sentence1
stringlengths 3
1.7k
| sentence2
stringlengths 3
1.73k
| lang
stringclasses 4
values |
---|---|---|
I am convinced it would have fared better as a 10 to 30 minute short movie to test the waters. | I dey convince e for beta as 10 to 30 minute short film to test di wata. | en400-pcm |
drama without purpose. | Drama wey no get porpose. | en400-pcm |
Well intentioned but amateurish attempt to move the viewer. | Di intention gud but na novince attempt dem use move di people wey dey watch | en400-pcm |
Imagine trying to make indomie without spice. . This movie is soo bad that 5 minutes to the end you're still wondering what's going o. | Just imagine say u wan try run indomie without di spice .. . Dis film too bad so tey 5 minutes to di finishing u go still dey wonda say wetin dey hapin. | en400-pcm |
The screenplay is ridiculous | U no fit believe di screenplay | en400-pcm |
They just sewed together different jokes, memes and videos of little known comics that have gone viral on Nigerian social media, called it their own movie and brought it to cinema. If you are Big on social media, you will have seen many of them, many times before. And you are not likely to find them to be very funny here as the producers even fail to excel at plagiarism, leaving 'Social Media 101' plagued by bottom of the barrel acting, very boring dialogue and particularly horrible scene lighting. This is all round ridiculous! | Dem just gum diffrend jokes togeda, memes and videos wey dem dey call comedy wey don cast for Naija social media, call am dem own film and carry am go cinema. If you dey big ontop social media, u go don see many of dem, many time before... And you no go wan find dem to be funny here as di people wey produce am fail to win for copy copy, comeleave 'Social media 101' wahala for di bottom of di barrel acting, di dialogue dey very boring and di main di main na di horrible scene lighting. Dis one na one big bad thing! | en400-pcm |
This movie is ugly. "Ugly" must be the word. | Dis film ugly. "Ugly" na di main word . | en400-pcm |
Another Nigerian Movie With Lot of Hype but Very Empty.. . I won't recommend this to anyone. | Anoda Naija film wey Dem use hype kill but e too empty. I no fit recomend am for anybodi. | en400-pcm |
It's not really that bad - but the script and directing suffers overall. | No be say dis wan too bad, but di script and how dem direct am na ein suffer am. | en400-pcm |
The movie’s opening is jarring. There is no backstory for Laila’s appearance | Di opening of di fim clash. Dem no create backtori for Laila appearance | en400-pcm |
Very poor story telling... and a massive rewrite of history for the sake of the movies plot. | Di Tori telling too poor ....and Dem too rewrite history bikos of di film plot. | en400-pcm |
Retarded. Gratuitous. And senseless. | Delay. Unnecessary And no make sense. | en400-pcm |
Not a great movie | No b beta film | en400-pcm |
This movie was an eyesore | Dis film no make for eye atall. | en400-pcm |
it tells a piecemeal story one could swear was hurriedly written by a primary school pupil for last year's Cultural Day drama presentation | Na pieces tori, pesin fit swear say na one primary sku pikin just rush write am, wen Dem wan do last year presentation drama. | en400-pcm |
If you value your time, work hard to dodge this at a premium. | If sa you value your time, make you work hard make you dodge dis for di premium. | en400-pcm |
Can a movie be bad, but important? | Film fit bad, but make im important? | en400-pcm |
If I were a film prof trying to get away with torturing my students, I truly cannot think of a better fit for a required screening. | If I be film Prof I kon dia try to torture my student, I no fit think for better required screening. | en400-pcm |
Too long, bad acting, too much irrelevance | E too long acting wey bad, wetin no get meanin too much. | en400-pcm |
. Forceful story-telling and embarrassingly bad acting are the hallmarks of this shabby pretender. | By force tori wit bad actin wey dey embarrassin wit di hallmark of dis shabby pretender. | en400-pcm |
How does a movie with this subject matter wind up being this slow and boring? | How film with dis subject matter wind up fit slow like dis and boring | en400-pcm |
