣèré.
en400-yo400
Good storyline, poor execution
Ọ̀nàìkọ̀tàn tó dára , Ìṣe tí kò dára
en400-yo400
The acting was bad, the soundtrack were repetitive, the storyline was... (if there was one I would have described it here).
Ṣíṣe ere náà kódà a, orin rẹ̀ jẹ́ àkọtúnkọ...... . Ọ̀nàìkọ̀tàn náà jẹ́ . . (bí ó bá jẹ́ pé mo le fi ùn kan tọ́ka sí i níbí )
en400-yo400
The plot it's good, but the technical aspects aren't that good at all.
Ìpì̀lẹ̀ ère náà daada, ṣùgbọ́n ẹ̀ka tẹ́kíníkà kò dára rárá.
en400-yo400
A clunky, clumsy handling of a book with (here untapped) depth
Abojútó, mímú mímú ìwé kan pẹ̀lú (níbi tí a kò tẹ̀) ìjìnlẹ̀
en400-yo400
There's nothing good about 'That Which Binds Us'. Absolutely nothing.
Kò sí òun kán tó dára nípa 'What Binds Us'.
en400-yo400
Production of this movie is tight but the heart is missing
Ṣíṣejáde fíìmù yìí ti ṣòro, ṣùgbọ́n ọkàn ti ń sọnù.
en400-yo400
Focused as it is on the relationship between Joseph and Suzy, the movie sheds little light on the February 13, 1976, assassination, which brought Olusegan Obasanjo to power.
Kọ́kọ́ wà lórí ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàrín Jósẹ̀fù àti súsì, Eré tí ó rán ìmọ́lẹ̀ sí Fẹ́búárì 13,1976,Ìpànìyàn, tí ó mú Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ wá sí ìjọba.
en400-yo400
Utter rubbish! These are not serious people. Please, don't reward them with your Naira.
Ìsekúse gbàá! Àwọn ẹni yìí kò ní nkán ṣe. Dákun, má fí náírà rẹ fún wọn lérè.
en400-yo400