this is a story that has the potential for critical acclaim, but the execution is poor and makes it easily forgettable. | Dis one na tori wey get potential to critical acclaim, but as dem take do am poor and e make am easy to forget | en400-pcm |
This movie has less charisma than the 'Third Eye' series from the nineties with Pa Olu Jacobs. Stay away from this. | Dis film get small charisma pass 'Third Eye' series from nineties with Pa Olu Jacob. No put mouth for dis one | en400-pcm |
nollywood keeps disgracing us | Nollywood just dey disgrace us | en400-pcm |
Survival of Jelili' is a pageantry of the absurd and a flagrant eyesore. | Survival of Jelili na pageantry rubbish wey dey vex person. | en400-pcm |
At the conclusion of the original Chief Daddy movie, the introduction of a new character in the last scene hinted at a sequel, but Chief Daddy 2 takes the sophomore curse to a new level of low. | For di conclusion for original chief Daddy film, de introduction for one new character for de last scene hinted for sequel, but chief Daddy self take sophomore curse for one new level of low. | en400-pcm |
Wasn't supposed to end there.. unprofessional screenwriter | E no suppose to end there...screenwriter wey no sabi work | en400-pcm |
The plot was totally unrealistic and it was all over the place. | Di plot no dey realistic atall and e dia for everiwhere | en400-pcm |
A colossal waste of time and money | Na big waste for time and money | en400-pcm |
this movie is so lame, even children will not like it. | Dis film dey lame, even children no go like ahm. | en400-pcm |
A steamy soap opera unfolding against the backdrop of a cautionary history lesson reminding us that in Nigeria, the more things change, the more they stay insane. | Fíìmù ìgbà dé gba tí ó ń șọ́ra sọ ìtàn tí ó ń kọ́ni lọ́gbọ́n tí ó sì ń rán wa létí pé ní Nàìjíríà bí àyípadà ṣe ń dé náà ni gbogbo ǹkan ń dàrú sí i. | en400-yo400 |
An enormous amount of work and scrutiny went into making this. Such an enormous amount, its quality stands out easily and brazenly. The sheer amount of authenticity is simply breathtaking. | Íṣe takuntakun àti àyẹ̀wò lọ sí inú iṣẹ yìí, iṣẹ takuntakun, àmì rẹ dára yàtọ̀ bákannáà, òtítọ́ ati ìgbé kalẹ̀ rẹ ya ní lẹ́nu gídígán | en400-yo400 |
My Village People is a movie that will have you losing your home training while watching it. But it is a pathfinder of sorts. Nollywood generally has not done a good job of making the supernatural sexy and appealing. My Village People achieves it effortlessly, and deserves copious amount of praise. | Fíìmù My Village People jẹ́ èyí tí ó jẹ́ pé á mú ẹ sọ ẹ̀kọ́ ìwà dídára rẹ̀ ẹ nù. Ṣùgbọ́n ó jẹ́ bíi olùtọ́pa ọ̀nà ni bákàn. Lápàapọ̀, Nollywood ò kìí ṣe àwọn ipa oní agbára ìbílẹ̀ dáradára. My Village People ṣe é yàtọ̀ ní ọ̀nà tó dára, ó sì yẹ fún ìgbóríyìn. | en400-yo400 |
The story is nothing we haven't seen before but its told from a Nigerian perspective, its funny, quirky and the dialogue is great when compared with others available in the Nigerian market.. . . . I totally enjoyed the movie, would definitely recommend (to my Naija folks!). | Kìí se pé ìtàn yí jẹ́ èyí tí ojú kò rírí ṣùgbọ́n ọ̀nà ìṣọwọ́ ronú tí Nàìjíríà ni wọ́n fi kọ ọ́. Ó pani lẹ́rìn-ín, kò múná d’óko tó àti pé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ inú rẹ̀ dára jù àwọn èyí tí a tún lè rí rà ní ọjà Nàìjíríà.. . Mo gbádùn fíìmù yẹn gan-an ni, máà rí I pé mo sọ fún àwọn tèmi ní Nàìjíríà kí wọ́n wò ó. | en400-yo400 |
1980's, drug mules, beautiful black women ... I'm in heaven | Àwọn ọdún 1980,àwọn tí wọ́n ń lọ oògùn olóró, àwọn obìnrin dúdú tí wọ́n rẹwà… ìgbádùn ọ̀run ni mò ń jẹ yìí o. | en400-yo400 |
Realistic but slow pacing and very melodramatic.. . . . Good acting, based on true events and a decent story. The pacing was a little too slow for my liking and some scenes feel like a made-for-tv movie (the cheese music and the over dramatization).. . . . Overall watchable if you know what you are getting into ahead of time. | Eré- aládùn tó ní ìrírí tó sì ń lo létòlétò.. . . . Eré tó dára, tó sì dá lóríi ìṣẹ̀lẹ̀ tó ń lọ káàkàkiri, ìtàn náà sì jágere, àmọ́ wọ́n o ṣe kíá kíá , ṣe ló fáà , àti pé irúfé orin tí wọ́n lò àti bí wọn ti gbàkókò ènìyàn kò yẹ fún irú eré àgbéléwò báyìí .. . Àmọ́ ó dára ní wíwò fún ẹni tó bá ní àkòkò púpò lọ́wọ́. | en400-yo400 |
Correction.. . . . Thanks for this. I am impressed with it. But I Nelson Orah played the character of Ahmed, not Umar. I will appreciate it if it is corrected. | Àtúnṣe.. . Esé fún èyí. Orí mìi wú. Sùgbọ́n kí Nelso Orah ṣe apá ìwà Umar. Inú mi á dùn tí àtúnse bá wà ní ipa yìí. | en400-yo400 |
She is' Super Fantastic! You want to see this movie. This movie is extraordinarily enjoyable. Pure Nollywood sweetness. | O kọja bẹẹ, ẹ ó fẹ́ wọ fíìmù yìí, fíìmù náà jẹ́ oun tí e ma gbádùn yàtọ̀, Nollywood to dùn gaara | en400-yo400 |
I was thrilled after watching the movie, everything was on point. I was particularly impressed with the quality of the cast and crew. The director, Kemi Adetiba did a great job and I'm so proud of her. I have recommended it to so many people. I look forward to watching more of her work. | Inú mi dùn lẹ́yìn tí mo wo fíìmù náà, ohun gbogbo lọ bó se yẹ kó lọ. àwọn Olùdarí àti atùkọ̀eré yí mú inú mí dùn gan. Olùdarí, Kémi Adétiba ṣe gudugudu méje yàyà mẹfà, inú mi dùn sí i. Mo ti gba àwọn èèyàn láti wo sinima yìí. Mo n'ireti láti wo àwọn sinima tí Kémi adétiba máa tún darí. | en400-yo400 |
Genevieve Nnaji stamps her foot concretely in the pantheon of genuis directors. She doesn't disappoint in her debut, Lion Heart. It's a must watch, as it announces the birth of an international Nollywood. | Genevieve Nnaji kan ẹsẹ mọlẹ ninu awọn.oludari olóyè. Kò já kulẹ nínú iṣẹ àkọkọ rẹ. Eré lion heart je agbọdọ wo, bi o se polongo ibi Nollywood káàkiri àgbáyé. | en400-yo400 |
Nollywood at its peak!!!!. . . . This movie tells a story about culture, unity and family. So many themes that I can't finish mentioning. | Nollywood ńṣe bẹbẹ!!!. . . . Eré yii sọ̀rọ̀ nípa àsà, ìbásepọ̀ ati ìdílé. Orísirísi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀kọ́ ninu eré yii tí nkò lè sọ́ tán. | en400-yo400 |
A Good and Wise film. It was a good film, that shows the dangers of Nigerian tribalism and how it can affect a young love. | Sinimá tó dára ni. Ó fihàn ẹwù tó wà nínu ẹlẹ́yà mẹ̀yà ní orílé èdè Nàìjíríà àti bí ó ṣẹ nípa tí o da lórí àwọn ọmọ | en400-yo400 |
this movie is a good offering in the genre. | Eré yìí dára | en400-yo400 |
Loved this Movie. . . . I was really surprised to read negative reviews for this movie. Do we truly know what a good movie is? This movie was really good, very enjoyable. Well developed characters, believable and relatable story line. And the quality, fantastic. Well done guys. Loved it even more than wedding party 1 and 2. I am not disappointed at all. | Mo fẹ́ràn eré yi. . . . Ó se mí ní kàyéfì láti ka ìròyìn burúkú lóri àjábọ̀ eré yìí. ṣé ati ẹ mọn eré ti ódára bí?. . Eré yii dára ósì lárinrin púpọ̀ pẹ̀lú. Àwon òsèré to pójú òsùwòn, ìtàn to dabi ìsẹ̀lẹ̀ tootọ. ati kúọ́lítì rẹ̀ kamama. Ekú isẹ́ takuntakun. Mo fẹ́ràn rẹ̀ gan ju "Wedding party" apá kinní ati apá kejì lọ. kò já mi kulẹ̀ rárá | en400-yo400 |
Saw the Premieré in Houston Texas. . . . This movie should win an Oscar Award. The Storyline is so good. The Actors weré all incredible. | Mo wo àkọ́kọ́ ìgbéjáde rẹ̀ ní Houston Texas. . . . Ó yẹkí fíìmù yìí gba Oscar Award. Ìtàn eré náà dára púpọ̀. Gbogbo àwọn òṣèré rẹ ló fakọyọ. | en400-yo400 |
Anyone who loves art, Who's seen part one will know the plot and storyline was already built dEré and this was a follow up. | Ẹnikẹ́ni tí ó fẹ́ràn àwòrán, tí ó wo apá kíní yóò ní òye ìtan tí wọ́n lò àti ti wọ́n tẹ́lẹ̀ nínú àgbéjáde eré náà. | en400-yo400 |
Great outcome. | Gbígbéjáde tó dára. | en400-yo400 |
Expository Movie. . . . This is a very good and distinct movie. Some people might not like it perhaps because they are used to the love or thriller story films or perhaps because they are not used to life with a vehicle. They movie truly shows how things really are in the life of mechanics, apprentices and customers. It also teachers parents and children a good lesson. It is a seemingly perfect expository movie. | Eré tó n ṣí ní lójú. . . . Eré yi dára gan o sì tún dáa yàtọ.̀. . Àwọn èlòmíràn léè má feran eré náà bóyá torí wọn ti má feran eré èfè àti eré ẹrù tàbí ayé pẹlú ọkọ kotii mọ́ wọn lára. Eré na fihàn bi ayé atún ọkọ̀ se, ọmọ ikọse àti àwọn oníbara. Ósì tún kọ́ àwọn òbí àti àwọn ọmọ ní èkó. O jẹ́ eré tí o máa ṣí ní lójú. | en400-yo400 |
Understated, powerful crime drama with historical flavor. . This was a very character rich film. Not a single scene was wasted. | Ìfi ojú tẹ́nbẹ́lú, ère nípa ọ̀ràn tí ó lágbára pẹ̀lú adùn ìtàn . . Èyí jẹ́ fíìmù ọlọrọ púpọ̀ nípa ìwà . Kò sí ààyè kan tí ó pàdánù. | en400-yo400 |
Great continuity throughout the movie... The writer and director is highly intelligent and creative. Thank you so much for this amazing movie | Ìtèsíwájú eré nlá ní. Olùkòtàn àti Olùdarí eré yìí ní ọpọlọ. Ẹsé gan fún eré nlá yìí. | en400-yo400 |
I enjoyed seeing very good parts of Lagos, both on the mainland and the island, used, unlike other movies that stay in one location. Lagos is a beautiful place to shoot a movie, especially if the diversity of the state is put to use, as seen here. Accident scenes are usually tricky for Nollywood to portray, but it was a pleasant surprise to see a very believable one here. | Mo gbàdún pé mo rí àwọn mélaǹdì àti áilàndì tí wọ́n lò, èyí yàtọ̀ sí àwọn eré mìíràn. Èkó jẹ́ ibi tí ó rẹwà láti ya fíìmù, pàápàá tí ó bá jẹ́ wípé àwọn èyàn aláràmbàrà ni wón lé lò gẹ́gẹ́ bi aṣe rí i nínú eré yìí. Àwọn apá ìjàm̀bá máa ń jẹ́ ìdàmù fún Nollywood láti ṣe, sùgbọ́n ìyàlẹ́nu ló jẹ́ pé wọ́n rí i ṣe níbí | en400-yo400 |
Citation the movie. . Perfect Movie. Loved every second of the movie. Wished it didn't end | Eré Itokasi. . Fíìmù to pe. Mo feran gbogbo iseju aaya Fíìmù na, Mi ko fe ko pari mo. | en400-yo400 |
Akinnuoye-Agbaje's directorial debut is a troubling coming-of-age story based upon the directors own experiences as a 'farmed out' Nigerian child in the UK during a period of surging xenophobia in the wake of the Windrush generations arrival. The look and feel of the films early moments present a setting and characters so raw and realistic that one could only capture from having experienced them. The pacing of the film in many ways reflects this. At times seeming to take on an almost frantic pace which is meaningful in a way that captures the effect of somebody recalling their life story - made up of the important details and traumatic moments - though occasionally making it difficult to capture and appreciate the passage of time bordering on surreal. The supporting characters similarly are raw and identifiable foils though lacking in the depth required to be whole characters beyond their interactions with the film's lead. Furthermore the film does little to address or contextualize its setting, deliberately choosing to focus on the internal struggles of it's central character. Despite this the films central character is compelling enough to keep the viewer engaged solely in his development throughout the film. Overall Farming is an impressive directorial debut that tackles issues of dual identity and self-hatred in a manner that leaves plenty unsaid but provides a bitter and frequently heartbreaking account of an individuals struggle for meaning and identity. There is so much to be admired about this film which presents an often overlooked period in British history, the importance of such a personal topic deserving of a greater run-time than the films mere 107 minutes. | Íṣe Olùdarí àkọkọ Akinnuoye - Agbaje je itan tí o bá ní nínú jẹ́ to dá lórí ìrírí Olùdarí náà èyí tí o jẹ ọmọ ti wọ́n 'gbìn jáde' ni Nàìjíríà lọ sí ìlú ọba ni asiko ìgbà kan . Wí wo ìgbà àkọ́kọ́ fíìmù yìí fi ibi ati òṣèré tí o ṣé gbàgbọ́ nípa wípé a ti ni ìrírí rẹ̀,ìgbà míràn yíò gbà ọnà ti o ni ìtúmọ̀ yíò fi ipá eni tó n rántí ìrírí ayé rẹ̀ ti o fi àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ pataki hàn. Sí wájú sí, fíìmù nà kò tọ́ka sí ibi tí o ti ṣẹlẹ, ṣùgbọ́n ìjàkadì tí òṣèré pàtàkì n jà nínú rẹ. Pẹlú gbagbo èyí, òṣèré pàtàkì fíìmù na ni ìwà ti o fé kí àwọn olùwò yíò fe mo bí o ṣe dàgbà sókè nínú fíìmù náà. Lápapọ̀, ìgbìn jẹ iṣẹ Olùdarí àkọ́kọ́ tí o kọjú sí ọ̀rọ̀ ìdánimọ̀ méjì àti ìkórìrá ẹni ní ọnà tí o fi òun púpọ lẹ̀laisọ sùgbọ́n o pèsè ìbànújẹ́ ati ìkòrò fun ènìyàn tó n tiraka fún ìtumò ati ìdánimọ̀. Òun tí a lè nifẹ sí pọ ninu fíìmù yìí, èyí tí o mú ìgbà kan ninu ìtàn àwọn aláwọ̀ funfun wá sáyé, pàtàkì kókó ọ̀rọ̀ ara eni ye ju ìṣẹ́jú éjeléniọgọ́run ti won fi ṣe. | en400-yo400 |
amazing film must see | Eré to yanilenu tí a gbọ́dọ̀ wo. | en400-yo400 |
Good series. . I really like this show. All the characters are great and I enjoy watching. Hope it stay around for more seasons. Looking forward to the next season!!! | Ipele eré tó dára. . Mo gbádùn eré yìí. Gbogbo òṣèré ṣe dára dára mo ṣì gbádùn wíwò ẹ. Ó wù mí kó sésìn tó pọ̀. Mo ń dúró de sésìn tó kù. | en400-yo400 |
Working from a script by playwright Darci Picoult, Dosunmu fashions a tale that’s realistic, melodramatic and culturally specific (we spend as much time ogling colorfully patterned dresses as we do admiring Gurira’s endlessly expressive face), yet unmistakably archetypal. | Iṣẹ́ ṣíṣe láti inú àkọsílẹ àtowọ́ olùkọ̀tàn Darci Picoult, Dòsùnmú ṣe ìtàn lẹ́ṣọ̀ọ́ lónà tí ó bòjúmu, eré orí ìtàgé tí ó ṣe wẹ́kí pẹ̀lú ohùn orin, ó sọ ojú abe àṣà níkǒ (a lo ọ̀pọ̀ ìgbà láti tẹjú mọ́ àwọn tí àwọ̀ ara wọn ṣe rẹ́gí, bí a ṣe lo ọ̀pọ̀ ìgbà náà láti yófẹ̀ẹ́ ojú Gurira tí ó ń sọ orísirísi ọ̀rọ̀ láì lanu), tí ó sì ń farajọni. | en400-yo400 |
Great movie! | Eré tí o lágbara | en400-yo400 |
No words to describe the power of this movie and its reminder of how fortunate it is to have never lived through a civil war. Extraordinary story telling of tragic, recent Nigerian history and the humanity within it all. | Kò sí ọ̀rọ̀ kánkán tí ó le júwe irú agbára tí ère yìí ni ati wípé ó ṣe ìrántí oriire tí ó jé láti là ìjà abéle kọjá. Ìtàn àgbàyanu tí ó sọ nípa ìtàn ìṣẹ̀lẹ̀ ni burúkú tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti nípa àwọn ènìyàn inú rẹ. | en400-yo400 |
Beautiful | Ó dára | en400-yo400 |
Rational representation of the Igbos. . . . Lion heart represented what it really means to be Igbo - hard-working and communal system of living. | oniduro àwon ígbò. . Lionheart se aṣojú ohun tí ó tú mọ̀ si láti jẹ́ ọmọ ígbò- ṣíṣe iṣẹ́ taratara àti ètò ìgbé ayé | en400-yo400 |
There is a lot of mediocre acting here and there and some things made little to no sense for me but overall i did enjoy it for what it is. I would probably not watch it ever again but seeing it once is nice. | Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣọwọ́ ṣeré tó mẹ́hẹ àti àwọn ǹkan kan tí kò mú ọpọlọ dání sí èmí ṣùgbọ́n ju gbogbo rẹ̀ lọ, mo gbádùn rẹ̀ b’óșe rí. Mo lè má tún un wò mọ́ láyé, àmọ́ ó dára ní ẹ̀ẹ̀kan tí mo wò ó yẹn. | en400-yo400 |
While the themes here are, of course, redolent of neorealism, the filmmakers don’t make ostentatious nods to cinema past. Their voice is their own; the camera is mobile when it needs to be, but stands still much of the time, letting the excellent cast build their characters as the events of the film test their endurance. | Nígbà tí àwọn àkòrí rẹ̀ jẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ òtítọ́ tí ó dùn moní, àwọn olùpilèsè eré náà ó kàn ṣe àwítúnwí asán àwọn fíìmù tí wọ́n ti ṣe sẹ́yìn. Ohùn wọn jẹ́ tiwọn. Irinṣẹ́ ìyafọ́tò (camera) náà kò dúró ṣin nígbà tí ó yẹ kí ó máa káà kiri, ṣùgbọ́n ó dúró lópòlopò ìgbà láti fi àyè sílẹ̀ fún àwọn òṣèré kí wọ́n lè fi àwọn àbùdá wọn hàn kedere gẹ́gẹ́ bí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ fíìmù náà ń dán ìrọ́jú wọn wò. | en400-yo400 |
Funny Funny Funny. . . . Oh mehn, this movie is super funny. if you are looking for a movie to lift your mood up then this is the right movie for you. | Ó pa ni lẹ́rìín ó pa ni lẹ́rìín . . . . Ó ga, fíìmù yí pa ni lẹ́rìín gan-an ni. tí ó bá ń wá fíìmù kan láti gbé ìṣe sí rẹ sókè lẹhinna èyí ni fíìmù tí ó tọ́ fún ọ. | en400-yo400 |
Superb movie!!. . This has got to be the best made movie to come out of Nigeria, not to mention hilariously funny! | Fíìmù tó ga jù !!. . Èyí ní láti jẹ́ fíìmù tí ó dára jù lọ tí a ṣe jáde ní Nàìjíríà, kí a tó mẹ́nuba abala àrín tàkìtì?! | en400-yo400 |
BEAUTIFUL AFRICAN WOMEN | ÀWỌN OBÌNRIN ILẸ̀ ADÚLÁWỌ̀ TÍ Ó RẸWÀ. | en400-yo400 |
I don't know on what basis people have given this movie such a low rating but believe me after a long time I've a watched such a good, cute, clean and better than Bollywood movie. | Mi ò mọ ìdí tí àwọn èèyàn fi ń fún fíìmù yìí ní òṣùwọ̀n tó kéré. Ṣùgbọ́n tí e ó bàá gbàmígbọ́, ó ti pé tí mo ti wo eré tó dára tó báyìí, tí ó sí tún dára ju eré Bollywood lọ. | en400-yo400 |
The picture quality of this movie is great, and the director did a good job. | Àwòrán eré yìí dára púpọ̀. Olùdarí náa ṣe iṣẹ́ tó dára. | en400-yo400 |
Outstanding performance. . . . Temi Otedola's performance was truly stunning. I thoroughly enjoyed the layers that the story had and the way that each key piece of information was revealed. | Iṣẹ́ tí ó tayọ . . . . Ìṣe Temi Otedola jẹ́ ìyàlẹ́nu gan-an ní tòótọ́ . Mo gbádùn àwọn ìpele tí ìtàn náà ní ní kíkún àti ọ̀nà tí wọ́n fi ṣàfihàn àlàyé pàtàkì. | en400-yo400 |
A Major Step in taking back our narrative. . . . This movie, has really showed a deep side of the struggles of the people we often ignore. Easy to see a person to judge, but when stories like these are told you start to look at everyone with a different lens. The ending, though abrupt keeps you in a limbo and holds you in a powerful suspense pondering on what you just witnessed. | Igbese tó lakaaki láti ṣe ipepada ìṣe àti ìtàn wá.. . . . Sinima àgbéléwò yìí safihan kirakita àwọn ènìyàn tí a máa ń yìn nù. Ó rọrùn láti gbé sí orí ìwọ̀n àmọ́, nígbà tí irú ìtàn yìí bá jẹyọ ojú ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni a fi máa wo oníkálukú. Looto, ní ìgbẹ̀yìn, aisedeede fi o hàn gẹ́gẹ́ bí alaimokan, yóò si gbé ọ gesin aáyán lórí ohun tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣojú rẹ | en400-yo400 |
Spot On!!! 🔥🔥🔥. . Definitely African movie of the year, enjoyed every minute of the 2hours 30minutes 😀👏👏👏🔥🔥🔥🔥🔥🔥✔✌ | Ó wà ní bẹ̀!!! 🔥🔥🔥. . Dájúdájú ère Áfríkà tó gbayì nínú ọdún yìí, mo gbádùn gbogbo ìṣẹ́jú tó wà nínú wákàtí méjì àti ọgbọ̀n ìṣẹ́jú 😀👏👏👏🔥🔥🔥🔥🔥🔥✔️✌️ | en400-yo400 |
A rare story about the values of family from a very distinctive perspective. Eloquently interpreted with perfect casting | Ìtàn to sọwọn nipa àṣà ìdílé lati ọna ti o yàtọ ti won sì gbejade pẹlu òṣèré ti o koju osunwon. | en400-yo400 |
Finally a great Nigerian film. For years I’ve been hoping that Nigeria would produce a really great film, and that’s where the Esiri brothers come in. | Níparí eré orílèdè Nigeria tó lágbára, fún òpọ̀lopọ̀ mò ún nírètí pé orílèdè Ngeria ma pèsè eré tó lágbára, àti ibè ni àwon arákùnrin Esiri tí má wolé | en400-yo400 |
Honestly this movie is really good production wise and the sequel. Chills from top notch acting. | Ka má parọ́ ṣiṣé eré orí ìtàgé yìí dára gan nii. Àgbà ní o sí jẹ́ láàárín àwọn eré orí ìtàgé. | en400-yo400 |
Hardly was there a period of 5 minute in this movie with nothing to smile, chuckle or laugh about. I don't think there is a Nigerian movie that beats this in it's genre (Fictional Comedy). The movie effects were as well commendable. | Tipátipá ni a fi lè rí ojú ìṣẹ́jú márùn-ún tí kò pa ènìyàn lẹ́rìn-ín. N kò rò pé ere àgbéléwò kankan wà ní Nàìjíríà tó lè borí fíìmù yìí. Iṣẹ́ eré yìí kúnjú òṣùwọ̀n. | en400-yo400 |
Good Nollywood romantic comedy. . This movie is exactly cheesy enough to make you smile after a bad day. | Eré Nollywood tí ọ̀rọ̀ ìfé ti ó n panilérìn-ín. Eré yìí Dára tó láti Fi Ẹ̀rín síni lẹ́nu lẹ́yìn ọjó tí ó burú. | en400-yo400 |
Nice cross-country movie. . . . The only thing that I don't like about this movie is the way there was little or no interaction with the Nigerian or Indian environment.. . . . Beautiful romantic movie. | Eré àgbéléwò dìdára lórí jákèjádò- orílè-èdè . . . . Oun kan pàtó tí mi ò féràn nípa fíìmù yìí ni pé ko si ibásepò pẹlu ágbègbè orílè-èdè Nàìjíríà ati india bó ti wu ó kéré mọ. . . . . Eré àgbéléwò ìfé tó lárindin lè yìí | en400-yo400 |
The story starts a bit slow but stick with it. Very good story. | Ìtàn yí kò já fáfá láti ìbẹ̀rẹ̀ ṣùgbọ́n má jẹ́ kí ó sú ọ. Ìtàn gidi gbáà ni. | en400-yo400 |
King of Boys. . . . This series is absolutely fantastic, from the story line to the cast, costumes and the emotion portrayed by the protagonist. I'm sure proud to be a Nigerian at this time. Well done Kemi Adetiba, well done Sola Sobowale! | King of Boys. . Eré yìí dára gidi, láti ìtàn dé àwọn òṣèré, aṣo ati ìmọ̀lára tí akoni eré náà. Inú mi dùn láti jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè nàìjíríà. Kú iṣé takuntakun Kémi Àdetìbà, Kú iṣé takuntakun Solá Sóbòwálé. | en400-yo400 |
A must see for everyone. . . . Namaste wahala is a masterpiece and officially a cross between cultures. This Nollywood Bollywood collaboration have everything in a good romantic movie should have, the indian actors weré all great and played their roles perfectly. | Àgbọ̣dọ̣ rì fún gbogbo ènìyàn. . . . Namaste wahala jẹ̣́ ọ̀gá nínú àwọn eré, ó sì kó orísìí àṣà papọ̀. Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Nollywood àti Bollywood yìí ni gbgogbo oun tí eré ìfẹ́ tó bá dára máa ní. Àwọn òṣèré tí ó jẹ́ ọmọ India fakọyọ, wọ́n sì kọ́ ipa wọn dáradára | en400-yo400 |
Realistic, entertaining and all round good vibes. I could watch it all day. I wish they would air more than once a week though, asides from that, its just great. Most reality shows come off as scripted but not this one. | Ojúlówó, ìdánilárayá àti ìmọ̀lára dídára. Mo le fi gbogbo ọjọ́ wò ó. Ó wù mí kí wọ́n gbé e jáde síi ju ẹ̀kan lọ́sè lọ. Yàtọ̀ sí èyíinì, ó kàn sáa dára púpò ni. Òpò nínú àwọn eré olótìtọ́ọ́ jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń kó kí wọ́n tó ṣe é, ṣùgbọ́n, èyí kọ́. | en400-yo400 |
On a Nollywood scale I'll give this movie an 9 because of it's unique storyline and excellent production which sets it aside from other Nigerian movies | Màá fún ere yìí ni ẹẹ́sàn an lórí òṣùwọ̀n Nollywood nítorí ìtàn ere náà jẹ àrà ọ̀tọ, bẹ́ẹni àgbéjáde rẹ̀ tó jẹ́ kó yàtọ̀ sí gbogbo àwọn eré àgbéléwò yòókù ni ilẹ̀ Nàìjíríà | en400-yo400 |
Good story line. . . . It's a good movie and storyline. Loved it. | Ìtàn gidi.. . Ó jẹ́ eré àti ìtàn gidi. Mo fẹ́ràn rè. | en400-yo400 |
Speechless;. . . . This movie gave me goose bumps I connected in a way that literally tore my soul. Indeed depicted God the way and manner it should God bless the writer, producers and all involved. The actors too are top top everyone did a fantastic job. | Ó gbenután. . . . Eré yìí wọ akínyẹmí ara mìi lọ. Mo bá eré náà lọ tọkàntọkàn. Lóòtọ́ọ́, ó fi ọlọ́run hàn lónà tó yẹ. Olórun yóò bùkún olùkọ̀tàn náà, àwọn olùgbéjáde, àti gbogbo àwọn tó kópa pátápátá. Àwọn òsèré náà kò gbéyìn, gbogbo ènìyàn ló ṣe iṣé tó dára. | en400-yo400 |
I enjoyed the relationship crafted between Mr. Tayo (Bimbo Manuel) and Ejiro (RMD), | Mo gbádùn ìbáṣepọ̀ tó wà láàrín-in Mr. Tayo (Bimbo Manuel) àti Ejiro (RMD) | en400-yo400 |
One thing I like about the movie is the way the story was told and the ways the actors interpreted it. The writers, directors and cinematographers deserve an applaud for this effort. | Nǹkan kan tí ó mo fẹ́ràn nínú eré yìí ni bí a ṣe sọ ìtàn rẹ̀ àti bí àwọn òṣèré ṣe túmọ̀ rẹ̀. Ó yẹ kí a gbé oríyìn fún àwọn òǹkọ̀tàn, olùdarí, àti àwọn a yàwòrán fún làálàá wọn lórí iṣẹ́ yìí. | en400-yo400 |
Best Christian Movie!!!. . . . I love this movie! It's so well done - The acting was awesome and the storyline was refreshing. Kudos to the entire cast and crew! Definitely a must-watch!. . . . P. S. You'll need tissues. | Fíìmù krììstẹ́nì tí ó dára jùlọ̣ !!!. . . . Mo fẹ́ràn eré yìí! Wọ́n ṣe é dáradára. Eré ṣíṣe náà kọjá àfẹnusọ, ìtàn náà sì dára. Ìgbóríyìn fún àwọn òsèré àti àwọn ẹgbẹ́ tó kópa nínú ṣíṣe eré náà. Dájúdájú àgbọdọ̀ wò ni.. . . . Ṣùgbọ́n, wàá nílò ǹkan ìnujú. | en400-yo400 |
Love it!. . I love the movie, the actors , the director etc. Everyone absolutely made it great with their acting skill. . . . Anyone who finds it bad doesn't clearly know a good movie, and possibly can't relate with our cultures. | Fẹ́ràn rẹ̀!. . . . Mo fẹ́ràn eré sinimá nàá, àwọn òṣèré, olùdarí, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ. Gbogbo ènìyàn lo jé kí ó dára púpọ̀ pẹ̀lú eré ṣíṣé wọn.. . Dájúdájú, ẹnikẹ́ni tí ó bá so wípé kò dára ò mọ fíìmù gidi, tàbí kí àṣà àwọn elòmíràn má nítumò síi. | en400-yo400 |
Awesome. . . . The movie was awesome with beautiful characters. I love seeing Bisola in movies, she's good. | Erè naa dára pẹ̀lù àwọ̀n òsèré tó rẹwà. Mo fẹ́ràn lati maa rí Bísọ́lá nínú eré, ó dára | en400-yo400 |
Beautiful acting, beautiful directing, not so great story. . I had to open an account just to review this movie. This is a beautiful work of art.. . | Eré ṣíṣe tó fakọyọ, ìdarí tó fi òye hàn ṣùgbọ́n ìtàn yìí kò fi bẹ́ẹ̀ wúni lórí. . . Mo ní láti sí a sì àkáǹtì kí n lè ṣe àgbéyẹ̀wô eré yìí. Iṣẹ́ yìí rẹwà púpọ̀. . . | en400-yo400 |
Interesting. . . . I really enjoyed this movie. The acting and story line was really good. I found it to be very interesting to wonder about Ishi's life - this for sure is an eye opener to so many who are forced into marriage. | Ó dùn móni. . Mo gbádun eré náà. Eré náà àti ìtàn náà Dára púpọ. Mó rí gẹ́gẹ́bí oun tí ó múmi ronú Lórí ọ̀rọ̀ ìgbèsí ayé– èyí dájúdájú yíò je ìlanilójú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ tí wón ń to ṣe ìgbéyàwó. | en400-yo400 |
Gabriel Afolayan is in a class of his own as an actor; he always understands the task. | Gabriel Afolayan tún jẹ́ òṣèré tó yàtọ̀ láàyè tirè. Òye iṣẹ́ máa ń yé e ni sáá. | en400-yo400 |
Not as Bad as reviewed. | Kò burú fún àgbéyẹ̀wò | en400-yo400 |
Great film and great action. . . . Great story original great action and great comedy all combined in one. Thrilling film and great cast. | Fíìmù gidi àti ìsesí àwọn òșèré tí ó máyàn lórí.. . Ojúlówó ìtàn gidi, ìṣọwọ́ ṣeré gidi àti ì dá ẹ̀rín pá òșónú rere ni wọ́n pò pọ̀ sí ojú kan. Fíìmù tí ó mú ara gbá yágíyágí àti àwọn òșèré tí ó lé kenkà. | en400-yo400 |
A well-acted, finely wrought epic that nevertheless struggles to balance the requirements of melodrama with its drive to capture a historical moment. | Ere tí àgbékalẹ̀ rẹ dára ṣùgbọ́n tí ó tiraka láti sàfihàn àmúyẹ ere apanilẹ́rìín àti dírámà pẹ̀lú èrò láti ni ipa mọ́nigbàgbé. | en400-yo400 |
Awesome. . . . The first time I saw this movie I was blown away. I don't want to sound crazy but I try to study things of this world. I hope to see a second installment with the same characters and a darker plot. | Ó LÉ KENKÀ. . Nígbà tí mo kọ́kọ́ wo sinimá yìí, ó yà mí lẹ́nu gan-an ni o. N kò fẹ́ dàbí ẹni tí ó ń ronú ju bó ṣe yẹ lọ o, ṣùgbọ́n mo máa ń ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ohun ayé yìí. Mò ń fi ojú sọ́nà fún apá kejì pẹ̀lú àwọn òșèré kan náà àti ìtàn tí yóò tún rújú ju èyí lọ. | en400-yo400 |
Amazing. . I'd of normally flicked past this, but honestly it's an amazing story. You can tell it had a low budget, but the direction and screen play is fantastic! The choreography of the fight scenes lacked a little. Worth a watch definitely | Ìyàlẹ́nu. . Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, mi ò kí n kàsíí, ṣùgbọ́n nítòótó, eré yìí yanilẹ́nu. Níṣe ni èèyàn máa mọ wípé, wón kò náwó púpọ̀ lórí eré náà sùgbọ́n ìfojúsùn wọn àti ìṣe eré náà yanilẹ́nu. Bótilẹ̀jẹ́pé, ibi ìṣẹ̀lẹ̀ ìjà náà kò dára tó, síbẹ̀síbẹ̀, ó yẹ fún wíwo. | en400-yo400 |
Engrossing tale of family and war. . . . I recommend this movie without reservation. | Ìtàn idile àti ogun. Mo fi taratara fi ọwọ́ sí eré náà. | en400-yo400 |
Wow. . . . This movie really made me change my relationship for the best. Great movie. The movie did start off slow but it definitely kept me interested. The flash backs really made the ending even more intense because everything came together. | Ó gajù. . . . Fíìmù yìí ti jẹ́ kí n yí ọkàn mi padà nípa nǹkan tó dára. Ere tó fakọyọ ni. Ere yìí fà nílẹ̀ díẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ ṣùgbọ́n ó wuyì láti wò. Ìrántí àwọn abala tó ti kọjá jẹ́ kí ìparí ere náà túnbọ̀ dùn nítorí pé gbogbo nǹkan kàn ń ṣẹlẹ̀ papọ̀ ni. | en400-yo400 |
People will never learn if they don't even try.. . . . This movie tackles so many issues including the biggest one of all. Identity Crisis in Black men. | Awon eniyan ko ni kekoo ti won ko ba gbiyanju nkan.. . . . Eré yìí fi oríṣii ìṣòro hàn, pàápàá jùlọ, èyí tó ṣe pabambàrì èyí tí ó jẹ mọ̣́ ìpòrúru ipò àwọn aláwọ̀ dúdú ní àwùjọ | en400-yo400 |
Through an economy of exposition, Eyimofe, (translated as “This is My Desire”) delivers a timeless, universal portrait of human resilience while establishing Arie and Chuko as a welcome new addition to the filmmaking brood. | Nípasẹ̀ ọrọ̀ -ajé ti ìṣà fihàn, Èyímofẹ́, (tí a túmọ̀ sí “Èyí ni Ìfẹ́ Mi”) ṣe àfihàn àílákókò, àwòrán àgbáyé ti ìfarabalẹ̀ ènìyàn lákòókò tí ó ṣe ìdásílẹ̀ Arie ati Chuko gẹ́gẹ́bí ọìtẹ́wẹ́gbà tuntun sí ṣíṣe fíìmù. | en400-yo400 |